Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa the type of reptile. Fún ìtumọ́ míràn, ẹ wo: Ọmọ onílé (ìṣojútùú).

Taxonomy not available for Gekkota; please create it automated assistant

Àdàkọ:Wikispecies Ọmọ onílé tàbí Ọmọnlé tàbí Ọmọọ́lé jẹ́ ẹranko kékeré tí ó ma ń jẹ àwọn kòkòrò àti labalábá, ìrísí rẹ̀ dàbí ti Alángbá. Kò sí ibi tí ọmọnlé kò sí ní orílẹ̀ àgbáyé àyà fi ibi tí wọ́n ń pe ní Antarctica tí ó tutù jùlọ lórilẹ̀ àgbáyé. Ọmọ́ólé jẹ́ ìkan nínú ẹbí ẹranko infraorder. Àwọn agbègbè tí wọ́n jẹ́ agbègbè olóoru tàbí tí ó lọ́ wọ́rọ́ ni ọmọọ́lé ma ń gbé. Wọ́n ma ń gùn tó ìwọ̀n bàtà kan àbọ̀ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ 1.6 to 60 centimetres (0.6 to 23.6 inches).

Gecko
Temporal range: 110–0 Ma
Albianpresent
Gold dust day gecko
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ e ]
Subgroups

Ọmọ onílé yàtọ̀ gidi gan láàárín àwọn aláàmù tókù nípa bí wọ́n ṣe ma ń bára wọn sọ̀rọ̀ tí ó yàtọ̀ sí ti àwọn ẹ̀yà wọn tókù. Wọ́n sábà ma ń lo ohùn wọn tí ó ma ń dún bí ìfé. Àwọn ọmọńlé sábà ma ń pariwo tí wọ́n bá ń gura wọn lọ́wọ́. Wọ́n sì ma ń pòṣé nígbà tí wọ́n bá ẹ̀mí wọn bá wà nínú ewu. Nínú ẹbí alaángbá àwọn ni wọ́n ní ẹ̀yà tí ó pọ̀ jùlọ, tí wọ́n tó ẹgbẹ̀rún kan niye. [1]

Àwọn itọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Search results – gecko". Reptile-Database.Reptarium.cz. The Reptile Database.