Banana Island, Lagos
Banana Island jẹ erekuṣu atọwọda ti o wa nitosi Ikoyi, ìpínlè Eko, Naijiria. A fun ní oruko náà nitori boserí. A dá erukusu náà fún igbé àti láti jé ojà fun títà ríràrira, o ni àwon ilé igbé, ilé itaja àti ilé idaraya.
Itan kíkó rè
àtúnṣeOlogbe Adebayo Adeleke ni ó ya àwòrán Erukusu Banana Island tí a pè ní Lagoon city nígbà kíkó rè. Adebayo ni Alakoso ilé-isé City Property Development Ltd.
Banana Island jẹ erekusu atowoda ni Ipinle Eko, Naijiria ti ìrísí rè dabi ti Ogede O wa ni orí Adagun Èkó o si ní afara to so pò mó Erukusi Ikoyi. Ilé-isé Lebanon-Nigeria Chagoury Group ni o kọ erekuṣu naa pèlú ajọṣepọ Federal Ministry of Works and Housing. [1]
Itobi erukusu náà to awọn 1,630,000 square meter asì pin pin si awọn ploti 536 A pese awọn olugbe pẹlu awọn ohun elo bi omi àti iná àti nẹtiwọki satẹlaiti ibaraẹnisọrọ.[2]
Àwon ilé-isé nla nla ni orilẹ-ede Naijiria bi- Etisalat Nigeria, Airtel Nigeria, [3] Ford Foundation Nigeria ati Olaniwun Ajayi & CO[4] kalè sí Banana Island.
Díè ninú awọn olugbe ibè
àtúnṣe- Mike Adenuga - Onisowo
- Aliko Dangote - Onisowo
- Davido - olorin Afrobeats
- Linda Ikeji
- Iyabo Obasanjo - Sẹnetọ Naijiria tẹlẹri
Àwon Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ "The Chagoury Group Construction Division - Projects". chagouryconstruction.com. October 28, 2006. Archived from the original on December 14, 2007. Retrieved September 11, 2022. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "The Sun News On-line/Exquisite Property". sunnewsonline.com. June 20, 2004. Archived from the original on July 14, 2009. Retrieved September 11, 2022. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Contact Us - airtel Nigeria". airtel.com. March 22, 2014. Archived from the original on March 22, 2014. Retrieved September 11, 2022. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Olaniwun Ajayi LP". olaniwunajayi.net. June 23, 2010. Archived from the original on March 22, 2014. Retrieved September 11, 2022. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)