David Ferrer
David Ferrer Ern (Valencian pronunciation: [daˈvit feˈreɾ ˈɛɾn]; ojoibi April 2, 1982 ni Xàbia, Alicante, Valencian Community) je osise agba tenis ara Spein to wa ni ipo nomba 5 Lagbaye ni ori ito ATP, ohun ni ara Spein keji ti ipo re gajulo leyin No. 4 Lagbaye Rafael Nadal.
Ferrer at the 2011 Australian Open. | |
Orílẹ̀-èdè | Spéìn |
---|---|
Ibùgbé | Valencia, Spain |
Ọjọ́ìbí | 2 Oṣù Kẹrin 1982 Xàbia, Alicante, Spain |
Ìga | 1.75 m (5 ft 9 in) |
Ìgbà tódi oníwọ̀fà | 2000 |
Ọwọ́ ìgbáyò | Right-handed (two-handed backhand) |
Ẹ̀bùn owó | $17,049,089 |
Ẹnìkan | |
Iye ìdíje | 488–246 |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 18 |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 4 (February 25, 2008) |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 5 (November 12, 2012) |
Grand Slam Singles results | |
Open Austrálíà | SF (2011) |
Open Fránsì | SF (2012) |
Wimbledon | QF (2012) |
Open Amẹ́ríkà | SF (2007, 2012) |
Àwọn ìdíje míràn | |
Ìdíje ATP | F (2007) |
Ìdíje Òlímpíkì | 3R (2012) |
Ẹniméjì | |
Iye ìdíje | 61–95 |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 2 |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 42 (October 24, 2005) |
Grand Slam Doubles results | |
Open Austrálíà | 3R (2005) |
Open Fránsì | 2R (2009) |
Wimbledon | 1R (2003, 2004, 2005, 2006, 2009) |
Open Amẹ́ríkà | 2R (2004, 2006) |
Àwọn ìdíje Ẹniméjì míràn | |
Ìdíje Òlímpíkì | SF - 4th place (2012) |
Last updated on: September 20, 2012 by Asmazif. |
Orúkọ yìí lo àṣà ìṣorúkọ ní èdè Spéìn; àkọ́kọ́ tàbí orúkọ ìdílé bàbá ni Ferrer èkejì tàbí orúkọ ìdílé ìyà ni Ern.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |