Fabio Fognini jẹ́ ògbónta rìgì agbá bọ́ọ̀lù ẹlẹ́yin orí pápá tí a mọ̀ sí tennis.[1] Wọ́n bíi ní Ọjọ́ kẹrìnlélọ́gbọ̀n Oṣù karun Ọdún 1987. Fabio tí a bí ní Italy jẹ́ ògbónta-rìgì akópa fún orílẹ̀ èdè rẹ̀, lẹ́yì tí ó mú kí ó wà ní ipò kẹtàlá nínú iṣé tó yan láàyò ní ọdún 2014. Bákan náà ló tún jáwé olúborí ti ọdún 2015. Ó fẹ́ran kí ó maa wọ nkan pupa lọ́pọ̀lọpọ̀ ìgbà, pàápàá jùlọ ní èyí tí ó wọ̀ nínú ìdíje mẹ́ta kan ìyẹn atuttgart àti vina del mar níbi tí ó ti gbá ayò lọ́un nikan títí dé ìpele kòmẹsẹ̀-é-yọ̀ quater final ti ilẹ̀ Faranse ní ọdún 2011, àti ti ọdún 2013 Monte-Carlo MasterMaster pẹ̀lú ìdíje Simone Bolell. Ọ̀gbéni Fabio tún gbégbá orókè nínú ìdíje ìsidíje eré ìdárayá ti Viña del Mar.

Fabio Fognini
Orílẹ̀-èdè Italy
IbùgbéArma di Taggia, Italy
Ọjọ́ìbí24 Oṣù Kàrún 1987 (1987-05-24) (ọmọ ọdún 37)
Sanremo, Italy
Ìga1.78 m (5 ft 10 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà2004
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed (two-handed backhand)
Olùkọ́niJose Perlas
Ẹ̀bùn owó$7,175,087
Ojúewé Íntánẹ́ẹ̀tìfabiofognini.eu
Ẹnìkan
Iye ìdíje222–215 (50.8% in Grand Slam and ATP World Tour main draw matches, and in Davis Cup)
Iye ife-ẹ̀yẹ4
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 13 (31 March 2014)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 41 (1 August 2016)
Grand Slam Singles results
Open Austrálíà4R (2014)
Open FránsìQF (2011)
Wimbledon3R (2010, 2014)
Open Amẹ́ríkà4R (2015)
Àwọn ìdíje míràn
Ìdíje Òlímpíkì1R (2012)
Ẹniméjì
Iye ìdíje124–128
Iye ife-ẹ̀yẹ3
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 7 (20 July 2015)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 21 (1 February 2016)
Grand Slam Doubles results
Open AustrálíàW (2015)
Open FránsìSF (2015)
Wimbledon2R (2014)
Open Amẹ́ríkàSF (2011)
Àdàpọ̀ Ẹniméjì
Grand Slam Mixed Doubles results
Open Austrálíà2R (2013, 2016)
Wimbledon2R (2012, 2013)
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò
Davis CupSF (2014)
Last updated on: 1 February 2016.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Roger Races On", Roger Federer's official site, 9 August 2007.