Farooq Kperogi
Farooq Adamu Kperogi a bi ní ọdún 1973, ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ọmọ Nàìjíríà àti Amẹ́ríkà, akọ̀wé, (born 1973), media scholar(ọ̀mọ̀wé ìgbóhùngbáwòrán sáfẹ́fẹ́), akọ̀ròyìn, bílọ́gà àti ajìjàgbara. Ó jẹ́ afìròyìn léde àti aṣàtúnṣe ìròyìn ní ọ̀pọ̀ iwé ìròyìn ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó fi mọ́ Daily Trust, Daily Triumph àti New Nigerian.[1][2]
Farooq Kperogi | |
---|---|
Kperogi in 2021 | |
Born | March 30, 1973 Baruten, Kwara State, Nigeria |
Institutions | Kennesaw State University |
Alma mater | Georgia State University (Ph.D) University of Louisiana at Lafayette (M.Sc) Bayero University (B.A) |
Doctoral advisor | Michael L. Bruner |
Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i aṣèwádìí ní ẹ̀ka ìwádìí àti ìbánisọ̀rọ̀ tí ààrẹ ní ìgbà ìṣèjọba Olusegun Obasanjo, tí ó sì kọ́ ṣíṣẹ ìròyìn àti sísọ̀ ìròyìn ní Ahmadu Bello University àti Kaduna Polytechnic.
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ìgbé ayé àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeA bí Kperogi ní ọdún 1973 ní Okuta, Baruten tí ń ṣe agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìpínlè Kwara, ní Nàìjíríà, ó sì jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Bariba (Baatonu) people.[3] Ó lọ sí Bayero University láàárín1993 àti 1997, ní bi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní mass communication. Ó sì ní ìwé ẹ̀rí nínú communication ìyẹn master's degreeUniversity of Louisiana at Lafayette àti Ph.D. ní Georgia State University ní United States ní ọdún 2011.[4]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Renowned Nigerian columnist, university teacher, Farooq Kperogi, promoted professor" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-03-26. Retrieved 2021-12-18.
- ↑ "Farooq Kperogi | Kennesaw State University - Academia.edu". kennesaw.academia.edu. Retrieved 2021-12-18.
- ↑ "Kperogi: The Man Who Redefined Grammar Column Writing in Nigeria". jarushub.com. JarusHub. Archived from the original on 6 October 2017. Retrieved 6 October 2017.
- ↑ "About me". farooqkperogi.com. Farooq A. Kperogi. Retrieved 6 October 2017.