Fresh FM
Fresh FM jẹ́ nẹ́tíwọkì àwọn ilé-iṣẹ́ rédíò ní Nàìjíríà, Olayinka Joel Ayefele ló ni í. Àwọn ìbùdó Fresh FM wà ní Abẹ́òkuta, Adó-Èkìtì, Àkúrẹ́, Ìbàdàn, Èkó, àti Òṣogbo .
Frequency | |
---|---|
Language(s) | English, Yoruba |
Owner | Yinka Ayefele |
Website | freshfmnigeria.com |
Ìtàn
àtúnṣeÈtò bẹ̀rẹ̀ ní Ìbàdàn ní ọdún 2015 àti Abẹ́òkuta ní ọdún 2018; ìbùdó Adó-Èkìtì bẹ̀rẹ̀ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ lọ́dún 2020.[1][2]Nẹ́tíwọkì náà gbòòrò dé Òsogbo ní Oṣù Kẹwàá ọdún 2021 àti sí Èkó ní ọdún 2022; ìkànnì fún Ìlorin ti jẹ́ dídá sílẹ̀. [3][4]Fresh FM ní ìbùdó ní gbogbo ìpínlẹ̀ Gúúsù-ìwọ̀-oòrùn mẹ́fẹ̀ẹ̀fà Nàìjíríà pẹ̀lú ìran lati gbòòrò dé àwọn agbègbè mìíràn ní ọjọ́ iwájú.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Yinka Ayefele's Fresh FM Begins Transmission in Ekiti". InsideOyo.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-07-19. Retrieved 2021-12-08.
- ↑ Abdulrahman, Adebayo (2020-07-10). "PHOTOS: Ayefele’s 106.9 FM, Modeled After BBC, Begins Test Transmission In Ado-Ekiti". OyoInsight (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-12-08.
- ↑ "Dr. Yinka Ayefele Adds Ilorin, Lagos to his list of Network Stations -" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-28. Archived from the original on 2022-02-23. Retrieved 2022-02-23.
- ↑ "Fresh 105.9 FM". Streema. Retrieved 2022-02-23.