Fresh FM jẹ́ nẹ́tíwọkì àwọn ilé-iṣẹ́ rédíò ní Nàìjíríà, Olayinka Joel Ayefele ló ni í. Àwọn ìbùdó Fresh FM wà ní Abẹ́òkuta, Adó-Èkìtì, Àkúrẹ́, Ìbàdàn, Èkó, àti Òṣogbo .

Fresh FM
Frequency
Language(s)English, Yoruba
OwnerYinka Ayefele
Websitefreshfmnigeria.com

Ìtàn àtúnṣe

Ètò bẹ̀rẹ̀ ní Ìbàdàn ní ọdún 2015 àti Abẹ́òkuta ní ọdún 2018; ìbùdó Adó-Èkìtì bẹ̀rẹ̀ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ lọ́dún 2020.[1][2]Nẹ́tíwọkì náà gbòòrò dé Òsogbo ní Oṣù Kẹwàá ọdún 2021 àti sí Èkó ní ọdún 2022; ìkànnì fún Ìlorin ti jẹ́ dídá sílẹ̀. [3][4]Fresh FM ní ìbùdó ní gbogbo ìpínlẹ̀ Gúúsù-ìwọ̀-oòrùn mẹ́fẹ̀ẹ̀fà Nàìjíríà pẹ̀lú ìran lati gbòòrò dé àwọn agbègbè mìíràn ní ọjọ́ iwájú.

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Yinka Ayefele's Fresh FM Begins Transmission in Ekiti". InsideOyo.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-07-19. Retrieved 2021-12-08. 
  2. Abdulrahman, Adebayo (2020-07-10). "PHOTOS: Ayefele’s 106.9 FM, Modeled After BBC, Begins Test Transmission In Ado-Ekiti". OyoInsight (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-12-08. 
  3. "Dr. Yinka Ayefele Adds Ilorin, Lagos to his list of Network Stations -" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-28. Retrieved 2022-02-23. 
  4. "Fresh 105.9 FM". Streema. Retrieved 2022-02-23.