Igbobi College (Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Igbobi) jẹ́ kọlẹẹjì ti ìṣẹ̀tọ́ ètò nípasẹ̀ àwọn Methodist àti Àwọn ilé ìjọsìn Anglican ní ọdún 1932, ní agbègbè Yaba ní Ìlú Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Gúúsù ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà. Ó tún wà lórí ààyè atìlẹ̀bá rẹ̀ àti púpọ̀ jùlọ àwọn ilé àtilébá rẹ̀ ṣì wà ní ipò gidi tí ó wà láti lẹ̀. Ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ilé-ìwé gíga jùlọ ní Ilẹ̀ Nàìjíríà, àti pé ó ti jẹ́ ilé-ìwé tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọmọ Nàìjíríà olókìkí ti jáde. Ní ọdún 2001 ilé-ìwé náà ti padà sí ọ̀dọ̀ àwọn tí ó níi ní atìlẹ̀bá nípasẹ̀ Bola Tinubu ti ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó.[1]

Igbobi College Emblem
Igbobi college
Front view of igbobi college

Ọgbọ́ntarìgì Àwọn Akékọ̀ọ́ Tó Ti Igbobi Jáde àtúnṣe

Ibi Àwòrán Kékeré àtúnṣe

Ìjápọ̀ Ohun Tó Rànmo Igbobi àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́ka Sí àtúnṣe

  1. Atueyi, Ujunwa (15 August 2019). "Anglican, Methodist churches sign pact to advance Igbobi College". Guardian (Nigeria). https://guardian.ng/features/education/anglican-methodist-churches-sign-pact-to-advance-igbobi-college/.