Jamopyper
Jamiu Damilare Tajudeen (tí wọ́n bí ní 25 October 1995) tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Jamopyper, jẹ́ olórin Afrobeat ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1][2] Ní ọdún 2020, Jamopyper tẹwọ́bọ̀wé pẹ̀lú Zlatan ibile, tó ni "Zanku Records".[3] Wọ́n yàn án fún ọ̀kan lára àwọn àmì-ẹ̀yẹThe Headies 2020.[4][5]
Jamopyper | |
---|---|
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Jamiu Damilare Tajudeen |
Ọjọ́ìbí | 25 Oṣù Kẹ̀wá 1995 |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Instruments | Vocals |
Associated acts |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Jamo Pyper brings something new to the scene". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 21 June 2020. Retrieved 2021-07-02.
- ↑ "Jamopyper : I Don't Want to be Known for a Particular Sound". THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 10 July 2021. Retrieved 2021-07-12.
- ↑ "Zlatan launches his record label, ZANKU Records and promotes his new act, Oberz". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 12 February 2020. Retrieved 2021-07-12.
- ↑ "Omah Lay, Tems, Bella Shmurda... five music stars to look out for in 2021". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 3 January 2021. Retrieved 2021-07-12.
- ↑ "14th Headies Awards: Davido, Wizkid, Burna Boy Nominated". The Guardian Nigeria News – Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 4 December 2020. Archived from the original on 2021-02-22. Retrieved 2021-07-12.