Zlatan
Ọmọ́níyì Tèmídayọ̀ Raphael (bí ní ọjọ́ kọnkọ̀dínlógún oṣù Kejìlá ọdún 1994), tí wọ́n mọ̀ ọ́ ní tiyì sí Zlatan Ìbílẹ̀, jẹ́ Rápà, Akọrin, Akọ-Orin, Olórin àti Oníjó Nàìjíríà láti Èkìtì,[1] Ijero local government area, Ìpínlẹ̀ Èkìtì.[2] Ó jẹ́ Olórí àti Olùdásílẹ̀ Zanku Records.[3] Ní ọdún 2014, ó gba ipò àkọ́kọ́ tí ilé-iṣẹ́ Airtel pàsè tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ One Mic talent show tí wọ́n ṣe ní ọdún 2014, Abéòkúta, Ìpínlẹ̀ Ògùn.[4]
Zlatan | |
---|---|
zlatan Ibile | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Omoniyi Temidayo Raphael |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Zlatan Ibile, Kapaichumarimarichupako , World President |
Ọjọ́ìbí | 19 Oṣù Kejìlá 1994 Lagos, Nigeria |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Instruments | Vocals, Drums |
Years active | 2014-Present |
Labels | Zanku Records |
Associated acts |
Kó tó di ìparí ọdún 2018, Zlatan kọ orin sílẹ̀ tí ó pè ní Zanku", pẹ̀lú ijọ́ tuntun tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ orúkọ orin náà.[5] Ní ọjọ́ kẹ́ta oṣù kọkọ̀nlá ọdún 2019,Ó fi álíbọ̀bù àkọ́kọ́ rẹ̀ sílẹ̀ tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ ZANKU, tí ó túmọ̀ sí Zlatan Abeg No Kill Us.[6] Akọrin náà sọ wí pé ó wu òun láti di Agbábọ̀lù-Afẹṣẹ̀gbá ní ọdún 2020, pé kí í ṣe Olórin.[7]
Ọmọ́níyì Tèmídayọ̀ Raphael (bí ní ọjọ́ kọnkọ̀dínlógún oṣù Kejìlá ọdún 1994), tí wọ́n mọ̀ ọ́ ní tiyì sí Zlatan Ìbílẹ̀, jẹ́ Rápà, Akọrin, Akọ-Orin, Olórin àti Oníjó Nàìjíríà láti Èkìtì,[8] Ijero local government area, Ìpínlẹ̀ Èkìtì.[9] Ó jẹ́ Olórí àti Olùdásílẹ̀ Zanku Records.[10] Ní ọdún 2014, ó gba ipò àkọ́kọ́ tí ilé-iṣẹ́ Airtel pàsè tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ One Mic talent show tí wọ́n ṣe ní ọdún 2014, Abéòkúta, Ìpínlẹ̀ Ògùn.[11]
Kó tó di ìparí ọdún 2018, Zlatan kọ orin sílẹ̀ tí ó pè ní Zanku", pẹ̀lú ijọ́ tuntun tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ orúkọ orin náà.[12] Ní ọjọ́ kẹ́ta oṣù kọkọ̀nlá ọdún 2019,Ó fi álíbọ̀bù àkọ́kọ́ rẹ̀ sílẹ̀ tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ ZANKU, tí ó túmọ̀ sí Zlatan Abeg No Kill Us.[13] Akọrin náà sọ wí pé ó wu òun láti di Agbábọ̀lù-Afẹṣẹ̀gbá ní ọdún 2020, pé kò kí í ṣe Olórin.[14]
Ìbẹ̀ẹ̀rẹ Ayé àti ìgbé ayé rẹ̀
àtúnṣeỌmóníyì Tèmídayọ̀ Raphael jẹ́ bíbí àti dàgbà ní Ìlọrin, Ìpínlẹ̀ Kwara ṣùgbọ́n ó ní ìbátan pẹ̀lú Ìpínlẹ̀ Èkìtì. Ní ọdún 2011, ó jáde pẹ̀lú ìmọ̀ ètò ìṣòwò ní Moshood Abíọ́lá Politẹ́nííkì.[15][16] Zlatan pinnu láti mú orin kíkọ ní iṣẹ́-ààjò rẹ̀ lẹ́yìn tó parí ilé-ìwé sẹ́kọ́ndírì.[17] Ní ìgbà tí ó pé ọmọ ọdún mọkàndínlógún, ó gba ipò kìíní ní ìdíje tí Airtel pàsè èyí tí wọ́n ṣe ní ọdún 2014 "One Mic Campus Tour" ìdíje Olórin, tí wọ́n ṣe ní Abẹ́òkúta, Ìpínlẹ̀ Ògùn.[18] Ó di ìlú mọ̀ ọ́ ká láàárín ẹgbé akọrin Nàìjíríà lẹ́yìn tí ó fí orin tí Ọlámìídé ràn ọ́ lọ́wọ́ nínu ẹ̀"My Body" ní ọdún 2017.[19][17] Ní ọdún 2018, Lawrence Irabor, ìkan lára àwọn tó ni Alleluyah Boiz Entertainment fọwọ́ bọ ìwé pẹ̀lú Zlatan sí láàárín wọn A.B.E. Record. Nígbà tó gbó orin tí Zlatan kọ pẹ̀lú Ọlámìídé, ó wá sọ wí pé ‘I Don’t Regret Signing Zlatan T o A.B.E Records’.
Àwọn orin rẹ̀
àtúnṣeÀwo orin rẹ̀
àtúnṣe- Zanku (2019)
- Resan (2021)[20]
Àwọn orin àdákọ rẹ̀
àtúnṣeYear | Title | Album | Ref | |
---|---|---|---|---|
2016 | rowspan="9"style="background: #ececec; color: grey; vertical-align: middle; text-align: center; " class="table-na" | Non-album single | [21] | ||
2017 | "Omoge" | [22] | ||
"My Body" (featuring Olamide) | [23] | |||
2018 | "Jogor" (featuring Lil Kesh and Naira Marley) | [24] | ||
"Zanku (Legwork)" | [25] | |||
"Oja" | [26] | |||
"Osanle" (featuring [Davido) | [27] | |||
2019 | "This Year" | |||
"4 Days in Ekohtiebo" | [28] | |||
"Killin Dem" (with Burna Boy) | African Gaint | |||
"Shotan" (featuring Tiwa Savage) | Zanku | |||
"kokosa" (featuring Juls, Damibliz, Jorlasi) | [8] | [9] | ||
style="background: #ececec; color: grey; vertical-align: middle; text-align: center; " class="table-na" | Non-album single | ||||
"Gbeku" (featuring Burna Boy) | Zanku | [10] | ||
"Yeye Boyfriend" | [11] | |||
2020 | rowspan="2" style="background: #ececec; color: grey; vertical-align: middle; text-align: center; " class="table-na" | Non-album single | [12] | ||
"Unripe Pawpaw" (featuring Papisnoop, Jamo Pyper and Oberz) | [13] | |||
2020 | "The Matter" | Non-album single | [14] | |
2020 | "Soro Soke" | Non-album single | [15] | [16] |
2020 | "Lagos Anthem" | Non-album single | ||
2021 | "Alubarika" (featuring Buju ) | Resan | [18] | |
2021 | "Ale Yi" | Resan |
- As featured artist
Year | Title | Album | Ref |
---|---|---|---|
2019 | "Jo" (Dammy Krane featuring Zlatan and Olamide)|rowspan="12" style="background: #ececec; color: grey; vertical-align: middle; text-align: center; " class="table-na" | Non-album single | [19] | |
"Am I a Yahoo Boy" (Naira Marley featuring Zlatan) | |||
"Kowope" (HDT featuring Zlatan and GCN) | [29] | ||
"Flenjo" (Ceeza Milli featring Zlatan) | |||
Lock Up (Davolee ft. Zlatan) | [30] | ||
"Chacha" (Remix) (Harrysong featuring Zlatan) | |||
"Onye Eze 2.0" (CDQ featuring Zlatan) | [31] | ||
"Gelato" (DJ Cuppy featuring Zlatan) | [32] | ||
2020 | "Chairman" (Remix) (Dremo featuring Zlatan) | [33] | |
"Pongilah" (Slimcase featuring Zlatan) | [34] | ||
"Egungun" (Remix) (Obesere featuring Zlatan) | [35] | ||
"Of Lala" (Rahman Jago featuring Zlatan and Jamo Pyper) | [36] | ||
"O Por" (Rexxie featuring Zlatan) | Afro Street Vol. 1 | [37] |
Awọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣeYear | Event | Prize | Recipient | Result | Ref |
---|---|---|---|---|---|
2018 | City People Music Awards | Rookie of the Year | Himself|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [38] | |
2019 | The Headies | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [39] | ||
Best Street Hop Artiste | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
Best Coaborations | Gbàá | ||||
Song of the Year | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
African Muzik Magazine Awards | Best New Act | Gbàá | [40] | ||
Best Collaboration | Gbàá | ||||
Song of the Year | Gbàá | ||||
2021 | Net Honours | Most Searched Actress | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [41] | |
Most played street hop song | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
Most played Hip Hop song | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé |
Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Joy as ijurin Ekiti opens a community library". Tribune. 21 January 2021. https://tribuneonlineng.com/joy-as-ijurin-ekiti-opens-community-library/.
- ↑ "Zlatan Ibile - Biography". Streetot. Archived from the original on 6 October 2021. Retrieved 7 December 2019..
- ↑ Alake, Motolani (12 February 2020). "Zlatan launches his record label, ZANKU Records and promotes his new act, Oberz". Pulse.ng. Retrieved 19 November 2021.
- ↑ "19-year-old student wins Airtel One Mic Talent show". The Nation Nigeria. 2014-06-02. Retrieved 2019-04-09.
- ↑ "Zanku: the new viral dance that has taken over the Nigerian music scene". Pulse.ng. 2018-12-12. Retrieved 2019-04-09.
- ↑ Motolani Alake (November 4, 2019). "Zlatan's debut album, 'ZANKU' suffers from lack of vision and terrible A&R [Album Review]". Pulse Nigeria. Pulse Nigeria. Retrieved 6 December 2019.
- ↑ "MTV Base Behind The Story: I wanted to be a footballer, not musician". Vanguardngr.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-02-17. Retrieved 2021-02-26.
- ↑ 8.0 8.1 "Zlatan x Damibliz x Juls x Worlasi – "Kokosa" » tooXclusive | MP3". tooXclusive (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-02-14. Archived from the original on 2020-11-01. Retrieved 2021-04-17.
- ↑ 9.0 9.1 "Zlatan - Ale Yi" » NaijaLanded | MP3". NaijaLanded (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-02-14. Archived from the original on 2021-10-23. Retrieved 2021-04-17.
- ↑ 10.0 10.1 Damola Durosomo (October 28, 2019). "Zlatan and Burna Boy Drop Another Banger With New Single 'Gbeku'". OkayAfrica. Retrieved 6 December 2019.
- ↑ 11.0 11.1 Damola Durosomo (October 23, 2019). "Zlatan Drops New Song and Video 'Yeye Boyfriend'". OkayAfrica. Retrieved 10 May 2020.
- ↑ 12.0 12.1 "[Music] Zlatan - Quilox | Mp3 Download « NotJustOk". Latest Naija Nigerian Music, Songs & Video - Notjustok (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-01-06. Archived from the original on 2020-03-07. Retrieved 2020-04-28.
- ↑ 13.0 13.1 "Zlatan - Unripe Pawpaw | Video & Mp3 Download « NotJustOk". Latest Naija Nigerian Music, Songs & Video - Notjustok (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-03-14. Archived from the original on 2020-04-22. Retrieved 2020-04-28.
- ↑ 14.0 14.1 "DOWNLOAD Zlatan – The Matter". lokcitymusic.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-06-14. Retrieved 2020-05-31.
- ↑ 15.0 15.1 "[Music] Zlatan - Soro Soke (EndSARS) » Naijaloaded". Naijaloaded (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-10-21. Retrieved 2021-01-22.
- ↑ 16.0 16.1 "Zlatan – Resan » Legitbaze". Legitbaze (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-10-21. Archived from the original on 2021-10-08. Retrieved 2021-01-22.
- ↑ 17.0 17.1 "I am not signed to Davido's record label – Zlatan Ibile". Ghanaweb.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-04-12.
- ↑ 18.0 18.1 BellaNaija.com (2021-08-17). "New Video: Zlatan feat. Buju – Alubarika". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-18.
- ↑ 19.0 19.1 "Zlatan x Dammy Krane x Olamide – "Jo"". TooXclusive. February 28, 2019. Archived from the original on 6 December 2019. Retrieved 6 December 2019.
- ↑ Motolani Alake (9 November 2021). "Wow Zlatan! you did that 'Resan'". Pulse. Retrieved 20 December 2021.
- ↑ Jim Donnett (February 6, 2016). "Zlatan X Spaceboi – "Odun Yi"". TooXclusive. Retrieved 6 December 2019.
- ↑ Al Yhusuff (March 2, 2017). "Zlatan Ibile – "Omoge" ft. Oritsefemi". TooXclusive. Retrieved 6 December 2019.
- ↑ Marcus Brown (October 13, 2017). "Zlatan – My Body ft. Olamide". TooXclusive. Archived from the original on 6 December 2019. Retrieved 6 December 2019.
- ↑ Oluwatobi Ibironke (May 11, 2018). "Zlatan – "Jogor" f. Lil Kesh x Naira Marley". TooXclusive. Archived from the original on 6 December 2019. Retrieved 6 December 2019.
- ↑ Tomiwa (October 19, 2018). "Zlatan – "Zanku"". TooXclusive. Archived from the original on 6 December 2019. Retrieved 6 December 2019.
- ↑ Oghene Michael (February 4, 2018). "MUSIC: Zlatan Ibile – Oja". 360nobs. Archived from the original on 7 December 2019. Retrieved 6 December 2019.
- ↑ Posted by Adeyanju Adewumi on November 7, 2018 at 7:24am in Entertainment. "DOWNLOAD MUSIC: Zlatan Ft. Davido – Osanle mp3". Community.vanguardngr.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-04-12.
- ↑ "Days After Release From EFCC Custody, Zlatan Ibile Drops Single '4 Days In Okotie Eboh'". Saharareporters.com. Retrieved 19 November 2021.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "HDT – "Kowope" f. Zlatan & GCN". TooXclusive. July 15, 2019. Retrieved 6 December 2019.
- ↑ Tomiwa (October 2, 2019). "Davolee x Zlatan – "Lock Up"". TooXclusive. Archived from the original on 6 December 2019. Retrieved 6 December 2019.
- ↑ "CDQ x Zlatan – "Onye Eze 2.0"". TooXclusive. June 27, 2019. Retrieved 6 December 2019.
- ↑ Michael Bamidele (16 August 2019). "DJ Cuppy & Zlatan Serves Us Party Flavoured "Gelato"". Guardian Life. Archived from the original on 6 December 2019. Retrieved 6 December 2019.
- ↑ "Dremo ft. Zlatan - Chairman (Remix) | Mp3 Download « NotJustOk". Latest Naija Nigerian Music, Songs & Video - Notjustok (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-01-23. Archived from the original on 2020-03-21. Retrieved 2020-04-28.
- ↑ "Slimcase - Pongilah Ft. Zlatan » Naijaloaded | Mp3 Download". Naijaloaded (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-01-30. Retrieved 2020-04-28.
- ↑ Peter OKH (March 19, 2020). "Obesere ft. Zlatan – Egungun (Remix)". NotJustOk. Archived from the original on 19 March 2020. Retrieved 19 March 2020.
- ↑ "Rahman Jago Of Lala Ft. Zlatan » Naijaloaded | Mp3 Download". Naijaloaded (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-14. Retrieved 2020-04-28.
- ↑ "Rexxie ft. Zlatan - O Por". Notjustok (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-25. Archived from the original on 2020-04-25. Retrieved 2020-04-28.
- ↑ Reporter (2018-10-17). "#CPMA2018: City People Music Awards Nominees' List Out". City People Magazine. Retrieved 2019-04-12.
- ↑ Gbenga Bada (October 20, 2019). "Headies 2019: Here are all the winners at the 13th edition of music award". Pulse Nigeria. Retrieved 20 October 2019.
- ↑ "Here Are the Winners at the 2019 African Muzik Magazine Awards in Dallas". OkayAfrica. October 28, 2019. Retrieved 6 December 2019.
- ↑ Mofijesusewa, Samuel (2021-06-20). "NET Honours 2021: “Damages” by Tems Named Most Played Alternative Song". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-07-21. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)