Johnny Drille
John Ighodaro (tí a bí ní ọjọ́ karùn-ún oṣù keje, ọdún 1990), tí gbogbo èèyàn mọ sì Johnny Drille, jẹ́ akọrin àti òǹkọrin tí Nàìjíríà. Iṣẹ́ orin rẹ̀ di ohun mímọ̀ nígbà tí ó tún orin Diʼja tí àkọlé rẹ jẹ "Awww" kọ. Wọ́n tí gba gẹ́gẹ́ bí ara àwọn olórin Mavin Records.[1][2]
Johnny Drille | |
---|---|
Background information | |
Orúkọ àbísọ | John Ighodaro |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Johnny Drille |
Ọjọ́ìbí | 5 Oṣù Keje 1990 Edo, Nigeria |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Instruments |
|
Years active | 2012–present |
Labels | Mavin Records |
Associated acts |
Ìbẹ̀rẹ̀ Ìgbésí Ayé Rẹ̀
àtúnṣeA bí a sì tọ́ Johnny Drille ni ìpínlẹ̀ Edo, Nàìjíríà. Bàbá rẹ̀ jẹ́ ọ̀gá ilẹ̀ - ẹ̀kọ́ àti Àlùfáà. Ò ní ọmọ ìyá mẹ́rin. Drill bẹ̀rẹ̀ ọrin kíkọ ni ilẹ̀ ìjọosìn bàbà rẹ̀ láti ọmọọ kékeré.
Ètò ẹ̀kọ́
àtúnṣeÓ lọ sí Yunifásitì tí Benin, Beninn, níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì àti litiréṣọ̀.[3][4]
Ìṣe tó yàn láàyò
àtúnṣeDrille bẹ̀rẹ̀ ìṣe orin íkọ ni ilẹ̀ ìjọsìn. Ó jé ọkàn lára àwọn olùdíje àgbéjáde kẹfà tí project Fame West Africa ni 2013.[5][6] Ni 2015, ó sʼàgbéjáde ẹ̀dà orin Di'Ja' tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Awww", eyí tí ó sì pe àkíyèsí Olùdarí Mavin's tí Don jazzy Orin àkọ́kọ́ tí ó dá kọ ní "Wait for Me" tí ó sì gbé jáde ní 2015. Wọ́n yàn fún Best Alternative Song ńi The Headies 2016. Ó kẹ́gbẹ́ pẹ̀lú Niniola, èyí tí ó jẹ ọ̀kan lára olùdíje àgbéjáde kẹfà, ti wọn jọ kọ "Start All Over".[7] Ní oṣù kejì ọdún 2017, ó buwọ́ lu ìṣe orin kíkọ pẹ̀lú Mavin Records.[8][9] Ní oṣù kẹsàn-án, 2021, ó sʼàgbéjáde àwo orin rẹ̀ àkọ́kọ́, èyí tí ó ní tíràkì mẹ́rìnlá tí àkọ́lé rẹ sì jẹ n [10]'Before We Fall Asleep' ti o pe àwọn ọlọ́rin tí ó sì tún jé ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Ayra Starr, Ladipoe, Lagos community choir, DonRecords., Chylde, Kwitte, Cilsoul and the classic afro R&B group, Styl plus lábẹ́ the label Mavin Records.
Ìgbésí ayé
àtúnṣeJohnny fẹ́ adarí orin tí orúkọ rẹ ǹjẹ́ Rima Tahini.[11]
Àtọ̀jọ àwọn orin rẹ̀
àtúnṣeÀwo orin
àtúnṣeTitle | Album details | Ref. |
---|---|---|
Before We Fall Asleep |
|
[12][13] |
EP
àtúnṣeTitle | Details | Peak chart positions |
---|---|---|
NG | ||
Home[15] |
|
12 |
Orin àdákọ
àtúnṣe- 2015 – "Wait for Me"
- 2015 - "Love Don't Lie"
- 2016 – "My Beautiful Love"
- 2016 - "Start All Over (Featuring Niniola)
- 2017 – "Romeo & Juliet"
- 2018 – "Halleluya" (featuring Simi)
- 2018 – "Awa Love"
- 2019 - "Forever"
- 2019 - "Shine"
- 2019 - "Finding Efe"
- 2019 - "Papa"
- 2019 - "Dear Future Wife"
- 2019 - "Count on You"
- 2020 - "Something Better"
- 2020 - "Mystery Girl"
- 2021- "Ova"
- 2021 - "Bad Dancer"
- 2021 - "Loving Is Harder"
- 2021- "Odo"
- 2021- "Sister"
- 2021- "In the light"
- 2021- "Sell my soul"
- 2022 - "How Are You (My Friend)"[16]
- 2022- "All I'm saying"
- 2022- " Love and life"
- 2022- "Journey of our lives
- 2023- "Believe me"
- 2023- "The Best Part"
Àtòjọ àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣeYear | Event | Prize | Recipient | Result | Ref |
---|---|---|---|---|---|
2016 | The Headies | Best Alternative Song | "Wait for Me" | Wọ́n pèé | [17] |
2018 | Best Vocal Performance (Male) | "Romeo & Juliet" | Wọ́n pèé | [18][19] | |
Best R&B Single | Wọ́n pèé | ||||
Best Alternative Song | Wọ́n pèé | ||||
Next Rated | Himself | Wọ́n pèé | |||
2019 | Best Alternative Song | "Finding Efe" | Gbàá | [20] | |
Best Vocal Performance (Male) | Wọ́n pèé |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Adelagun, Oluwakemi (August 10, 2018). "Why Nigerian musicians fall out with their record labels – Johnny Drille". Premium Times. https://www.premiumtimesng.com/entertainment/music/279634-why-nigerian-musicians-fall-out-with-their-record-labels-johnny-drille.html. Retrieved August 21, 2018.
- ↑ Odoh, Chux (May 6, 2018). "HEADIES 2018: 'It Only Gets Better From Here' – Johnny Drille Speaks on Headies Loss". The Net. http://thenet.ng/headies-2018-gets-better-johnny-drille-speaks-headies-loss/. Retrieved August 21, 2018.
- ↑ Ibori, Diana (January 15, 2018). "Johnny Drille's biography and career achievements". Naija.ng. Archived from the original on August 21, 2018. https://web.archive.org/web/20180821223152/https://www.naija.ng/amp/1141618-johnny-drilles-biography-career-achievements.html. Retrieved August 21, 2018.
- ↑ [https://mavinrecords.com/M/johnny-drille/ Mavin Records]
- ↑ Amade, Alex (August 3, 2013). "16 contestants enters MTN project fame season 6 academy". Vanguard. https://www.vanguardngr.com/2013/08/16-contestants-enters-mtn-project-fame-season-6-academy/amp/. Retrieved August 21, 2018.
- ↑ Adetu, Bayo (August 2, 2013). "MTN Project Fame Season 6 Contestants Unveiled". PM News Nigeria. https://www.pmnewsnigeria.com/2013/08/02/mtn-project-fame-season-6-contestants-unveiled/amp/. Retrieved August 21, 2018.
- ↑ Solanke, Abiola (June 3, 2016). "New Music Niniola, Johnny Drille – 'Start all over'". Pulse Nigeria. https://www.pulse.ng/entertainment/music/new-music-niniola-johnny-drille-start-all-over-id5110385.html. Retrieved August 21, 2018.
- ↑ "Johnny Drille".
- ↑ Young (July 7, 2018). "Johnny Drille Explains How He Got A Record Deal with Mavin". Information Nigeria. https://www.informationng.com/2018/07/johnny-drille-explains-how-he-got-a-record-deal-with-mavin.html/amp. Retrieved August 21, 2018.
- ↑ "DOWNLOAD: Johnny Drille drops ‘Before We Fall Asleep’ album". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-09-03. Retrieved 2021-09-26.
- ↑ Akinyode, Peace (2023-07-04). "Social media abuzz as Johnny Drille's wedding pictures go viral". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-07-04.
- ↑ Alake, Motolani (2021-09-10). "Johnny Drille’s ‘Before We Fall Asleep’ is worth its ‘wait’ in needed evolution [Pulse Album Review]". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-11-08.
- ↑ 1883 (2021-09-03). "Johnny Drille - ‘Before We Fall Asleep’ - Track By Track". 1883 Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-11-08.
- ↑ "Nigeria Top 50 Albums". www.turntablecharts.com. TurnTable. Retrieved 11 November 2022.
- ↑ BellaNaija.com (2022-10-28). "New EP + Video: Johnny Drille – Home". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-11-08.
- ↑ Itodo, Sunny Green (2023-07-10). "Death of Don Jazzy's mum inspired my hit song - Johnny Drille". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-11-08.
- ↑ Adelana, Oladolapo (November 9, 2016). "Full list of nominees for the 2016 Headies Awards". YNaija. https://www.ynaija.com/full-list-of-nominees-for-the-2016-headies-awards/amp/. Retrieved August 21, 2018.
- ↑ Odoh, Chux (May 6, 2018). "HEADIES 2018: 'It Only Gets Better From Here' – Johnny Drille Speaks on Headies Loss". The Net. http://thenet.ng/headies-2018-gets-better-johnny-drille-speaks-headies-loss/. Retrieved August 21, 2018.
- ↑ Anonymous (April 13, 2018). "Headies 2018: Full list of nominees". Punch. https://punchng.com/headies-2018-full-list-of-nominees/. Retrieved August 21, 2018.
- ↑ Gbenga Bada (October 20, 2019). "Headies 2019: Here are all the winners at the 13th edition of music award". Pulse Nigeria. Retrieved 20 October 2019.