Joseph Adéyemí
Babatunde Joseph Adéyemí jẹ biṣọọbu Ánglíkánì ní Nàìjíríà, ọ jẹ Bishop ti Badagry lọ́wọ́lọ́wọ́.[1] [2][3][4]
Joseph Adéyemí | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 14 Oṣù Kejì 1957 |
Ẹ̀kọ́ | Lagos State University |
Ọjò kérìnlá oṣù kìnnì ọdún 1957 ní wọ́n bí Adeyemi ní Ojo ni Ìpínlẹ̀ Èkó. Ọ tí kọ ẹkọ ní Government Teachers’ Training College ní Badagry; Emmanuel College of Theology ní ìlú Ìbàdàn; àtí Lagos State University. Lẹ́hin ọdun mẹ́ta gẹ́gẹ́bi olùkọ́, ọ jẹ diakoni ní 1984 atí álụfá ní ódun 1986. Lẹ́hin ìwe-kíkọ́ ní Ebute Metta, ọ ṣé awọn ìṣẹ ní Awodi-Ora, Idumu átí Festac Town. Ọ dì Canon ní ọ́dun 1999 átí Archdiakoni tí Festac ní ọ́dun 2000.
Ọ tí yásọtọ gẹ́gẹ́ bí Bishop aṣáájú-ọnà tí Badagry ní ọ́jọ́ 13 Oṣu Kẹ́ta 2005.[5] Ó tí jẹ́ alábòójútó Ẹgbẹ́ Ìwé Mímọ́ Èkó láti ọdún 2010.
Àwọn itọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Anglican Communion Office. "Diocese - Nigeria - Badagry". anglicancommunion.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-12-04.
- ↑ "The Rt Joseph Adeyemi - The Church Of Nigeria (Anglican Communion) - Anglican Communion". worldanglican.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-12-04.
- ↑ "Anglicans Online | Nigeria". anglicansonline.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-12-04.
- ↑ "GadgetVicar: Nigeria - Day 3 - Badagry and the Church of Pentecost". gadgetvicar.org.uk (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-12-04.
- ↑ "Church of Nigeria now has 91 dioceses". www.anglicannews.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-03-14.