Lagos Cougars jẹ́ fíìmù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jáde ní ọdún 2013 tó jẹ́ fíìmù ajẹmọ́fẹ̀ẹ́, èyí tíDesmond Elliot.[1] Ìṣàfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ wáyé ní ọjọ́ kẹta oṣù kejìlá ọdún 2013, ní Silverbird Galleria, Victoria Island.[2] Fíìmù náà dá lórí àwọn òṣìṣébìnrin mẹ́ta; Elsie (Monalisa Chinda), Aret (Uche Jombo) àti Joke (Daniella Okeke) pẹ̀lú ìlàkàkà wọn láti ṣalábàápàdé ìfẹ́.

Lagos Cougars
AdaríDesmond Elliot
Olùgbékalẹ̀Emem Isong
Àwọn òṣèré
Ilé-iṣẹ́ fíìmùRoyal Arts Academy
Olùpín
  • Royal Arts Academy
  • Silverbird Distributions
Déètì àgbéjáde
  • 3 Oṣù Kejìlá 2013 (2013-12-03)
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèEnglish

Àwọn akópa

àtúnṣe

Ìgbàwọlé

àtúnṣe

Fíìmù náà ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àríwísí. Nollywood Reinvented fún fíìmù yìí ní ìṣedára 18%, nítorí pé àhùnpọ̀ ìtàn náà ó dára tó, bẹ́ẹ̀ sì ni ìṣedarí rẹ̀ ò dára tó.[3]

YNaija bomi lu ọ̀rọ̀ ìfẹ́ tó wà láàárín Monalisa Chinda àti olólùfẹ́ rẹ̀ Benjamin Touitou. Wọ́n sọ ọ́ di mímọ̀ pé "Fíìmù Lagos Cougars panilẹ́rìn-ín ṣùgbọ́n àwàdá inú rẹ̀ ò bára mu".[4]

Sodas àti Popcorn sọ ọ́ nínú àríwísí wọn pé "...ìtàn náà ò kẹnú, kò sí ní ẹ̀yà kankan tí a lè fi wé...".[5]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Lagos Cougar". moviepencil.com. Archived from the original on 14 April 2014. Retrieved 8 May 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Lagos Cougar premieres". Archived from the original on 22 February 2014. Retrieved 8 May 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Lagos Cougar review on Nollywood Reinvented". Nollywood Reinvented. Retrieved 8 May 2014. 
  4. "Lagos Cougar is Funny but not always for the right reasons". YNaija. Retrieved 8 May 2014. 
  5. "Lagos Cougar review on Bella Naija". bellanaija.com. Retrieved 8 May 2014.