Desmond Elliot

Desmond Elliot ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹrin oṣù Kejì ọdún 1974. Jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, adarí eré àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà [2][3] Ó ti kópa nínú eré àti àwọn eré àtìgbà-dégbà onípele orí ẹ̀tọ amóhùn-máwòrán tí ó ti jú igba lọ ní orílẹ̀-èdè baba rẹ̀ ati ní òkè òkun.[4] Ó ti gba amì-ẹ̀yẹ fún amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹ̀dá ìtàn tí ó peregedé jùlọ níbi ayẹyẹ ti Africa Magic Viewers Choice Awards ẹlẹ́kejì irú rẹ̀, ó sì tún ti gba amì-ẹ̀yẹ fún amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹ̀dá ìtàn tí ó peregedé jùlọ níbi ayẹyẹ ti Africa Movie Academy Awards ẹlẹ́kẹwàá irú rẹ̀. Wọ́n tún yàn án kí ó lọ ṣojú àwọn ènìyàn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ SúrùlérèIlé ìgbìmọ̀ Aṣòfin ti Ìpínlẹ̀ Èkó nínú ìdìbò tí ó wáyé ní ọjọ́ kọkànlá oṣù Kẹrin ọdún 2015.

Desmond Elliot (ODE)
Desmond Elliot.jpg
Lagos State House of Assembly, Surulere constituency 1
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
11 April 2015
AsíwájúKabiru Lawal
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Olúwáṣọlá Desmond Elliot (ODE)

4 Oṣù Kejì 1974 (1974-02-04) (ọmọ ọdún 49)
Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ọmọorílẹ̀-èdèNàìjíríà
(Àwọn) olólùfẹ́Victoria Elliot[1]
OccupationActor
Film director
Politician

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀Àtúnṣe

Wọ́n bí Desmond ní agbègbè OlówógbowóÌpínlẹ̀ Èkó, bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ Yorùbá tí wọ́n bí ní agbègbè Lagos Island, ní Ìpínlẹ̀ Èkó tí ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ ìlú Illah ní ìjọba ìbílẹ̀ Oshimili North, ní Ìpínlẹ̀ Delta;[5]Ó kẹ́kọ̀ọ́ jáde ní ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ológun ojú òfurufú tí ó sì pada lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ St John's College, ní ìlú Jos. Ó kẹ́kọ̀ó gboyè nínú ìmọ̀ okòwò ní iléẹ̀kọ́ gíga ti Yunifásitì Ìpínlẹ̀ Èkó tí ó sì jáde ní ọdún 2003.[6]

Iṣẹ́ rẹ̀Àtúnṣe

Kíkópa nínú eré oníṣẹ́ orí-ìtàgé Demond ni ó jẹ́ wípé ọ̀rẹ́ rẹ̀.kan ni ó ṣokùnfà rẹ̀.[6] Ó bẹ̀rẹ̀ sí ń kópa nínú awọn eré onípele àtìgbà-dégbà ti Everyday People, One Too Much ati Saints and Sinners. Ó jẹ́ ọ̀kan lára awọn lààmì-laaka òṣèré ní ilé-iṣẹ́ Nollywood, nígbà tí ó ti kópa nínú awọn eré tí ó ti tó ọgọ́rùn ún tí a ti rí Men Who Cheat, Yahoo Millionaire àti Atlanta. Ní ọdún 2006, wọ́n yàn án fún Òṣèrékùnrin amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ tó peregedé jùlọ nínú amì-ẹ̀yẹ African Movie Academy Award nínú eré "Behind closed doors".[7][8][9] Ní ọdún 2018, Desmond pawọ́pọ̀ gbé eré tí akọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Reloaded. Eré tí wọ́n yàn fún amì-ẹ̀yẹ mẹ́ta ọ̀tọ̀tọ̀ bíi: African Movie Academy Awards ní ọdún 2009.[10][11][12][13] Wọ́n yàn án fún amì-ẹ̀yẹ Òṣèrékùnrin tí ó peregedé jùlọ ní ọdún 2009 àti ọdún 2010.[14] Ní ọdún 2014, wọ́n yan Elliot fún àmì-ẹ̀yẹ "African Movie Academy Award" fún amì-ẹ̀yẹ Òṣèrékùnrin amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ tó peregedé jùlọ nínú eré "Finding Mercy"[15]

Ìṣèlú rẹ̀Àtúnṣe

Elliot kéde ìfẹ́ rẹ̀ láti gbégbá ìbò sí Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó ní àsìkò ọdún 2014 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress. Ó díje sí ipò yí, ó sì wọlé láti ṣojú agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Sùúrùlérè nínú ìdìbò tí ó wáyé ní ọjọ́ kọkanlá oṣù Kerin ọdún 2015.[16]Ní inú oṣù Kẹwàá ọdún 2020 lásìkò rògbòdìyàn End SARS,[17] Wọ́n sọ̀rọ̀ sí Demond látàrí wípé ó fọwọ́ sí kí wọ́n fagi lé àwọn ìròyìn orí ìkanì ìbánidọ́rẹ̀ẹ́ gbogbo tabí kí wọ́na ṣe àgbéyẹ̀wọ̀ gbogbo ìròyìn tí yóò gba ibẹ̀ kọjá. [18][19][20] Nínú àwọn fọ́nrán fídíò tí ó ń kọjá nígboro lórí ìkanì ayélujára, wọ́n rí Desmond nínú fọ́rán yí wípé ó ń sọrọ̀ kíkan kíkan tako ìròyìn orí ìkanì ayélujára gbogbo. Bí kò bá rí bẹ́ẹ̀, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà yóò bàjẹ́.[1]] [21]

Ẹbí rẹ̀Àtúnṣe

Desmond Elliot àti ìyàwó rẹ̀ ti bímọ mẹ́rin.[12] si tun je agbẹnu sọ fún ilé-iṣẹ́ ì̀bánisọ̀rọ̀ Globacom.[12][22] Desmond àti ìyawó rẹ̀ ṣe ayẹyẹ ọdún kẹẹ̀dógún lórí ìgbéyàwó wọn ní ọjọ́ Kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 2018.[23]

Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀Àtúnṣe

Eré orí amóhù-máwòrán rẹ̀Àtúnṣe

See alsoÀtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasíÀtúnṣe

  1. "See Nollywood actor Desmond Elliot and his wife Victoria". 27 October 2011. Retrieved 9 October 2014. 
  2. "Desmond Elliot's Rebound Premieres in America". Lagos, Nigeria: National Daily Newspaper. Retrieved 31 July 2010. 
  3. Njoku, Benjamin (19 February 2010). "Desmond Elliot for Face of Hope". AllAfrica Global Media (Lagos, Nigeria). http://allafrica.com/stories/201002190902.html. Retrieved 1 December 2010. 
  4. "Desmond Elliot". IMDb. Retrieved 2020-08-31. 
  5. Olonilua, Ademola (20 September 2014). "From the tube to politics: Desmond Elliot, 9ice, KSB speak on controversies". The Punch Newspaper. The Punch NG. Archived from the original on 14 October 2014. Retrieved 9 October 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. 6.0 6.1 Onyekaba, Corne-Best (30 September 2005). "Why I run away from women". Daily Sun (Lagos, Nigeria). http://www.sunnewsonline.com/webpages/features/showtime/2005/sept/30/showtime-30-09-2005-001.htm. Retrieved 1 December 2010. 
  7. Kerrigan, Finola (2010). Film Marketing (1 ed.). Elsevier Ltd.. p. 87. ISBN 978-0-7506-8683-9. https://books.google.com/books?id=w2vDPMtYBt0C&pg=PA87&dq=%22desmond+elliot%22&hl=en&ei=uab2TIWJL4X94AbM3-2SBw&sa=X&oi=book_result&ct=result&resnum=4&ved=0CC8Q6AEwAw#v=onepage&q=%22desmond%20elliot%22&f=false. 
  8. Olukole, Ope (11 September 2010). "My Home Suffers A Lot 'Cos of My Career -Desmond Elliot". Nigerian Tribune (Ibadan, Nigeria). http://www.tribune.com.ng/sat/index.php/entertainment-extra/2005-my-home-suffers-a-lot-cos-of-my-career-desmond-elliot.html. Retrieved 1 December 2010. 
  9. Clayton, Jonathan (3 April 2010). "Nollywood success puts Nigeria's film industry in regional spotlight". The Times Online (London, UK: Times Newspapers Ltd). http://www.timesonline.co.uk/tol/news/world/africa/article7086248.ece#cid=OTC-RSS&attr=797093. Retrieved 1 December 2010. 
  10. "AMAA Nominees and Winners 2009". Lagos, Nigeria: African Movie Academy Awards. Archived from the original on 5 April 2011. Retrieved 1 December 2010.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  11. Salawi, Femi (14 August 2010). "Desmond Elliot". The Nation (Lagos, Nigeria: Vintage Press Limited). http://thenationonlineng.net/web3/sunday-magazine/screen/9547.html. Retrieved 1 December 2010. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  12. 12.0 12.1 12.2 "Glo Ambassadors – Desmond Elliot". Globacom. Archived from the original on 26 September 2011. Retrieved 1 December 2010.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  13. Njoku, Benjamin (27 November 2009). "Isong, Desmond Elliot, Uche Jombo premiere two movies". The Vanguard (Lagos, Nigeria). http://www.vanguardngr.com/2009/11/isong-desmond-elliot-uche-jombo-premiere-two-movies/. Retrieved 1 December 2010. 
  14. "List of Nominees: Nigerian Entertainment Awards 2010". Retrieved 1 December 2010. 
  15. Benjamin Njoku (19 February 2010). "Desmond Elliot for Face of Hope". AllAfrica Global Media. http://allafrica.com/stories/201002190902.html. Retrieved 1 December 2010. 
  16. "Actor Desmond Elliot wins Parliamentary elections in Nigeria". CitiFMOnline. 13 April 2015. Retrieved 13 April 2015. 
  17. https://www.vanguardngr.com/2020/10/davido-skales-others-blast-desmond-elliot-over-social-media-regulation/
  18. https://punchng.com/lagos-not-developing-bill-to-regulate-social-media-desmond-elliot/
  19. https://www.arise.tv/desmond-elliot-denies-pushing-social-media-regulation/
  20. https://www.kanyidaily.com/2020/10/desmond-elliot-denies-claims-that-he-sponsored-a-bill-to-regulate-social-media-in-lagos-video.html
  21. "Desmond Elliot Reacts After Nigerians Dragged Him For Allegedly Supporting An Anti-Social Media Bill (Video)". The African Media (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-10-27. Retrieved 2020-10-27. 
  22. Osuagwu, Prince (9 October 2009). "Arguments, doubt, surprises as Glo presents N8m, 21 cars to winners in Lagos". The Vanguard (Lagos, Nigeria). http://www.vanguardngr.com/2009/10/arguments-doubt-surprises-as-glo-presents-n8m-21-cars-to-winners-in-lagos/. Retrieved 1 December 2010. 
  23. Helen, Ajomole (26 December 2018). "Desmond Elliot and wife celebrate 15th wedding anniversary" (in en). Legit.ng - Nigeria news. (Naija.com). https://www.legit.ng/1211813-desmond-elliot-wife-celebrate-15th-wedding-anniversary.html. Retrieved 8 January 2019. 
  24. ""Black Val" Toyin Aimakhu, Iyabo Ojo, Dayo Amusa, Desmond Elliott attend premiere". Pulse.ng. Chidumga Izuzu. Retrieved 16 February 2016. 
  25. "'The Department' Watch Osas Ighodaro, OC Ukeje, Majid Michel in trailer". Pulse Nigeria. Chidumga Izuzu. Retrieved 16 January 2015. 
  26. 26.0 26.1 Tope Olukole (31 July 2010). "We Want To Make People Cry And Laugh". Nigerian Tribune. http://www.tribune.com.ng/sat/index.php/entertainment-extra/1694-we-want-to-make-people-cry-and-laugh-uche-jombo.html?fontstyle=f-smaller. Retrieved 1 December 2010. 
  27. Samuel Olatunji (17 January 2010). "Isong, Jombo, Elliot shoot N20m movie". Daily Sun. http://www.sunnewsonline.com/webpages/features/showpiece/2010/jan/17/showpiece-17-01-2010-003.htm. Retrieved 1 December 2010. 
  28. 28.0 28.1 "Isong on the march again". AllAfrica Global Media. 13 June 2009. http://allafrica.com/stories/200906171066.html. Retrieved 1 December 2010. 
  29. Francis Addo (8 January 2010). "Desmond Elliot Premieres New Movie in Ghana". Peace FM Online. http://showbiz.peacefmonline.com/movies/201001/36081.php. Retrieved 1 December 2010. 
  30. "Review of King of The Town". Modern Ghana News. 7 October 2006. http://www.modernghana.com/print/521/4/review-of-king-of-the-town.html. Retrieved 1 December 2010. 
  31. Clemetina Olomu (24 June 2007). "Did the Zeb Ejiro And Ibinabo Love Story in Phillipine [sic Turn Sour?"]. AllAfrica Global Media. http://allafrica.com/stories/200706250990.html. Retrieved 1 December 2010. 
  32. Tony Erhariefe (19 March 2005). "Images in the Mirror sets to rule market". Daily Sun. http://www.sunnewsonline.com/webpages/features/blockbuster/2005/mar/19/blockbuster-19-03-2005-004.htm. Retrieved 1 December 2010. 
  33. "My Wife and My Kids are My World – Desmond Elliot". GhanaWeb. 30 January 2009. http://www.ghanaweb.com/GhanaHomePage/nigerianfilms/article.php?id=856. Retrieved 1 December 2010. 
  34. 34.0 34.1 34.2 "I Eat Right To Keep Fit- Desmond Elliot". Peace FM Online. 4 October 2010. http://showbiz.peacefmonline.com/movies/201010/88312.php. Retrieved 1 December 2010. 

Ìtàkùn ìjásódeÀtúnṣe

Àdàkọ:Authority control