Uche Jombo
Uche Jombo Rodriguez tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1979 (December 28, 1979), jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin àti oǹkọ̀tàn àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ Nàìjíríà.
Uche Jombo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Uche Jombo December 28, 1979 (ọmọ ọdún 44) Enugu
|
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ẹ̀kọ́ | University of Calabar |
Iṣẹ́ | Actress, Film Producer, director, Writer |
Olólùfẹ́ | Kenney Rodriguez |
Àwọn ọmọ | Matthew Rodriguez |
Ìgbésí ayé rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Uche Jombo sí ìlú Abiriba, ní Ìpínlẹ̀ Abia, lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà lọ́jọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1979. Ó kàwé gbàwé ẹ̀rí dìgírì nínú ìmọ̀ ìṣirò àti àtò-iye (Mathematics and Statistics) ní yunifásítì, University of Calabar, àti ìmọ̀ nípa Ètò Ìmọ̀ Ẹ̀rọ Kọ̀m̀pútà Computer Programming ní Federal University of Technology Minna.[1][2]
Àwọn àṣàyàn sinimá àgbéléwò rẹ̀
àtúnṣeỌdún | Sinimá | Ẹ̀dá-ìtàn | Àkíyèsí |
---|---|---|---|
1999 | Visa to hell[3] | ||
2000 | Girls Hostel | with Mary Uranta[4] | |
2002 | Fire Love | pẹ̀lú Desmond Elliot | |
2004 | Scout | pẹ̀lú Alex Lopez | |
2005 | Endless Lies | Becky | pẹ̀lú Desmond Elliot |
Darkest Night | pẹ̀lú Genevieve Nnaji, Richard Mofe Damijo àti Desmond Elliot | ||
Black Bra | |||
2006 | Secret Fantasy | pẹ̀lú Ini Edo | |
Price of Fame | pẹ̀lú Mike Ezuruonye àti Ini Edo | ||
My Sister My Love | Hope | pẹ̀lú Desmond Elliot | |
Love Wins | Ege | pẹ̀lú Desmond Elliot | |
Co-operate Runs | pẹ̀lú Zack Orji | ||
2007 | World of Commotion | pẹ̀lú Zack Orji àti Mike Ezuruonye | |
Rush Hour | |||
Price of Peace | pẹ̀lú Chioma Chukwuka àti Jim Iyke | ||
Most Wanted Bachelor | pẹ̀lú Ini Edo àti Mike Ezuruonye | ||
Keep My Will | pẹ̀lú Genevieve Nnaji àti Mike Ezuruonye | ||
House of Doom | pẹ̀lú Zack Orji àti Mike Ezuruonye | ||
Greatest Harvest | pẹ̀lú Pete Edochie | ||
Final Hour | pẹ̀lú Tonto Dikeh | ||
2008 | Feel My Pain | pẹ̀lú Mike Ezuruonye | |
Beyonce & Rihanna | Nichole | pẹ̀lú Omotola Jalade-Ekeinde, Nadia Buari àti Jim Iyke | |
2009 | Love Games | pẹ̀lú Jackie Appiah àti Ini Edo | |
Entanglement | pẹ̀lú Desmond Elliot, Mercy Johnson àti Omoni Oboli | ||
Silent Scandals | Muky | with Genevieve Nnaji & Majid Michel[5] | |
2010 | Home in Exile | pẹ̀lú Desmond Elliot | |
Holding Hope | Hope | pẹ̀lú Desmond Elliot àti Nadia Buari | |
2011 | Kiss and Tell | Mimi | pẹ̀lú Desmond Elliot àti Nse Ikpe-Etim |
Damage[6] | pẹ̀lú Tonto Dikeh | ||
2012 | Mrs Somebody | Desperado | |
2012 | Misplaced | Debra | with Van Vicker |
2013 | After The Proposal | Mary | with Patience Ozokwor and Anthony Monjaro |
2016 | Wives on strike[7] | pẹ̀lú Chioma Chukwuka and Omoni Oboli | |
2017 | Banana Island Ghost[8] | pẹ̀lú Chigul àti Dorcas Shola Fapson | |
2018 | Heaven On My Mind[9] | Uju | with Ini Edo |
2016 Lost in Us pẹ̀lú Okey Uzoeshi
Àwọn ìgbóríyìn
àtúnṣeỌdún | Ètò | Àmìn-ẹ̀yẹ | Àkọ́lé sinimá | Èsì |
---|---|---|---|---|
2008 | AfroHollywood Awards -UK | Òṣèrébìnrin tó dára jù | GbàáÀdàkọ:Cn | |
4th Africa Movie Academy Awards | Amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèrébìnrin tó dára jù | Keep My Will | Yàán | |
2010 | 2010 Best of Nollywood Awards | Amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèrébìnrin tó dára jù | Silent Scandals | Gbàá |
City People Entertainment Awards | Òṣèrébìnrin tó dára jù | GbàáÀdàkọ:Cn | ||
Abia State Awards | Àmìn ìbọláfún | Herself | Gbàá | |
Life Changers Awards-UK | Gbajúmọ̀ òṣèré Nollywood lọ́dún naa | Herself | Gbàá | |
5 Continents Awards -New York | Àmìn-ẹ̀yẹ afowóṣàánú | Herself | GbàáÀdàkọ:Cn | |
2011 | ELOY awards | Olú-ẹ̀dá-ìtàn òṣèrébìnrin tó dára jù | Damage | GbàáÀdàkọ:Cn |
2011 Best of Nollywood Awards | Olú-ẹ̀dá-ìtàn òṣèrébìnrin tó dára jù | Damage | Yàán | |
Òṣèré ojú ìran tó dára jù | Yàán | |||
Olùfẹnukẹnu to dára jù pẹ̀lú Kalu Ikeagwu | Yàán | |||
2012 | Nafca | Olú-ẹ̀dá-ìtàn òṣèrébìnrin tó dára jù | Damage | Gbàá |
Best Film | Gbàá[10] | |||
2012 Golden Icons Academy Movie Awards | Àmìn-ẹ̀yẹ ààyò àwọn òlùwòran tó dára jù | herself | Yàán | |
8th Africa Movie Academy Awards | Olú-ẹ̀dá-ìtàn òṣèrébìnrin tó dára jù | Damage | Yàán | |
2013 | Africa International Film Festival | Olú-ẹ̀dá-ìtàn òṣèrébìnrin tó dára jù | Lies Men Tell | Gbàá[11] |
2013 Best of Nollywood Awards | Olú-ẹ̀dá-ìtàn òṣèrébìnrin tó dára jù sinimá èdè Gẹ̀ẹ́sì | Mrs Somebody | Yàán | |
2014 | ELOY Awards[12] | Olóòtú obìnrin tó dára jù lọ́dún | N/A | Wọ́n pèé |
2014 Golden Icons Academy Movie Awards | Akópà ìran tó dára jù pẹ̀lú (Patience Ozokwor) | After The Proposal | Yàán | |
Àmìn-ẹ̀yẹ àwọn òlùwòran tó dára jù | Herself | Yàán | ||
2014 Africa Magic Viewers Choice Awards | Sinimá aláwàdà to dára jù | Lies Man Tell | Yàán | |
10th Africa Movie Academy Awards | Olú-ẹ̀dá-ìtàn òṣèrébìnrin tó dára jù | Lagos Cougars | Yàán | |
2015 | 2015 Golden Icons Academy Movie Awards | Òṣèrébìnrin tó dára jù | oge's sister | Yàán |
Female Viewers Choice | Herself | Gbàá |
Àwọn ìtọ́kasí ìta
àtúnṣeÀdàkọ:Authority control [http://guardian.ng/saturday-magazine/uche-jombos-heaven-on-my-mind-is-still-trending/ [https://web.archive.org/web/20190417001923/https://guardian.ng/saturday-magazine/uche-jombos-heaven-on-my-mind-is-still-trending/ Archived 2019-04-17 at the Wayback Machine. [https://www.vanguardngr.com/2018/10/uche-jombo-ini-edo-collaborate-on-new-movie-heaven-on-my-mind/[https://leadership.ng/2018/10/12/uche-jombo-debuts-heaven-on-my-mind/[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] [http://thenationonlineng.net/ini-edo-why-i-agreed-to-work-with-uche-jombo/ [https://www.pulse.ng/entertainment/movies/uche-jombo-releases-trailer-for-new-https://naijagists.com/heaven-on-my-mind-nigerian-movie-release-date-uche-jombo/movie-heaven-on-my-mind-id8995753.html)https://guardian.ng/saturday-magazine/uche-jombos-heaven-on-my-mind-is-ready/[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] [http://xplorenollywood.com/nta-uche-jombo-releases-poster-for-heaven-on-my-mind-a-directorial-debut/ [https://ynaija.com/heres-when-uche-jombos-directorial-debut-heaven-on-my-mind-will-hit-cinemas/ [https://www.stelladimokokorkus.com/2018/10/actors-uche-jombo-and-ini-edo-set-for.html
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Glo Ambassadors - Uche Jombo". Lagos, Nigeria: Globacom Limited. Archived from the original on 26 September 2011. Retrieved 28 September 2011. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Adeniran, Yemisi (10 September 2011). "I found acting boring -Uche Jombo". National Mirror (Lagos, Nigeria: Global Media Mirror Limited). Archived from the original on 8 June 2012. https://web.archive.org/web/20120608185706/http://nationalmirroronline.net/entertainment/celebrity/20296.html. Retrieved 28 September 2011.
- ↑ Olatunji, Samuel (26 June 2011). "Nollywood’s ‘A’ list stars". Daily Sun (Lagos, Nigeria). http://www.sunnewsonline.com/webpages/features/showtime/june/26/showtime-26-06-2011-001.html. Retrieved 28 September 2011.
- ↑ Erhariefe, Tony (2013-04-28). "Mary Uranta: Sexual harassment drove me out of Nollywood". Sunnewsonline.com (Daily Sun). Archived from the original on 2014-04-19. https://web.archive.org/web/20140419015616/http://sunnewsonline.com/new/?p=24700. Retrieved 2014-04-18.
- ↑ "Silent Scandals hits movie shelves soon". Vintage Press Limited. Archived from the original on 26 July 2011. Retrieved 28 September 2011. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Uche Jombo Storms Cinemas With Damage". AllAfrica.com. 28 July 2011. http://allafrica.com/stories/201108010242.html. Retrieved 28 September 2011.
- ↑ "Watch the Trailer for "Wives On Strike" starring Uche Jombo, Omoni Oboli, Ufuoma McDermott & More". BellaNaija. Retrieved 2016-05-12.
- ↑ "Banana Island Ghost Full Cast". Uzomedia. Retrieved 2017-05-20.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Uche Jombo’s heaven on my mind is still trending". Guardian NG. Archived from the original on 2019-04-17. Retrieved 2019-04-21.
- ↑ "Uche Jombo wins Best Actress at NAFCA - Vanguard News". 21 September 2012.
- ↑ "Desmond Elliot, Uche Jombo win big at AFRIFF - The Nation Nigeria". 18 November 2013.
- ↑ "Seyi Shay, Toke Makinwa, Mo’Cheddah, DJ Cuppy, Others Nominated". Pulse Nigeria. Chinedu Adiele. Archived from the original on 3 July 2017. Retrieved 20 October 2014.