Ifeanyi Kalu jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, model, àti aránṣọ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó di ìlú-mòọ́ká látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Lagod Cougars. [1] Òun àti Uche Jombo ,Monalisa Chinda àti Alex Ekubo ni wọ́n jọ kópa nínú eré náà.[2] Ó tún kópa nínú eré onípele àtìgbà-dégbà kan tí wọ́n pe àkòrí rẹ̀ ní Allison Stands, òun pẹ̀lú àwọn òṣèré bíi: Victor Olaotun, Bímbọ́ Manuel, àti Joselyn Dumas. Wọ́n ma ń fi eré yí hàn ní orí ìkànì Africa Independent Television (AIT). [3][4]

Ifeanyi Kalu
Ọjọ́ìbíIfeanyi Kalu
13 Oṣù Kejì 1988 (1988-02-13) (ọmọ ọdún 36)
Surulere, Lagos, Nigeria
Iṣẹ́Actor, Model, fashion designer
Ìgbà iṣẹ́2010 – present
Websiteifeanyikalu.com

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Kalu ní ìlú SúrùlérèÌpínlẹ̀ Èkó, àmọ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Imo lọ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó kẹ́kọ́ nípa ìmọ̀ Kọ̀mpútà nílé ẹ̀kọ́ Yunifásitì.[1] .[5]

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Kalu bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ ngẹ́gẹ́ bí Model, tí ó sì fara han nínú àwọn ìpolongo ọjà oríṣiríṣi.[6] Ní ọdún 2011, ó dara pọ̀ mọ́ ilé-ẹ̀kọ́ Royal Arts Academy láti kọ́ nípa eré oníṣẹ́. [5] Ipa tí ó kó nínú eréKokommal gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá ìtàn Usen ní ọdún 2012 tí Udauak Isong Ogunamanam gbé jáde tí Tom Robson. Wọ́n ti yàn án fún amì-ẹ̀yẹ ẹ̀mẹta nínú ayẹyẹ amì-ẹ̀yẹ 9th Africa Movie Academy Awards.[7]

Ní ọdún 2014, ipa tí ó kó nínú eré Lagos Cougars ati Perfect Union tí ó sì ti mu kí ó gba amì-ẹ̀yẹ Òṣèré tó ní ọjọ́ ọ̀la. [8]Wọ́n tún yàn án fún amì-ẹ̀yẹ yí kan náà ní ọdún 2017. [9] Ní ọdún 2019, wọ́n yàn án fún amì-ẹ̀yẹ ti City People Awards fún Best Supporting Actor,[10]Ní ọdún yí kan náà, wọ́n yàn án fún amì-ẹ̀yẹ ti Zulu African Film Academy Awards (ZAFAA) fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Best Supporting Actor ní ìlú UK nínú eré Kuvana níbi tí ó ti kópa pẹ́lú àwọn òṣèré bíi: Wálé Òjó, Sambasa Nzeribe àti Ivie Okujqiye.[11][12]

Ní ọdún 2019, Kalu fi ilé-iṣẹ́ aránṣọ tí ó pè ní Ready to Wear.[12]


Àwọn ipa rẹ̀ tí ó ti kó

àtúnṣe
Ọdún Ipa tí ó kó Àwọn olùdarí eré Notes
2012 Kokomma Usen Tom Robson Feature Film featuring Belinda Effah, Ekere Nkanga, Ini Ekpe
2013 Lagos Cougars Jite Desmond Elliot Feature Film starring Uche Jombo, Monalisa Chinda, Alexx Ekubo, Shawn Faqua, Daniella Okeke, Ben Touitou
2014 Perfect Union Eke Agbai Uzodinma Okpechi Feature Film starring Wole Ojo, Brycee Bassey, Joju Muse
2015 The Banker Kunle Ikechukwu Onyeka Feature Film featuring Seun Akindele, Mbong Amata, Belinda Effah, Maureen Okpoko, Nsikan Isaac
2016 Double Bind Nosa Emmanuel Akaemeh Feature Film starring Kiki Omeili, Ujams Cbriel, Mary Chukwu
2016 The Novelist Joseph Patience Oghre Imobhio Feature Film featuring Rykardo Agbor, Bayray Mcnwizu, Kehinde Olorunyomi, Labelle Vitien, Frank Paladini
2017 You, Me, and the Guys Koje Williams Esther Abah Feature Film featuring Lota Chukwu, Linda Ejiofor, Seun Akindele, Abayomi Alvin, Jude Orhorha
2017 3 is a Crowd Bayo Desmond Elliot Feature Film starring Tana Adelana, Desmond Elliot, Lilian Esoro, Alexx Ekubo, Eddie Watson, Cgris Akwarandu, Hauwa Allahbura
2018 Drowning Kay Charles Brain Nnoshiri Feature Film starring Mary Lazarus, Nazo Ekezie, Jide Kosoko, Jibola Dabo
2018 Almost a Virgin Ricardo Phillips Akin – Tijani Balogun Feature Film starring Bimbo Ademoye, Emem Ufot, Chioma Okafor, Nonso Kalango, Gifty Powers
2018 Will You Marry Me Uzor Emmanuel Mang Eme Feature Film featuring Ruth Kadiri, Wole Ojo, Stella Udeze, Peggy Ovire
2019 Lurikos Michael Edward Uka Feature Film featuring Bolanle Ninalowo, Tamara Eteimo, Christian Paul
2019 Tea Room Billy Okey Ifeanyi Feature Film starring Kenneth Okolie, Lota Chukwu, Calista Nwajide
2019 Kuvana Mendas Edward Uka Feature Film featuring Wale Ojo, Sambasa Nzeribe, Ivie Okujaye, Stella Udeze
2019 Red Obsession Temisan Esosa Egbon Feature Film starring Yvonne Jegede, Moyo Lawal, Georgina Ibeh, Wole Ojo

Ìpa rẹ̀ ní orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán

àtúnṣe
Ọdún Àkọ́lé Ipa tí ó kó Olùdarí eré Notes
2014 Allison’s Stand Allison (Lead) Peace Osigbe, Yemi Morafa(film boy) TV Series
2016 Desperate Housegirls Shawn (Lead) Sunkanmi Adebayo, Akin – Tijani Balogun TV Series on IrokoTV featuring Ini Edo, Belinda Effah, Deyemi Okanlawo, Bimbo Ademoye, Uzor Osimkpa, Uzor Arukwe
2017 Cougars Dubem Ikechukwu Onyeka, Akin – Tijani Balogun TV Series with Nse Ikpe Etim, Joselyn Dumas, Empress Njamah, Ozzy Agu, Monalisa Chinda
2017 Head over Heels Lead Ejiro Onobrakpor TV Series

Àwọn amì-ẹ̀yẹ rẹ̀

àtúnṣe
Ọdún Ayẹyẹ Amì-ẹ̀yẹ Èsì
2013 Nollywood Movie Awards Best rising star Wọ́n pèé
2014 City People Awards Most promising actor Wọ́n pèé
2015 Zaris Fashion and Style Academy Hall of Fame Gbàá
2017 Royal Arts Academy Award of Excellence Gbàá
City People Awards Most promising actor Wọ́n pèé
2018 HYPP Festival of Talents Recognition Award Gbàá
2019 City People Awards Best supporting actor Wọ́n pèé
ZAFAA Awards Best supporting actor Gbàá[12]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 "Ifeanyi Kalu has a Crush on Genevieve Nnaji". Thisday Newspaper (Lagos, Nigeria). 30 June 2018. https://www.pressreader.com/nigeria/thisday/20180630/281573766438001. Retrieved 6 December 2019. 
  2. "Omoni Oboli, Alex Ekubo, Julius Agwu, Desmond Eliot others attend Premiere of Lagos Cougars". TheNetNG Newspaper (Lagos, Nigeria). 23 November 2013. http://thenet.ng/photos-omoni-oboli-alex-ekubo-julius-agwu-desmond-elliot-uche-jombo-others-attend-premiere-of-lagos-cougars/. Retrieved 6 December 2019. 
  3. "Watch Joselyn Dumas, Victor Olaotan, others in season 2". PulseNG (Lagos, Nigeria). 3 December 2014. https://www.pulse.ng/entertainment/movies/allisons-stand-watch-joselyn-dumas-victor-olaotan-others-in-season-2/92vvl5p. Retrieved 8 December 2019. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  4. "Season Two of 'Allison's Stand' for Premiere On Sunday". Daily Independent via Allafricanews (Lagos, Nigeria). 4 December 2014. https://allafrica.com/stories/201412050058.html. Retrieved 8 December 2019. 
  5. 5.0 5.1 "Lessons Laernt from Acting". Punch Newspaper (Lagos, Nigeria). 24 February 2019. https://punchng.com/ive-learnt-the-difference-between-acting-school-and-being-on-set-ifeanyi-kalu/. Retrieved 6 December 2019. 
  6. "Ifeanyi Kalu". Thisday Newspaper (Lagos, Nigeria). 30 June 2018. https://www.thisdaylive.com/index.php/2018/06/30/ifeanyi-kalu-i-have-a-crush-on-genevieve-nnaji/. Retrieved 8 December 2019. 
  7. https://www.indiewire.com/2013/04/nigerian-dramedy-confusion-na-wa-tops-winners-at-the-9th-africa-movie-academy-awards-136164/
  8. "Meet the Nominees for City People Awards". Pulse NG (Lagos, Nigeria). 6 September 2014. Archived from the original on 25 June 2022. https://web.archive.org/web/20220625202314/https://www.pulse.ng/gist/meet-the-nominees-nominees-for-city-people-entertainment-awards/0vxvsgw. Retrieved 6 December 2019. 
  9. "City People Releases Nomination List For 2017 Movie Awards". City People Magazine (Lagos, Nigeria). 8 September 2017. http://www.citypeopleonline.com/city-people-releases-nomination-list-2017-movie-awards/. Retrieved 6 December 2019. 
  10. "Nominations for City People Awards (English)". city people magazine (Lagos, Nigeria). 24 October 2019. http://www.citypeopleonline.com/nomination-list-for-2019-city-people-movie-awards-english/. Retrieved 6 December 2019. 
  11. "Zafaa 2019 Nominees". zafaa.org. Lagos, Nigeria. 6 November 2019. Archived from the original on 6 December 2019. Retrieved 6 December 2019. 
  12. 12.0 12.1 12.2 "Ifeanyi Kalu’s Strides Across Facets". Thisday News. Lagos, Nigeria. 21 December 2019. Retrieved 23 December 2019.