Lucifer (fíìmù Nàìjíríà 2019)
Lucifer jẹ́ fíìmù Nàìjíríà ti ọdún 2019 tó dá lórí arákùnrin kan tí gbogbo ènìyàn bẹ̀rù ní agbègbè rẹ̀. Tope Adebayo àti Ibrahim Yekini ni olùdarí eré yìí. Orúkọ ìnagije Ibrahim Yekini ni Itele, òun sì ló gbé erẹ́ náa jáde.
Àwọn akópa
àtúnṣe- Ibrahim Yekini[1]
- Temitope Solaja
- Adisa Yusuf
- Taofeek Muyiba Adekemi
- Femi Adebayo
- Bimpe Oyebade
- Bimbo Akintola
- Oshiko Twins
- Bukunmi Oluwashina
- Kelvin Ikeduba
- Tunde Usman
- Antar Laniyan
- Oluwakemi Adejoro Ojo
Àmì-ẹ̀yẹ
àtúnṣeIbrahim Yekini gba àmì-èyẹ òṣèrékùnrin Yorùbá tó dára jù lọ ní BON AWARD ti ọdún 2020 fún fíìmù (Lucifer) yìí.[2][3][4]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Augoye, Jayne (2020-12-07). "BON Awards: Laura Fidel, Kunle Remi win Best Kiss (Full List of Winners)". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-01.
- ↑ "Ibrahim Yekini beats Lateef Adedimeji, others to best actor award - P.M. News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-01.
- ↑ Augoye, Jayne (2020-12-02). "2020 BON: Here are 5 nominees for 'Best Kiss' category". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-01.
- ↑ "BON Awards: 'Living In Bondage', 'This Lady Called Life' Win Big". Independent Newspaper Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-12-06. Retrieved 2022-08-01.