Mawlid, Mawlid an-Nabi ash-Sharif tàbí Eid Milad un Nabi ( المولد النبوي ní èdè Arabic) jé ayẹyẹ ọjọ́ ìbí anọ́bì Muhammad, [2], wọ́n sì ma ń sábà ṣe ayẹyẹ yí ní inú Oṣù Rabi' al-awwal, tí ó jẹ́ oṣù kẹta ti ònkà oṣù ojú ọ̀run àwọ Mùsùlùmí.[3] Rabi' al-awwal kéjìlá[4] ni ọjọ́ tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọ̀jọ̀gbọ́ Sunni fi ọwọ́ sí, Rabi' al-awwal ketadinlogbon si ni ijo ti òpòlopò òjògbón Shia fi owó sí, bi o tilè jé wípé kì I se gbogbo òjògbón Shia ni o fowo si ijo yi. Awon kan tún Ma un pe ayeye yi ni Maouloud ni ìwo oòrùn Africa.[5][6]

Mawlid
Mawlid
àwon Muslumi Sunni Malaysian ní ìwóde Mawlid kan ni Putrajaya, 2013.
Also calledMawlid an-Nabawī (المولد النبوي), Eid-e-Milad un-Nabi, Havliye, Donba, Maouloud, Gani[1]
Observed byAdherents of mainstream Sunni Islam, Shia Islam, Ibadi Islam and various other Islamic denominations. As a public holiday in Afghanistan, Algeria, Bahrain, Benin, Bangladesh, Brunei, Burkina Faso, Chad, Ethiopia, Egypt, Fiji, Gambia, Indian Subcontinent, Indonesia, Iran, Iraq, Jordan, Kuwait, Lebanon, Libya, Malaysia, Maldives, Mali, Mauritania, Morocco, Niger, Nigeria, Oman, Senegal, Somalia, Sudan, Tunisia, and Yemen
TypeIslamic
SignificanceTraditional commemoration of the birth of Muhammad
ObservancesHamd, Tasbih, public processions, Na`at (religious poetry), family and other social gatherings, decoration of streets and homes

Ìtàn nípa ayẹyẹ na ti wà láti ayé àtijó nígbà tí orin àti ewì tí àwọn Tabi‘un ko láti yín Muhammadu di ohun tí wọ́n ń kó sì àwọn ènìyàn .[7] O wà nínú ìtàn pé olùdarí Mùsùlùmí àkókò tí ó kókó se ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Muhammadu ni Muzaffar al-Din Gökböri (d. 630/1233).[8] Àwọn Ottomans kéde rẹ̀ ni ọjọ́ ìsinmi ni odun 1588. [9] tí a mọ̀ sí Mevlid Kandil.[10]

Mawlid jẹ́ ọ̀rọ̀ tí wọ́n ún lọ ní àwọn ibi kan ni àgbáyé, bí àpẹẹrẹ, Orílẹ̀ èdè Egypti gẹ́gẹ́ bí orúkọ fún òjọ́ ìbí àwọn ènìyàn pàtàkì nínú ìtàn bi Sufi saints.[11]

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹgbẹ́ Mùsùlùmí ni wón fi owó sì ṣíṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Muhammadu.[12][13] ṣùgbọ́n, láti ìgbà tí Wahhabism-Salafism, Deobandism, Ahl-i Hadith àti Ahmadiyya to dẹ́,[14] ọ̀pọ̀lọpọ̀ Mùsùlùmí bẹ̀rẹ̀ si ún lòdì sí ṣíṣe ayẹyẹ náà, wón ní kí ún se ayẹyẹ tó tọ́(bid'ah or bidat).[15][16] Wọ́n kaMawlid sí òjọ́ ìsinmi ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ Orílẹ̀ èdè tí Mùsùlùmí ti pò ju ẹ̀sìn mìíràn lo, yàtò sí orílè-èdè bi Saudi Arabia àti Qatar. Àwọn orílè-èdè míràn tí kì ún se mùsùlùmí ni ó poju níbè ṣùgbọ́n tí Mùsùlùmí pò níbè, orílè-èdè bí India, Tanzania àti Ethiopia, àti beebe lọ, tún ka ọjọ́ ìṣe ayẹyẹ Mawlid gẹ́gẹ́ bi ọjọ́ ìsinmi.[17]

Orísun ọ̀rọ̀ náà

àtúnṣe

Wọ́n yo "Mawlid" láti oro Arab "ولد", tí ó túmọ̀ sí "bíbí ọmọ tàbí ìran".[18] Lowolowo, wọ́n ń lọ Mawlid láti se àpèjúwe ibí Muhammad.[3] Yàtò sí pé wọ́n ún lọ fún ibí Muhammadu, a tún fi ún se àpèjúwe "àwọn ọ̀rọ̀ tí a ko ti a si ún kà tàbí fi korin ní ibi isayeye ọjọ́ ìbí Muhammad"[19]

Ọjọ́ ibí náà

àtúnṣe

Gégé bí ọ̀pọ̀lọpọ̀ Mùsùlùmí Sunni ati àwọn Mùsùlùmí Shi'a ṣe sọ, a bí Muhammadu ni ìjọ́ Kejìlá Rabi' al-awwal.[20][21][22][23] Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Mùsùlùmí Twelver Shia miran si so wípé ọjọ́ ketadinkogun ti Rabi' al-awwal ni a bi.[20][21] O je ọ̀rọ̀ àríyànjiyàn ikhtilaf nítorí àwọn ojogbon Shiite scholars bi Muhammad ibn Ya'qub al-Kulayni, Ibn Babawayh, àti Zayn al-Din al-Juba'i al'Amili to jiyàn pẹ́ ọjọ́ ìbí rè ni ọjọ́ Kejìlá Rabi' al-Awal.[24][25] Àwọn miran tilè sọ́ wípé ọjọ́ ìbí rè kò jẹ́ mímọ̀, wọn kò sì kó sínú ìwé ìtàn Mùsùlùmí.[26][27][28][29] Oro nípa àríyànjiyàn ọjọ́ Mawlid ni Ibn Khallikan ko pé ó jẹ́ àríyànjiyàn àkókó nípa ayẹyẹ náà.

Gégé bí àbá tí Nico Kaptein ti Leiden University fi léde, àwon Fatimids ni o bèrè Mawlid.[30] Àbá pé ìse ayeye mawlid bèrè ní ìdíle Fatimid ti jé àbá ti àwon òjògbón nínú imo Islam àti ìmò awujo ti gbà kakiri agbáyé.[31] Annemarie Schimmel tun so pe sísé ayeye ìbi Woli Mohammadu bèrè láti Egypti nígbà àwon Fatimids.

Òpìtàn Egypti, Maqrizi (d. 1442) so ro nípa okan ninú awon ayeye náà ti wón se ni odun 1122, o ni òpòlopò òjògbón kopa nínú ayeye náà. Won gbó iwasu, wón pín àwon òhun adun, papa julo oyin, òpòlopò àwon talaka ni wón si fun ni nkan.[32] Sugbon gégé bi Encyclopædia Britannica se fi lede, Muẓaffar al-Dīn Gökburi ti Sunnis ni o bèrè ayeye Mawlid ni odun 1207. [33][34][35]

Àwon kan tun so pé Abu al-Abbas al-Azafi ti ìlú Ceuta ni o bere ayeye Mawlid gégé bi ònà láti so àwon musulumi po ati láti sé bi àwon ayeye Ktisteni.Àdàkọ:Sfnp[36]

Èrò àwọn ojogbon Mùsùlùmí nípa ayẹyẹ náà

àtúnṣe

Ibn al-Hajj so sere nípa ṣíṣe ayẹyẹ náà gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà idúpẹ́, ṣùgbọ́n ó lòdì sí àwọn nkan eewọ tí òun ṣẹlẹ̀ níbè.Àdàkọ:Sfnp. O lòdì sí àwọn nǹkan, bí kí àwọn olorin má kọrin pẹ̀lú ìlù.Àdàkọ:Sfnp Ó bere pé kini isopo tí ó lẹ́wà láàrin ibi Mohammudu.Àdàkọ:Sfnp Ṣùgbọ́n ó sọ rere nípa bibowo fún ọjọ́ ìbí náà.Àdàkọ:Sfnp. Alhaji náà sọ pé "a gbọ́dọ̀ fi ṣíṣe réré àti fífi fún àwọn aláìní kún ibowo fún oṣù náà". Bí ẹnikẹ́ni kò bá ní le se bẹ́ẹ̀, kí ó yàgò fún ṣíṣe ohun tí kò da nínú ibowo fún oṣù náà.Àdàkọ:Sfnp Ó so wipe ohun kò lodi sì Mawlid sugbọn àwọn nkan eewọ ni wọn má ún se nígbà Mawlid.”Àdàkọ:Sfnp Oun kò sì lòdì sí dí dáná àti pípe àwọn ènìyàn wá jẹun.Àdàkọ:Sfnp

Ni Àfikún, ó ní àwọn míràn kò ṣe ayẹyẹ Mawlid nítorí ibowo ṣùgbọ́n wón fe gbà àwọn Fàdákà tí wón ti fún àwọn ènìyàn ní ayẹyẹ mìíràn,o si ní àwọn nkan ti o léwu wà ní irú ìwà yi.Àdàkọ:Sfnp

Skaykh al-Islam, abu I-Fadl ibn Hajar, "ẹni tí ó jé hafiz tí ó ga jù lọ”Àdàkọ:Sfnp so wipe sise ayẹyẹ Mawlid lè jẹ nkan rere àti nkan búburú, pé bí ènìyàn bá ṣe nkan rere nígbà tí ènìyàn ńṣe tí ó sì yàgò fún búburú, ìyẹn mú kí ayẹyẹ Mawlid jẹ́ rere, bí ó bá ṣe bẹ, ìyẹn mú kí ayẹyẹ Mawlid jẹ́ búburú.Àdàkọ:Sfnp O ni wíwà Woli náà je rere, àti pé ọjọ́ náà nìkan ni ó yẹ kí wón ma fowo fún(kí ṣe gbogbo oṣù náà.Àdàkọ:Sfnp O ní "o ye kí ènìyàn ṣe ohùn tí ó ma bọ̀wọ̀ fún Ọlọ́run, àwọn bí kika Qurani, fí fi oúnjẹ fún ni, fí fi ohùn ìní fún ni àti kiko orin ọpẹ́ tí óhun ran ènìyàn lọ́wọ́ láti se ohun rere.”Àdàkọ:Sfnp Ó ní àwọn “Sama àti erẹ́ le wà lára àwọn nkan ti o bá àwọn ìlànà ayẹyẹ náà ṣùgbọ́n nkan tí kò da kò da.Àdàkọ:Sfnp

Àwọn Ọ̀rọ̀ Mawlid

àtúnṣe

Pẹ̀lú àwọn àtọ́ka sí bi àwọn ayẹyẹ ti ọjọ́ ìbí ti Muhammad, ọ̀rọ̀ Mawlid tún ń tọ́kasí àwọn 'ọ̀rọ̀ pàápàá tí ó jẹ́ kíkọ nípasẹ̀ àtinúdá fún un àti sísọ ní ibi àjoyọ̀ Muhammad' tàbí "ọ̀rọ̀ tí a kà tàbí tí a kọ lórí ọjọ́ náà".[19] Irú àwọn ewì bẹ́ẹ̀ ni ó ti wà ní kíkọ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn èdè, pẹ̀lú Arabic, Kurdish àti Turkish.[37] Àwọn ọ̀rọ̀ wọ̀nyí ni àwọn ìtàn ti ìgbésí ayé Muhammad nínú, tàbí ó kéré jù díẹ̀ nínú àwọn ìpín wọ̀nyí láti ìgbésí ayé rẹ̀, ní ṣókí ní ìsàlẹ̀:[19]

  1. Àwọn bàbá ti Muhammad
  2. Àwọn Èròngbà ti Muhammad
  3. Ibi ti Muhammad
  4. Ìfihàn ti Halima
  5. Ìgbésí ayé ti ọ̀dọ Muhammad ní Bedouins
  6. Muhammad's orphanhood
  7. Abu Talib's nephew's first caravan trip
  8. Ètò ti Ìgbéyàwó láàrín Muhammad àti Khadija
  9. Al-Isra'
  10. Al-Mi'radj, tàbí ìgòkè lọ sí ọ̀run
  11. Al-Hira, ìfihàn àkọ́kọ́
  12. Àwọn àkọ́kọ́ ìyípadà sí Islam
  13. The Hijra
  14. Ikú Muhammad

Àwọn ìlò mìíràn ọ̀rọ̀ náà

àtúnṣe

Ní àwọn orílè-èdè bi Egypt àti Sudan, Mawlid jẹ́ ọ̀rọ̀ tí wón fi ún àpèjúwe ọjọ́ ìbí àwọn ènìyàn mímọ Sufi, kìí se fún àpèjúwe ọjọ́ ìbí Muhammadu nìkan.[38] Àwọn bí ayẹyẹ Mawlid 3,000 ni wọ́n ma ún ṣe ni ọdọọdún. Àwọn ènìyàn káàkiri àgbáyé ni wón ma ún se àwọn àjọ̀dún náà. Bí àpẹẹrẹ, àwọn ènìyàn tó tọ́ mílíọ̀nù mẹta ni wón ma ún kópa ní Ahmad al-Badawi, ènìyàn mimọ sufi ní 1200s[11]

Ibi Àwòrán

àtúnṣe

Àwon Ìtókasí

àtúnṣe
  1. "Mawlid in Africa". Muhammad (pbuh) – Prophet of Islam. Archived from the original on 14 March 2016. Retrieved 2 February 2016. 
  2. "Eid-e-Milad 2020 Festival Date,Is Celebrating Eid ul-Milad Allowed in Islam!". S A NEWS (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-10-27. Retrieved 2020-10-28. 
  3. 3.0 3.1 Mawlid. Reference.com
  4. The Sealed Nectar. https://www.amazon.com/Sealed-Nectar-Biography-Prophet-Muhammad-ebook/dp/B00DOKDP46/ref=sr_1_3?ie=UTF8&qid=1511971555&sr=8-3&keywords=sealed+nectar. 
  5. "Benin Public Holidays 2021". PublicHolidays.africa. Archived from the original on 10 October 2022. Retrieved January 3, 2021. 
  6. "Maouloud in Senegal". timeanddate.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved January 3, 2021. 
  7. "Mawlid an-Nabi: Celebrating Prophet Muhammad's (s) Birthday". The Islamic Supreme Council of America (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 5 November 2018. 
  8. İbrahim Kafesoğlu (1994). A Short History of Turkish-Islamic States (excluding the Ottoman State). Turkish Historical Society Printing House. p. 184. ISBN 9789751605719. https://books.google.com/books?id=B5VtAAAAMAAJ. 
  9. Shoup, John A. (1 January 2007) (in en). Culture and Customs of Jordan. Greenwood Publishing Group. p. 35. ISBN 9780313336713. https://books.google.com/books?id=dm7Ups_zsbcC. 
  10. Manuel Franzmann, Christel Gärtner, Nicole Köck Religiosität in der säkularisierten Welt: Theoretische und empirische Beiträge zur Säkularisierungsdebatte in der Religionssoziologie Springer-Verlag 2009 ISBN 978-3-531-90213-5 page 351
  11. 11.0 11.1 "In pictures: Egypt's biggest moulid". BBC News. http://news.bbc.co.uk/1/shared/spl/hi/picture_gallery/07/middle_east_egypt0s_biggest_moulid/html/2.stm. 
  12. Schussman, Aviva (1998). "The Legitimacy and Nature of Mawid al-Nabī: (analysis of a Fatwā)". Islamic Law and Society 5 (2): 214–234. doi:10.1163/1568519982599535. 
  13. McDowell, Michael; Brown, Nathan Robert (3 March 2009) (in en). World Religions at Your Fingertips. Penguin. p. 106. ISBN 9781101014691. https://books.google.com/books?id=urcyCnUurGMC. 
  14. Observing Islam in Spain: Contemporary Politics and Social Dynamics BRILL, 09.05.2018 ISBN 9789004364998 p. 101
  15. http://islamqa.info/en/249 Muhammed Salih Al-Munajjid.
  16. A Guide to Shariah Law and Islamist Ideology in Western Europe 2007–2009 Archived 13 February 2023 at the Wayback Machine., Centre for Islamic Pluralism (2009), p.84
  17. "Milad un-Nabi/Id-e-Milad in India". www.timeanddate.com. 
  18. قاموس المنجد – Moungued Dictionary (paper), or online: Webster's Arabic English Dictionary Archived 12 February 2009 at the Wayback Machine.
  19. 19.0 19.1 19.2 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Knappert
  20. 20.0 20.1 Mahjubah, 16, 1997, p. 8 
  21. 21.0 21.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named princeton
  22. Tahir ul Qadri (2014), Mawlid Al-nabi: Celebration and Permissibility, Minhaj-ul-Quran Publications, p. 25, ISBN 9781908229144 
  23. John L. Esposito (1995), The Oxford Encyclopedia of the Modern Islamic World, Oxford University Press, p. 121, ISBN 978-0-19-506613-5 
  24. Mohsen Kadivar, روز میلاد پیامبر بازگشت به رای متقدم تشیع, archived from the original on 21 December 2019, retrieved 10 October 2022 
  25. Rasool Jafariyan, ولادت رسول خدا (ص) در دوازدهم یا هفدهم ربیع الاول؟ 
  26. Sanjuán, Alejandro García, ed (2007). Till God Inherits the Earth: Islamic Pious Endowments in Al-Andalus (9–15th Centuries) (illustrated ed.). BRILL. p. 235. ISBN 9789004153585. https://archive.org/details/tillgodinheritse00sanj_163. 
  27. Annemarie Schimmel (1994). Deciphering the signs of God: a phenomenological approach to Islam (illustrated ed.). Edinburgh University Press. p. 69. 
  28. Eliade, Mircea, ed (1987). The Encyclopedia of religion, Volume 9 (illustrated ed.). Macmillan. p. 292. ISBN 9780029098004. 
  29. Fitzpatrick, Coeli; Walker, Adam Hani, eds (2014). Muhammad in History, Thought, and Culture: An Encyclopedia of the Prophet of God [2 volumes] (illustrated ed.). ABC-CLIO. p. 368. ISBN 9781610691789. 
  30. Àdàkọ:Harvp
  31. Àdàkọ:Harvp
  32. Schimmel, Annemarie (1985). And Muhammad is His Messenger: The Veneration of the Prophet in Islamic Piety. London: The University of North Carolina Press. pp. 145. ISBN 978-0-8078-4128-0. 
  33. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named britannica
  34. Àdàkọ:Harvp
  35. Àdàkọ:Harvp
  36. "mawlid | Meaning, Importance, Celebration, & Facts" (in en). Encyclopedia Britannica. https://www.britannica.com/topic/mawlid. Retrieved 2020-10-28. 
  37. Kenan Aksu Turkey: A Regional Power in the Making Cambridge Scholars Publishing, 18.07.2014 ISBN 9781443864534 p. 231
  38. Àdàkọ:Harvp