Nọ́mbà tíkòsí
Ninu imo Mathematiki, nọ́mbà tíkòsí (imaginary number) ni a mo si nomba tosoro ti alagbarameji (square) re je nomba gidi alapaosi. Rafael Bombelli ni o se itumo won ni odun 1572. Laye igbana ko seni to gba pe awon nomba ba hun wa, gege bi won se ro pe odo ati nomba apaosi ko si tabi ko wulo. Descartes ni o koko pe won be ninu iwe re isiro alawonile (La Geometrie]] lati fi re won sile
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |