Nancy Isime
Nancy Isime (tí wọ́n bí ní ọjọ́ 17 oṣù December, ọdún 1991) jẹ́ òṣèrébìnrin àti oníṣẹ́ orí ẹ̀rọ-ayélujára tí orílẹ̀-èdè Naijiria[1] .
Nancy Isime | |
---|---|
Nancy Isime at the AMVCAs 2020 | |
Ọjọ́ìbí | 17 Oṣù Kejìlá 1991 Edo State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Lagos |
Iṣẹ́ | |
Ìgbà iṣẹ́ | 2011- till date |
Early life and background
àtúnṣeÌpínlẹ̀ Ẹdó, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́ bí Nancy Isime sí, sínú ẹbí tó wá láti ìran Esan.[2] Lẹ́yìn tó parí ẹ̀kọ́ girama ní Benin City, ó lọ sí University of Lagos, láti lọ gboyè ẹ̀kọ́ si[3].
Nancy Isime pàdánú ìyá rẹ̀ ní ìgbà tó wà ní ọmọ ọdún márùn-ún, bàbá rẹ̀ ló sì tọ́ ọ dàgbà.[4] Ó dàgbà sí Ìpínlẹ̀ Èkó, níbi tó ti ka ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti ẹ̀kọ́ girama. Kò parí ẹ̀kọ́ girama rẹ̀ ní Èkó, Benin City ni ó ti parí ẹ̀kọ́ girama rè. Ó kẹ́kọ̀ọ́ olóṣù mẹ́fà ní University of Port Harcourt, kí ó tó wá lọ sí University of Lagos, láti gba oyè diploma nínú ẹ̀kọ́ Social Works[5].
Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀
àtúnṣe- Hex (2015)
- Tales of Eve (2015)
- On the Real (2016)
- A Trip to Jamaica (2016)
- Hire a Man (2017)
- Finding C.H.R.I.S (2017)
- The Surrogate (2017)
- Treachery (2017)
- Kanyamata
- Tempted
- Guilty
- Kylie's Quest
- A Better Family (2018)
- Club (2018)
- Johnny Just Come (2018)
- Liars and Pretenders (2018)
- My Name is Ivy (2018)
- Sideways (2018)
- Disguise (2018)
- Merry Men: The Real Yoruba Demons (2018)
- Don't get mad get even (2019)
- Hire a Woman (2019)
- Adaife (2019)
- The Millions (2019)
- Beauty in the Broken (2019)
- Another Angle (2019)
- Merry Men 2 (2019)
- Levi (2019)
- Living in Bondage: Breaking Free (2019)
- Made in Heaven (2019 film) (2019)
- Kambili: The Whole 30 Yards (2020)
- Creepy Lives Here (2021)
- The Razz Guy (2021)
- The Silent Baron (2021)
- Superstar (Nollywood Movie) (2021)
- Blood Sisters (2022)
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣeỌdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Fíìmù | Èsì | Ìtọ́ka |
---|---|---|---|---|---|
2016 | City People Entertainment Awards | Best VJ of the Year | N/A | Gbàá | [6] |
Nigerian Broadcasters Merit Awards | Sexiest On Air Personality (female) | Hip TV | Gbàá | [7] | |
2017 | The Future Awards | Best On Air Personality (Visual) | N/A | Gbàá | [8][9] |
2018 | 2018 Best of Nollywood Awards | Best Actress in a Lead Role - English | Disguise | Wọ́n pèé | [10] |
City People Movie Awards | Most Promising Actress (English) | N/A | Gbàá | [11] | |
2019 | Best Supporting Actress (English) | N/A | Gbàá | [12] | |
Best of Nollywood Awards | Best Kiss in a Movie | Jofran | Gbàá | [13] | |
Best Actress in a Lead role –English | Wọ́n pèé | [14] | |||
2021 | Net Honours | Most Popular Media Personality (female) | N/A | Wọ́n pèé | [15] |
Most Searched Media Personality | N/A | Wọ́n pèé | |||
2022 | 2022 Africa Magic Viewers' Choice Awards|Africa Magic Viewers' Choice Awards | Best Actress in A Comedy | Kambili: The Whole 30 Yards | Wọ́n pèé | [16] |
Best Actress in A Drama | Superstar | Wọ́n pèé |
Iṣẹ́ tóyàn láàyò
àtúnṣeNancy Isime bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré láti inú fíìmù orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán kan tí àkọ́lé rè ń jẹ́ Echoes, ní ọdún 2011. Ó sì tún jẹ́ olóòtú ètò kan lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán, tí wọ́n pè ní The Squeeze, What's Hot, àti MTN Project Fame apá keje[17]. Ní ọdún 2016, ó rọ́pò Toke Makinwa láti ṣe olóòtú ètò kan tí wọ́n pè ní Trending lórí HipTV.[18][19] Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùgbàlejò ti ètò The Headies award pẹ̀lú Reminisce.[20] Òun náà ni olóòtú ètò The Voice Nigeria tó wáyé ní ọdún 2021.[21] Ní ọdún 2019, Isime ṣàgbéjáde ètò tirẹ̀, tó pè ní The Nancy Isime Show.[22] Ní ọdún 2020, ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùgbàlejò ti ètò The Headies award pẹ̀lú Bovi.[23] Ní ọdún 2022, ó kópa nínú fíìmù Netflix kan, tí àkọ́lé rè jẹ́ Blood Sisters, ẹ̀dá-ìtàn tó sì ṣe ni Kemi. Ilé-iṣẹ́ Mo Abudu tí wọ́n ń pè ní Ebonylife TV studio ló ṣàgbéjáde eré yìí. Ní ọdún 2023, ó kópa nínú eré Shanty Town, gẹ́gẹ́ bí i ẹ̀dá-ìtàn Shalewa[24].
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "TV Personality, Actress & also a Model? "On The Real" Star Nancy Isime is a Triple Threat". bellanaija.com. Retrieved 6 February 2017.
- ↑ "I have no problem baring my cleavage - Nancy Isime". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-03-05. Retrieved 2022-08-27.
- ↑ "To become superstars, ladies need talent, not 'connection'- Model - Vanguard News". vanguardngr.com. 4 August 2016. Retrieved 6 February 2017.
- ↑ Oyedele, Oluwamuyiwa (2021-02-24). "How I lost My Mum At 5 - Nancy Isime". Vanguard Allure (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-27.
- ↑ "I have no problem baring my cleavage - Nancy Isime". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 5 March 2017. Retrieved 25 April 2021.
- ↑ "Full List Of Winners at 2016 City People Entertainment Awards - Nigerian Entertainment Today - Nigeria's Top Website for News, Gossip, Comedy, Videos, Blogs, Events, Weddings, Nollywood, Celebs, Scoop and Games". thenet.ng. 26 July 2016. Archived from the original on 8 December 2016. Retrieved 6 February 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Popoola, Kazeeem. "Finally! Here Is Authentic List Of Nominees For NBMA 2015". Nigeria Voice.
- ↑ "2017 Future Awards Africa winners". Punch.
- ↑ "Wizkid, Davido, Joshua winners at Africa’s Future Awards". Vanguard. Retrieved 25 October 2020.
- ↑ "BON Awards 2018: Mercy Aigbe, Tana Adelana shine at 10th edition". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 December 2018. Retrieved 23 December 2021.
- ↑ "Nominees For 2018 City People Movie Awards". City People.
- ↑ "Winner Emerge @ 2019 City People Movie Awards". 14 October 2019. Retrieved 20 October 2020.
- ↑ "BON Awards 2019: 'Gold Statue', Gabriel Afolayan win big at 11th edition in Kano". Pulse.
- ↑ Bada, Gbenga (15 December 2019). "BON Awards 2019: 'Gold Statue', Gabriel Afolayan win big at 11th edition". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 10 October 2021. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Net Honours - The Class of 2021". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 7 December 2021.
- ↑ "2022 Africa Magic Awards Nominees don land- See who dey list". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-60818021.
- ↑ "I can't date a man who is broke". The Nation. http://thenationonlineng.net/cant-date-man-broke/. Retrieved 13 October 2016.
- ↑ "Nancy Isime, Where Have You Been Hiding?". TNS. 25 June 2016. Archived from the original on 13 October 2016. Retrieved 13 October 2016.
- ↑ "Hip Tv unveils Toke Makinwa's replacement for 'Trending'". Nigerian Entertainment Today. 31 July 2015. Retrieved 6 February 2017.
- ↑ "Headies 2019: Teni, Falz, Burna Boy win big at 13th edition". Pulse.ng. 19 October 2019. Archived from the original on 19 October 2019. https://web.archive.org/web/20191019214707/https://www.pulse.ng/entertainment/music/headies-2019-all-the-winners-at-the-13th-edition/cvevtzt.
- ↑ "Premiere: Nancy Isime, Toke Makinwa graced The Voice Nigeria Season 3 with glitz and glam". Vanguard. 30 March 2021. Retrieved 16 June 2022.
- ↑ "TV personality, Nancy Isime launches TV Show". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 26 October 2019. Retrieved 30 March 2022.
- ↑ Meet the Hosts for the #14thHeadies, Nancy Isime & Bovi
- ↑ BellaNaija.com (2022-12-28). "Meet the Cast of “Shanty Town,” the Nigerian Crime Thriller Coming to Netflix in January". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-06.