Owerri
(Àtúnjúwe láti Owerri, Ipinle Imo)
Owerri ( /oʊˈwɛri/ oh-WERR-ee,[1] Igbo: Owèrrè)[2] ni olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Imo ní Nàìjíríà, ìlú náà wà láàrin ilẹ̀ igbó.[3] Òun tún ni ìlú tí ó tóbi jù ní Ìpínlẹ̀ Imo, ìlú Orlu, Okigwe àti Ohaji/Egbema sì ni ó tẹ̀lẹ́. Owerri ní ìjọba ìbílè mẹta, àwọn ni Owerri Municipal, Owerri North àti Owerri West, ìlú Owerri ní àwọn olùgbé 1,401,873 ní ọdun 2016. Owerri pín àlà pẹ̀lú Otamiri River ní apá ìwọ̀ oòrùn rẹ̀ àti Nworie River ní apá gúúsù rẹ̀.[4]
Owerri | |
Map of Nigeria showing the location of Owerri in Nigeria. | |
Coordinates: 5°29′06″N 7°02′06″E / 5.485°N 7.035°E | |
---|---|
State | Imo State |
Government | |
- Mayor | Oshieze Vincent Ehirim |
Area | |
- City | 104 km² (40.2 sq mi) |
- Land | 130 km² (50.2 sq mi) |
- Water | 20 km² (7.7 sq mi) |
- Metro | 100 km² (38.6 sq mi) |
Population (2007) | |
- City | 231,789 |
- Density | 1,400/km² (3,626/sq mi) |
- Metro | 281,789 |
estimated | |
Time zone | CET (UTC+1) |
- Summer (DST) | CEST (UTC+1) |
Website: www.imostate.com |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Owerri". Encarta World English Dictionary. Microsoft. http://encarta.msn.com/dictionary_1861685045_1861636161/prevpage.html. Retrieved 2010-07-03. Archived 2009-12-01 at the Wayback Machine.
- ↑ Egbokhare, Francis O.; Oyetade, S. Oluwole (2002). Harmonization and standardization of Nigerian languages. CASAS. p. 106. ISBN 1-919799-70-2.
- ↑ "Encyclopædia Britannica". 2007-04-07.
- ↑ Alex D.W. Acholonu (2008). "Water quality studies of Nworie River in Owerri, Nigeria". Mississippi Academy of Sciences. Retrieved 2009-10-14.