Simidele Adeagbo
Simidele Adeife Omonla Adeagbo[1] (tí wọ́n bí ní July 29, 1981, sí ìlú Toronto, Ontario, Canada)[2] jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó máa ń kópa nínú ìdíje eré-sísá. Ó kópa nínú ìdíje ti 2018 Winter Olympics. Ó jẹ́ ọmọbìnrin Nàìjíríà àti Africa àkọ́kọ́ tó jẹ́ skeleton athlete. Òun sì ní ọmọbìnrin aláwọ̀ dúdú àkọ́kọ́ tó máa kópa nínú eré-ìdárayá Olympic. Ní ọdún 2022, ó jáwé olúborí nínú ìdíje EuroCup ti ọdún 2022, tó wáyé ní ìlú Germany. Látàrí èyí, ó di ọmọ Africa àkọ́kọ́ tó gba jáwé olúborí nínú ìdíje àgbáyé.[3] Kí ó tó kópa nínú ìdíje skeleton, Adeagbo kópa nínú ìdíje triple jump, ní ọdún 2008.
Òrọ̀ ẹni | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Simidele Adeife Omonla Adeagbo |
Ọmọorílẹ̀-èdè | |
Ọjọ́ìbí | 29 Oṣù Keje 1981 Toronto, Ontario, Canada |
Ibùgbé | Johannesburg, South Africa |
Height | 1.70 m (5 ft 7 in) |
Weight | 65 kg (143 lb) |
Sport | |
Orílẹ̀-èdè | |
Erẹ́ìdárayá |
|
Event(s) |
|
University team | University of Kentucky |
Coached by | Nick Vienneau |
Achievements and titles | |
Regional finals | 2022 Woman's Monobob World Series; UK Scholar Athlete of the Year, 2003 Indoor Southeastern Triple Jump Champion |
National finals | Olympic Trials Finalist 2004 & 2008 (Triple Jump), 4 Time NCAA all American in the Triple Jump and Academic All-American, |
Olympic finals | 20th (Pyeongchang 2018) |
Highest world ranking | 74 |
Personal best(s) | Track and Field (Triple Jump) 13.99m (June 27 th , 2008) |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Adeagbo sí ìlú Toronto, ní Ontario, Canada, sínú ìdílé àwọn ọmọ Nàìjíríà. Ó kó lọ sí ìlú Ìbàdàn, ní Nàìjíríà nígbà tí ó wà lọ́mọ́dé, ó sì gbé níbẹ̀ fún ọdún mẹ́fà kí ó tó lọ sí United States.[4]
Iṣẹ́ tó yàn láàyò
àtúnṣeAdeagbo ṣiṣẹ́ fúnNike body double fún Serena Williams.[5] Adeagbo sì jẹ́ alábòójútó ètò ọrọ̀-ajé ti South Africa, láti ọdún 2012.[6]
Ní August 18, 2018, Adeagbo sọ̀rọ̀ níbi ayẹyẹ TEDxLagos ní Muson Centre, pẹ̀lú àwọn ènìyàn ńlá mìíràn bí i [7] Supo Shasore, Ade Olufeko, Tokini Peterside àti Banky W.[8]
Àwọn ìdíje rẹ̀
àtúnṣeLórí pápá àti abẹ́lé
àtúnṣeEvent | Result | Venue | Date |
---|---|---|---|
Outdoor | |||
100 meters | 12.05 (wind: +1.7) | Baton Rouge, Louisiana | 13 May 2000 |
100 meters | 11.96 (wind: +3.1) | Coral Gables, Florida | 17 Mar 2001 |
Long jump | 6.20 m A (wind: +0.9 m/s) | Eugene, Oregon | 19 Jun 2004 |
Long jump | 6.36 m A (wind: +4.9 m/s) | Austin, Texas | 06 Apr 2001 |
Triple jump | 13.99 m A (wind: +2.0 m/s) | Eugene, OR | 27 Jun 2008 |
Indoor | |||
60 meters | 7.59 | Lexington | 13 Jan 2001 |
Long jump | 6.25 m | Nampa, Idaho | 28 Jan 2005 |
Triple jump | 13.40 m | Seattle | 28 Jan 2006 |
Skeleton
àtúnṣeÀwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Olympians: Olympians for Life – website of the WOA
- ↑ "Sleigh, Simidele Adeagbo, Sleigh". Nike. 9 January 2018.
- ↑ "Nigeria's Adeabgo becomes first African to win international sled race". ESPN.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-01-17. Retrieved 2022-02-05.
- ↑ "Nigerian bobsledder aims for Africa's first Winter Games medal". BBC Sport. 13 February 2023. Retrieved 14 February 2023.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedIBSF-bio
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedNike-2018-01-092
- ↑ "Olasupo Sasore, Bankole Wellington, Simi Adeagbo, others deliver inspiring talks at event co-sponsored by Union Bank". Pulse. Archived from the original on 17 September 2018. Retrieved 17 September 2018.
- ↑ Ukiwe, Urenna (16 August 2018). "TEDXLagos Exciting "Spotlight" Set To Hold". The Guardian (Nigeria). Archived from the original on 17 September 2018. Retrieved 17 September 2018.
- ↑ "SIMIDELE ADEAGBO". IAAF Athletes. International Association of Athletics Federations.
- ↑ "Simidele ADEAGBO". IBSF Athletes. International Bobsleigh and Skeleton Federation. Archived from the original on 2020-11-22. Retrieved 2024-04-16.