Susan Peter's (Òṣèrébìnrin ọmọ Nàìjíríà)

Susan Peters tí wọ́n bí lọ́gbọ̀n ọjọ́ oṣù karùn-ún ọdún 1989 (30 May 1980) jẹ́ gbajúmọ̀ Òṣèrébìnrin ọmọ Nàìjíríà tí ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmìn-ẹ̀yẹ tí ó ju àádọ́ta lọ.[1] Ó jẹ́ gbajúmọ̀ atọ́kùn orí tẹlifíṣàn, afoge-ṣojú, atúnnúleṣe àti aṣerunlóge.[2] Láìpẹ́ yìí, ó gbàmìn ẹ̀yẹ Òṣèrébìnrin tó dára jù lọ nínú sinimá àgbéléwò lédè òyìnbó, 2011 Afro Hollywood Best Actress (English) Award fún ipa tó kó nínú sinimá tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ Bursting Out, àmìn-ẹ̀yẹ [3] NAFCA Archived 2014-06-16 at the Wayback Machine. fún Òṣèré (Nollywood ati African Film Critics Awards) North Carolina Nigerian Oscars: Best Actress in Supporting Role 2011[4] àmìn ẹ̀yẹ BON Archived 2012-01-20 at the Wayback Machine. (amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ Òṣèrébìnrin tó dára jù lọ lọ́dún 2011,[5] bẹ́ẹ̀ ló tún gbàmìn ẹ̀yẹ Òṣèrébìnrin tó dára jù lọ fún ọdún 2010, àti Òṣèrébìnrin tí fáàrí rẹ̀ dáńtọ́ jùlọ lọ́dún 2012 láti ọwọ́ City People Magazine Archived 2020-07-29 at the Wayback Machine..[6] Lọ́dún 2011, wọ́n yàn án fún àwòrán ìbẹ̀rẹ̀ tí ìwé-ìròyìn olóṣoooṣù àṣà àti ìṣé tí oṣù Kejìlá. Zen Archived 2012-01-05 at the Wayback Machine..[7] Olóòtú Said Zen Magazine, Ọ̀gbẹ́ni Arinze Nwokolo, júwe báyìí "... Susan Peters jẹ́ Òṣèrébìnrin tó lẹ́bùn àrà ọ̀tọ̀, tí ó sìn máa ń tẹpá mọ́ iṣẹ́ tó yàn láàyò dáadáa..." [8]

Susan Peters
Susan Peters lọ́dún 2011
Ọjọ́ìbí30 May 1980 (1980-05-30) (ọmọ ọdún 44)
Ado, Ìpínlẹ̀ Benue, Nàìjíríà
Ọmọ orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́òṣèrébìnrin
Websiterealsusanpeters.com

Àṣàyàn àwọn àmìn-ẹ̀yẹ tó gba

àtúnṣe
  • Àmìn-ẹ̀yẹ City People: Òṣèré tó dára jù lọ lọ́dún 2010
  • Àmìn-ẹ̀yẹ NAFCA (Nollywood and African Film Critics Awards) àríwá Carolina
  • Àmìn-ẹ̀yẹ Nigerian Oscars: Amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹ̀dá ìtàn tó dára jù lọ fún ọdún 2011
  • Àmìn-ẹ̀yẹ Afro-Hollywood Awards, UK: 16th African Film Awards 2011, Òṣèrébìnrin tó dára jù lọ nínú sinimá àgbéléwò èdè òyìnbó fún ipa tó kó nínú eré Bursting Out[9]
  • Àmìn-ẹ̀yẹ Best of Nollywood 2011: Amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹ̀dá ìtàn tó dára jù lọ nínú Bursting Out
  • Àmìn-ẹ̀yẹ DIVA 2011: fún idagbasoke ilé iṣẹ́ sinimá àgbéléwò
  • Àmìn-ẹ̀yẹ City People Magazine Beauty and Fashion 2012: Òṣèrébìnrin tí fáàrí rẹ̀ dára jù
  • Àmìn-ẹ̀yẹ Golden Icons Academy Movie Award (GIAMA) 2012, Houston, USA: Amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹ̀dá ìtàn tó dára jù lọ

Àtẹ àṣàyàn àwọn sinimá àgbéléwò rẹ̀

àtúnṣe
Susan Peter's movie career to date:
Ọdún Àkọlé Ipa Olùdarí Àwọn Òṣèré mìíràn
2002 Wasted Effort Masie Ayoade Andy Amanechi Ramsey Nouah, Rita Dominic, Muna Obiekwe
2002 The Hammer Izu Ojukwu
2002 Songs of Sorrow Kabat Esosa Egbon Tunde Alabi, Ini Edo, Pat Attah, Maureen Solomon, Muna Obiekwe
2002 11 days, 11 Nights Kabat Esosa Egbon Pat Attah, Dakore Egbuson, Yemi Blaq
2003 Squad 23 Tarila Thompson Saint Obi, Liz Benson, Enebeli Elebuwa, Gentle Jack, Ejike Asiegbu
2003 State of Emergency 2 Teco Benson Ejike Asiegbu, Bimbo Manuel and Saint Obi
2003 The Begotten E. O'Squires Ogbonnaya Ini Edo, Rita Dominic, Ngozi Ezeonu
2003 The President Must Not Die Zeb Ejiroz Ufuoma Ejenobor
2004 Stolen Bible Emeka Nwabueze Emeka Ani, Kate Henshaw-Nuttal, Benedict Johnson, Chinyere Nwabueze
2004 War Front 2 Teco Benson Festus Aguebor, Sam Dede, Steve Eboh, Enebeli Elebuwa
2004 Saving the Crown Lancelot O. Imasuen Patience Ozokwor, Jim Iyke, Festus Aguebor, Emmanuel Francis
2004 Wild Wind
2004 Second Adam Theodore Anyanji Chioma Chukwuka, Eucharia Anunobi and Mike Ezuruonye
2005 Life is Beautiful Pete Edochie, Stephanie Okereke
2005 Immoral Act Obi Okor Kanayo O Kanayo, Moses Armstrong
2005 30 Days Mildred Okwo Genevieve Nnaji, Joke Silva, Segun Arinze
2005 Moment of Truth Lancelot Oduwa Imasuen Chioma Chukwuka, Mike Ezuruonye and Benedict Johnson
2006 Behind the Plot Nonso Emekaekwue, Ikechukwu Onyeka Desmond Elliot, Benedict Johnson and Stephanie Okereke
2006 Young Masters Ikechukwu Onyeka Osita Iheme, Chinedu Ikedieze and Benedict Johnson
2006 Ghetto Language Sunny Okwori Kelvin Books, Ini Edo and Desmond Elliot
2006 Good Mother Amayo Uzo Philips Stephen Ahanaonu, Ifeanyi Egbulie and Osita Iheme
2006 Nollywood Hustlers Pauline Moses Inwang Uche Jombo, Charles Inojie, Monalisa Chinda, Ramsey Nouah, Ejike Asiegbu
2009 Timeless Passion Desmond Elliot Desmond Elliot, Ramsey Nouah, Uche Jombo, Mona Lisa Chinda
2009 Bursting Out Ibiere Desmond Elliot, Daniel Ademinokan Genevieve Nnaji, Majid Michel, Desmond Elliot, Omoni Oboli
2010 Catwalk Series (TV) Frank Rajah Arase Monalisa Chinda, Uru Eke, Memory Savanhu,
2010 Black Heat Tricia Esiegbe
2011 The Ransom Aquila Njamah Patience Ozorkwor, Funke Akindele, Jerry Amilo, Victor Esezobor
2011 Love Entrapped Wendy and Desmond Elliot
2014 Champagne Emem Isong Majid Michel, Alexx Ekubo, Tana Adelana
2017 Celebrity Marriage Pascal Amanda Toyin Abraham, Odunlade Adekola, Tonto Dikeh, Jackie Appiah, Kanayo O. Kanayo

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe