The Campus Queen
The Campus Queen jẹ́ fíìmù ilẹ̀ Nàìjíríà ti ọdún 2004, èyí tí Tunde Kelani darí, pẹ̀lú Mainframe Films and Television Productions tí wọ́n ṣe àgbéjáde fíìmù náà.[1][2] Ìṣàfihàn àkọ́kọ́ fíìmù yìí wáyé ní African Film Festival, ní New York City, U.S.A, ní ọdún 2004. Òun sì ni wọ́n yàn ní Black Film Festival ní Cameroon.[3]
The Campus Queen | |
---|---|
Adarí | Tunde Kelani |
Òǹkọ̀wé | Akínwùmí Iṣọ̀lá |
Àwọn òṣèré | |
Orin | Sound Sultan |
Ìyàwòrán sinimá | Tunde Kelani |
Olùpín | Rolex Nigeria Limited |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 100min |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | Yoruba and English |
Ìpilẹ̀ṣẹ̀
àtúnṣeThe Campus Queen jẹ́ fíìmù olórin, ijó àti oríṣiríṣi ìṣe àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga. Ó sì tún yànnàná ìfẹ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fún ipò àti ṣíṣe àkóso.[4]
Àwọn akópa
àtúnṣe- Jide Kosoko
- Lere Paimo
- Segun Adefila
- Sound Sultan
- Khabirat Kafidipe
- Tope Idowu
- Afeez Oyetoro
- Serah Mbaka
- Akinwunmi Isola
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "7 Tunde Kelani Films You Should Watch Immediately". 9 September 2015. Retrieved 16 September 2015.
- ↑ Ayodele Lawal; Femi Adepoju (10 October 2003). "Nigeria: Kelani Rolls Out 'Campus Queen', Sound Sultan Gets a Role". P.M. News (All Africa). http://www.allafrica.com/stories/200310100440.html. Retrieved 16 September 2015.
- ↑ "The Campus Queen Premiers". Thisday Live. 12 June 2004. http://www.naijarules.com/index.php?threads/the-campus-queen-premieres.2715/. Retrieved 16 September 2015.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Campus Queen". 10 November 2011. Archived from the original on 19 April 2015. Retrieved 16 September 2015.