Cleanser jẹ fiimu igbadun ti won gbe jade ni orilẹ-ede Naijiria ni odun 2021 ti Mathew Alajogun se ako sile re, James Abinibi si gbe ere naa jade.

The Cleanser
AdaríJames Abinibi
Olùgbékalẹ̀Mathew Alajogun
Òǹkọ̀wéMathew Alajogun
Àwọn òṣèréKehinde Bankole
Bolanle Ninalowo
Alex Osifo
Antar Laniyan
Déètì àgbéjáde
  • 22 Oṣù Kínní 2021 (2021-01-22)
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèEnglish & Yoruba

Awon olukopa tabi eda-itan inu ere naa ni: Kehinde Bankole, Bolanle Ninalowo, Alex Osifo ati Antar Laniyanti o je olu eda-itan..[1]

Agbekale ere naa

àtúnṣe

Ere naa da lori bi olu-eda itan inu ere yi se fe se idailekoo fun oselu jegudu-jera.

Won gbe ere naa jade ni ojo kokanlelogun osu Kinni odun 2021, won si fi aye gba ariwoye ati lameyito nipa ere naa lati odo awon onworan.[1]

Awon Eda Itan

àtúnṣe

Awon ito kasi

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 Tv, Bn (2021-01-21). "Kehinde Bankole, Bolanle Ninalowo, Chiwetalu Agu… Watch the Official Trailer for James Abinibi's "The Cleanser"". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-02-17. 

Àdàkọ:Portal bar Àdàkọ:Authority control