Àkójọpọ̀ oúnjẹ àwọn ará ilẹ̀ Ethiopia àti Eritrea

Àtòjọ lórí Wikimedia

Èyí jẹ́ àkójọpọ̀ àwọn oúnjẹ tí wọ́n ń jẹ ní Ethiopia àti Eritrea. Oúnjẹ àwọn ará Ethiopia àti àwọn ará Eritrea èyí tí ó sáábà máa ń kún fún àwọn ẹ̀fọ́, ata, àti ẹran. Ó sáábà máa ń wà ní ipò oúnjẹ wat (àti w'et, wot tàbí tsebhi), ọbẹ̀ tí ó ki, jíjẹ pẹ̀lú injera, búrẹ́dì ńlá ti sourdough,[1] èyí tí ó tóbi tó àádọ́ta sẹ̀ǹtímítà ní òòró, èyí tí a ṣe láti ara ìyẹ̀fun teff.[1] Àwọn ènìyàn orílẹ̀-èdè Ethiopia àti àwọn Eritrea máa ń jẹ ẹ́ pẹ̀lú ọwọ́ ọ̀tun wọn, nípa lílo injera láti fi jẹ entrées àti àwọn oúnjẹ àjẹpọ kan.[1]

This meal, consisting of injera bread topped with several kinds of wat (stew), is typical of Ethiopian and Eritrean cuisine.

Àwọn oúnjẹ àwọn ènìyàn Ethiopia àti Eritrea

àtúnṣe
 
Shahan ful (pictured right, garnished with lemon)

Búrẹ́dì

àtúnṣe

Oúnjẹ àárọ̀

àtúnṣe
  • Fir-fir – búrẹ́dì tí a máa ń jẹ pẹ̀lú niter kibbeh àti berbere.
  • Ga'at tàbí genfo – àsáró tí a ṣe láti ara barley tàbí ìyẹ̀fun wíìtì , pẹ̀lú niter kibbeh àti berbere.

Àwọn oúnjẹ

àtúnṣe
  • Ful medames – oúnjẹ àwọn ará Egypt tí wọ́n sè láti ara ẹ̀wà Vicia faba tí wọ́n máa ń jẹ pẹ̀lú òróró, cumin àti àlùbọ́sà, ata ilẹ̀, àti ohun mímu ẹlẹ́rìndòdò. Ó jẹ́ oúnjẹ tí ó gbajúmọ̀ ní orílẹ̀-èdè, Ethiopia, Eritrea àti àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn.
  • Gored gored – oúnjẹ tí ó kún fún ẹran.
  • Kitfo – ẹran pẹ̀lú mitmita àti niter kibbeh
  • Shahan ful – ọbẹ̀ ẹ̀wà fava tí wọ́n máa ń jẹ pẹ̀lú àwọn ẹ̀fọ́ tútù.
  • Shiroọbẹ̀ tí èròjà rẹ̀ jẹ́ chickpeas tàbí broad bean
  • Tibs
  • Tihlo
  • oúnjẹ Wat – ọbẹ̀ tí a le sè pẹ̀lú ẹran ṣínkìn, ẹran màálù, ẹran àgùntàn, onírúurú àwọn ẹ̀fọ́, berbere, àti niter kibbeh. Wat jẹ́ oúnjẹ tí wọ́n máa ń jẹ pẹ̀lú injera.

Irúgbìn

àtúnṣe
  • Enset [2][3]
  • Teff – wọ́n sáábà máa ń gbìn ín tí wọ́n sì máa ń lò ó ní Eritrea àti Ethiopia, níbi tí wọ́n ti máa ń fi í ṣe injera tàbí tayta. [4]
  • Gesho
  • Niger seed – wọ́n máa ń lo àwọn èso rẹ̀ láti ṣe àwọn òróró.

Àwọn èròjà amọ́bẹ̀dùn

àtúnṣe

Ohun mímu

àtúnṣe
  • Coffee - Wọ́n máa ń lò ó ní jebena.
  • Tej – Wáìnì olóyin [10] or mead that is brewed and consumed in Ethiopia and Eritrea.
  • Tella – Ọtí ìbílẹ̀ tí a ṣe ní orílẹ̀-èdè Ethiopia àti Eritrea èyí tí wọ́n ṣe láti ara teff àti sorghum. Wọ́n máa ń pè é ní siwaTigray àti Eritrea.

Wò pẹ̀lú

àtúnṣe

Àdàkọ:Portal box

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 1.2 Javins, Marie. "Eating and Drinking in Ethiopia." Archived 2013-01-31 at the Wayback Machine. Gonomad.com. Accessed July 2011.
  2. RHS A-Z encyclopedia of garden plants. United Kingdom: Dorling Kindersley. 2008. pp. 1136. ISBN 1405332964. 
  3. "Uses of Enset". The 'Tree Against Hunger': Enset-Based Agricultural Systems in Ethiopia. American Association for the Advancement of Science. 1997. Archived from the original on 19 August 2007. Retrieved 13 August 2007.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. ti. abre-Madhin, Eleni Zaude. Market Institutions, Transaction Costs, and Social Capital in the Ethiopian Grain Market. Washington, DC: International Food Policy Research Institute, 2001
  5.  Aframomum corrorima was published in Spices, Condiments and Medicinal Plants in Ethiopia, Their Taxonomy and Agricultural Significance. (Agric. Res. Rep. 906 & Belmontia New Series) 12:10. 1981. The specific epithet was taken from its basionym, Amomum corrorima A.Braun GRIN (April 9, 2011). "Aframomum corrorima information from NPGS/GRIN". Taxonomy for Plants. National Germplasm Resources Laboratory, Beltsville, Maryland: USDA, ARS, National Genetic Resources Program. Retrieved June 19, 2011. Synonyms: (≡) Amomum corrorima A.Braun (basionym) 
  6. Bernard Roussel; François Verdeaux (April 6–10, 2003). "Natural patrimony and local communities in ethiopia: geographical advantages and limitations of a system of indications" (PDF). 29th Annual Spring Symposium of Centre for African Studies. Archived from the original (PDF) on 2006-11-26. This Zingiberaceae, Aframomum corrorima (Braun) Jansen, is gathered in forests, and also grown in gardens. It is a basic spice in Ethiopia, used to flavor coffee and as an ingredient in various widely used condiments (berbere, mitmita, awaze, among others).  Unknown parameter |name-list-style= ignored (help)
  7. Debrawork Abate (2003) (in am). የባህላዌ መግቦች አዘገጃጀት (2nd ed.). Addis Ababa: Mega Asatame Derjet (Mega Publisher Enterprise). pp. 22–23. 
  8. Gall, Alevtina; Zerihun Shenkute (November 3, 2009). "Ethiopian Traditional and Herbal Medications and their Interactions with Conventional Drugs". EthnoMed. University of Washington. Retrieved January 27, 2011. 
  9. Katzer, Gernot (July 20, 2010). "Ajwain (Trachyspermum copticum [L.] Link)". Retrieved January 28, 2013. 
  10. Bahiru, Bekele; et al. (July–September 2001). "Chemical and nutritional properties of 'tej', an indigenous Ethiopian honey wine: variations within and between production units". Vol. 6, No. 3. The Journal of Food Technology in Africa. pp. 104–108. Retrieved 13 November 2014. 
àtúnṣe