Ada
Ada jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìlú tó wà ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Boripe, ní Ipinle Osun, ní orílẹ̀-èdè Naijiria. Oba Oyetunde Olumuyiwa Ojo (The Olona of Ada)[3] ni olórí ìlú náà. Lára àwọn ọjà tó wà ní ìlú náà ni Ile Oba Oludele, ile oba Adeitan, Ile oba Olugbogbo, Ile Aro, Ile Alagbaa, Ojomu Oteniola, Alade, Eesa, Jagun, Osolo, Oke Baale, Asasile, Oluode, Agba Akin, àti Ile Odogun.[4]
Ada | |
---|---|
Town | |
Motto(s): Akara Loro Ada | |
Coordinates: 7°53′44″N 4°42′34″E / 7.89556°N 4.70944°ECoordinates: 7°53′44″N 4°42′34″E / 7.89556°N 4.70944°E | |
Country | Nigeria |
State | Osun State |
Local Government area | Boripe |
Founded | 1900s |
Government | |
• Type | Monarchy |
• Olona Of Ada | Oba Oyetunde Olumuyiwa Ojo (2020-Present)[1] |
Area | |
• Total | 34.54 km2 (13.34 sq mi) |
Population | 174,152 [2] |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
National language | Yorùbá |
Ẹ̀sìn
àtúnṣeOríṣiríṣi ẹ̀sìn ni wọ́n ń ṣe ní ìlú Àdá, àmọ́ ẹ̀sìn Kirisiteeni àti Mùsùlùmí ló gbilẹ̀ jù. Àwọn ìjọ Pentecostal, Apostolic, Evangelical àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ló wà káàkiri ilẹ̀ náà.
Iṣẹ́ tí wọ́n yàn láàyò
àtúnṣeIṣẹ́ ọṣẹ dúdú ni àwọn ará Ada yàn láàyò. Wọ́n sì tún kúndùn iṣẹ́ àgbẹ̀.
Àwọn ilé ìgbafẹ́
àtúnṣeÌlú Ada ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé ìgbafẹ́ fún àwọn àlejò àti arìnrìn-àjò. Lára àwọn ilé ìgbafẹ́ ní ìlú Àdá ni.
- Miccom Golf Hotel
- Royal life Hotel
- Epic Hotel (àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ)
Àwọn ilé-ẹ̀kọ́
àtúnṣeLára àwọn ilé-ẹ̀kọ́ ní ìlú náà ni...
Àwọn ilé-ìwé ìjọba:
- Secondary commercial grammar school
- local authority middle school (L.A school)
- Baptist Primary School
- St Andrew Primary School
- Ajayi Memorial High School
Àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ...
Àwọn ilé-ìwé aládàáni:
- Goshen Model college
- El-Shaddai Private school
- Salem Comprehensive high school
- Excel kiddies School
Àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "New Olona of Ada Emerges". OsunDefender. 31 January 2020.
- ↑ "Map of Ada in Osun, Nigeria". Getamap.net. 28 August 2023.
- ↑ https://thenationonlineng.net/oyetunde-ojo-my-battles-with-tradition-as-ada-monarch/
- ↑ Princess Comfort Olufunke PonnLe: A Truncated Love Story Archived December 2, 2012, at the Wayback Machine., November 2012, ThisDayLive, Retrieved February 2016