Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Afikpo
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Afikpo jẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ebonyi ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olú agbègbè náà wà ní Ehugbo, Afikpo. Àwọn ìlú pàtàkì níbẹ̀ ni [Unwana]], Itim, Ohaisu, Nkpoghoro, Ugwuegu/Amaizu, Ozizza, Amasiri, Ibii/Akpoha. Èdè ìbílẹ̀ Igbo tí ó ń jẹ́ 'Ehugbo ni wọ́n máa ń sọ. Ìlú yìí kún fún àwọn àṣà Igbo tó jinná tí ó sì múnádóko àti àwọn ọdún ìbílẹ̀ bí i "ọdún iṣu tuntun" tí wọ̀n máa ń ṣe ní ìparí oṣù kẹjọ. [1]
Afikpo North Afikpo | |
---|---|
Country | Nigeria |
State | Ebonyi State |
Headquarters | Afikpo |
Major city |
|
Time zone | UTC+1 (WAT) |
Àwọn Èèyàn Gbajúmọ̀ ní agbègbè náà
àtúnṣeÀwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 7 October 2009. Retrieved 2009-10-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)