Àgbàjọ Tòkòwò àwọn Orílẹ̀-èdè Ìwọòrùn Áfríkà

Àgbàjọ Tòkòwò àwọn Orílẹ̀-èdè Ìwọòrùn Áfríkà (Economic Community of West African States; ECOWAS tabi EKOWAS) je adipo awon orile-ede meedogun ni agbegbe Iwoorun Afrika to je didasile ni May 28, 1975, pelu itowobowe Adehun ilu Eko. Ise re ni lati segbesoke asepo okowo.

Economic Community of West African States
HeadquartersAbuja, Nigeria
6°27′N 3°23′E / 6.45°N 3.383°E / 6.45; 3.383
Official languages English, French, Portuguese
Ọmọ ẹgbẹ́
Àwọn olórí
 -  Chairman Côte d'Ivoire Alassane Ouattara
 -  President of the Commission Bùrkínà Fasò Kadré Désiré Ouedraogo
 -  Speaker of the Parliament Nàìjíríà Ike Ekweremadu
Ìdásílẹ̀
 -  Treaty of Lagos 28 May 1975[1] 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 5,112,903 km2 (7th)
1,974,103 sq mi 
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2011 300,000,000 (4th)
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 49.2/km2 
127.5/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2011
 -  Iye lápapọ̀ US$ 703,279 Billion[2] (23rd)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan US$ 2500 [3] 
Owóníná Cape Verdean escudo (CVE)
Cedi (GHS)2
Dalasi (GMD)2
Guinean franc (GNF)2
Liberian dollar (LRD)3
Naira (NGN)2
Leone (SLL)3
West African CFA franc (XOF)
Àkókò ilẹ̀àmùrè (UTC0 to +1)
1 If considered as a single entity.
2 to be replaced by the eco in 2015.
3 Liberia has expressed an interest in joining the eco.ItokasiÀtúnṣe