Ini Dima-Okojie

Òṣéré orí ìtàgé

Ini Dima-Okojie (Ọjọ́ ìbí ni 24 June 1990) jẹ́ Òṣèré tí wá ní orílé Èdè Nàìjíríà. Ó fi iṣé rẹ silẹ ní Investment banking láti fí orúkọ sílẹ̀ ní Newyork Film Academy.[1] ó kọ́kọ́ yóò jáde nínú eré Taste Of love lẹyìn ní ò bèrè sí ní jáde nínú àwọn eré kàn kàn bi: multicultural(romcom), Namaste Wahala ni 2012 àti eré kàn tí ó jáde láti ilé iṣé Netflix Nigeria tí àkọlé rẹ jẹ́ Blood Sisters ni 2022.[2]

Ini Dima-Okojie
Dima-Okojie in 2017
Ọjọ́ìbí24 Oṣù Kẹfà 1990 (1990-06-24) (ọmọ ọdún 34)
Lagos, Lagos State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaCovenant University
Iṣẹ́Actress, fashion enthusiast
Ìgbà iṣẹ́2014–present
Gbajúmọ̀ fúnBlood sisters
Olólùfẹ́
Abasi Ene-Obong (m. 2022)

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

A bí Dima-Okojie ní 24, Oṣù Kẹẹ̀fà, Ọdún 1990 sínu ìdílé eléyàn mẹ́rin. Ini Dima-Okojie ni àbígbẹ̀yìn. Ini wá láti ilé àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n. Dókítà Ìṣògún ni bàbá rẹ̀ tí ìyá rẹ̀ sì jẹ́ Olùtọ́jú-òwò. Wọ́n jẹ́ onígbàgbọ́ Kátólìkì tọkàntọkàn.

Nígbà tí Ini n dàgbà, Ini súnmọ́ ìya rẹ̀ gaan ó sì fẹ́ láti dàbi rẹ̀. Ó fẹ́ràn láti máa wo ìya rẹ̀ nígbà tí ó bá n múra láti lọ ìdi iṣẹ́ rẹ̀. Gbogbo bí ìya rẹ̀ ti máa n múra maá n dùn mọ́ Ini. Nítorínà, ó bẹ̀rẹ̀ sí ní fẹ́ràn oge ṣíṣe àti ìmúra bótilẹ̀jẹ́pé ó jẹ́ onítìjú èyàn, Ini bẹ̀rẹ̀ sí ní ní ìgboyà tó bá di toge ṣíṣe

Ní ìdà kejì, arábìnrin ẹ̀gbọ́n rẹ̀ jẹ́ ọ̀dọ́mọdé oníràwọ̀ tí ó tí kópa nínu eré “Mr. Jack’s Dog” eré kan tí ó gbajúmọ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ àwọn ọdún 1990. Eré náà fún Ini ní ànfàní láti káàkiri àgbáyé ní ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀. Ní àkókò kan, ó lọ sí Istanbú, ní ìlu Tọ́kì níbi tí wọ́n ti ń ṣe ìyàwòrán ijó Tọ́kì kan fún eré náà. Wọ́n fi lọ Ini láti ṣe ipa kan nínu eré ṣùgbọ́n ó kọ̀ láti ṣé nítorí ìtìjú rẹ̀.

Fún ìgbà pípẹ́, Ini n gbé nínu ọkàn rẹ̀. Yóó maa wo ìfihàn àwọn àmì ẹ̀yẹ tí yóó sì ma wùú bi pé kí ó wà níbè.

Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Ini lọ sí Ilé-ẹ̀kọ́ Air Force Comprehensive Secondary School ní ìlú Ìbàdàn Nàìjíríà. Lẹ́hìn èyí, ó tẹ̀síwájú sí Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Covenant University ní Nàìjíríà bákan náà

Lẹ́hìn ìparí ẹ̀kọ́ àti àgúnbánirọ̀ rẹ̀, ó ríṣẹ́ sí ilé-iṣẹ́ ìtọ́jú òwò.

Àṣàyàn àwọn eré tí ó ti ṣe

àtúnṣe
  • Taste of Love (2014)
  • Skinny Girl in Transit (2015 - 2017)
  • Desperate Housewives Africa (2015)
  • It's Her Day (2016)
  • North East (2016)
  • The Royal Hibiscus Hotel (2017)
  • Death Toll[3]
  • Bad Hair Day
  • A Bone To Pick
  • The Following Day
  • Vanity Last Game (by MNet)
  • Battleground [4]
  • 5ive[5]
  • Sylvia (2018)
  • Funke! (2018)
  • Oga! Pastor (2019)
  • Kpali (2019)

Àwọn eré tí ati ri

àtúnṣe

Fíìmù àgbéléwò

àtúnṣe
Year Title Role Notes Ref
2022 Blood Sisters Sarah Duru A Netflix Original series [2]
2020 The Smart Money Woman Tami Based on a book of the same name by Arese Ugwu [6]
2019 Oga! Pastor Laitan Gesinde [7]
2018 Battleground (The final showdown) Teni Badmus Africa Magic original [8]
2017 Battleground [9]
2016 5ive [10]
2015–2017 Skinny Girl in Transit Hadiza [11]
2015 Desperate Housewives of Africa Aired on Mnet [12]
Vanity's Last Game
2014 Taste of Love Feyisayo Pepple Nigeria's first telenovela [13][14]

Fíìmù

àtúnṣe
Year Title Role Notes Ref
2021 Lockdown Angela A Nigerian romantic comedy featuring Omotola Jalade Ekeinde, Sola Sobowale and Tony Umez
The Wait Nkechi A Faith-based film
Namaste Wahala Didi Nollywood/Bollywood cross-cultural romantic comedy [15]
2020 Who's The Boss Jumoke A Nigerian Romantic Comedy Film featuring Sharon Ooja, Funke Akindele, Beverly Osu
DOD The first family adventure film in Nigeria
2019 Kpali Amaka Kalayor Alongside Nkem Owoh [16]
2018 Funke! Ms. Cathrine Set in 1996 – Alongside Segun Arinze and Jide Kosoko [17]
Sylvia Gbemi Ogunlana [18]

Àwọn Àmì Ẹ̀yẹ tí ó tí gbà àti àwọn ibi tí wọn tí Yàn

àtúnṣe
Year Award Category Result Ref
2020 Golden Movies Awards Best Golden Actress Drama Wọ́n pèé [19]
2017 Nigeria Entertainment Awards Best Actress in a Supporting Role Wọ́n pèé [20][21]
City People Movie Awards Most Promising Actress Wọ́n pèé [22][21]
ELOY Awards TV Actress of the Year (Battleground) Wọ́n pèé [23]
The Future Awards Africa Prize for acting Wọ́n pèé [24]

Àwọn àwòrán

àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Why I Left Investment Banking For Nollywood – Ini Dima-Okojie". TheInterview Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 22 December 2019. Retrieved 14 July 2021. 
  2. 2.0 2.1 Ravindran, Manori (7 April 2022). "Netflix's First Nigerian Original Series 'Blood Sisters' Unveils Trailer". Variety (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 4 May 2022. 
  3. Odumade, Omotolani. "10 snazzy photos of Ini Dima-Okojie". Pulse. Archived from the original on 2017-12-29. Retrieved 2017-12-28. 
  4. "Joke Silva, Oga Bello, Ini Dima-Okojie Star In Femi Odugbemi’s "Battleground" - 360Nobs.com". www.360nobs.com. Archived from the original on 16 March 2018. Retrieved 23 March 2018. 
  5. "#NEWSERIESALERT – OUR THOUGHTS ON 5IVE THE SERIES". 
  6. "Smart Money Woman: Firstbank Partners Arese Ugwu, Unveils TV Series of the Award-Winning Book". Smart Money Woman: Firstbank Partners Arese Ugwu, Unveils TV Series of the Award-Winning Book (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 21 February 2021. 
  7. BellaNaija.com (11 June 2019). "Ini Dima-Okojie, Uzor Arukwe, Pearl Okorie & Jimmy Odukoya Star in NdaniTV's New Web Series OGA! Pastor". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 21 February 2021. 
  8. "Battle Ground Final Showdown". Linda Ikeji's Blog (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 5 September 2018. Retrieved 9 July 2021. 
  9. BellaNaija.com (25 August 2017). "#AMBattleground Stars Ini Dima-Okojie & Shaffy Bello walk us through Stunning Closets & Extravagant Style". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 21 February 2021. 
  10. "Watch trailer for series starring KC Ejelonu, Baaj Adebule, Ini Dima-Okojie". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 21 October 2016. Retrieved 21 February 2021. 
  11. "Timini Egbuson joins season 3 of show". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 26 August 2016. Retrieved 21 February 2021. 
  12. "Behold, 8 Nollywood beauties to watch out for 2021". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 31 January 2021. Retrieved 21 February 2021. 
  13. "Ini Dima-Okojie, the pretty, dashing actress". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 6 December 2017. Archived from the original on 20 October 2021. Retrieved 21 February 2021. 
  14. "First Nigerian telenovela underway". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 11 August 2014. Retrieved 21 February 2021. 
  15. "Namaste Wahala film wey Nollywood/Bollywood collabo do dey totori fans". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-51569935. 
  16. "Ini Dima-Okojie says working with Nkem Owoh in 'Kpali' kept her on her toes". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 28 December 2019. Archived from the original on 26 February 2021. Retrieved 21 February 2021. 
  17. "Jide Kosoko, Segun Arinze, Eniola Badmus, Ini Dima-Okojie star in Yemi Morafa's 'Funke' | Watch the Teaser on BN". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 17 August 2018. Retrieved 21 February 2021. 
  18. "Sylvia… The 'art' of exploring 'spirit husband' in Nollywood". The Guardian Nigeria News – Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 September 2018. Retrieved 21 February 2021. 
  19. BellaNaija.com (26 November 2020). "Ini Dima-Okojie, Bimbo Ademoye, Ramsey Nouah are Nominees for 2020 Golden Movie Awards Africa". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 4 July 2021. 
  20. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :0
  21. 21.0 21.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :2
  22. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :1
  23. Ndeche, Chidirim (2 November 2017). "Full List Of Nominees For The 2017 ELOY Awards". guardian.ng. Archived from the original on 16 May 2021. Retrieved 21 February 2021. 
  24. BellaNaija.com (24 November 2017). "#NigeriasNewTribe: Wizkid, Ini Dima-Okojie, Simi, Davido nominated for The Future Awards Africa 2017 | See Full List". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 21 February 2021.