Hailliote Sumney

Òṣèrébìnrin ti ilẹ̀ Ghana

Hailliote Sumney tí àwọn ènìyàn tún mọ̀ sí Hallie Sumney jẹ́ òṣèrékùnrin ilẹ̀ Ghana, aṣojú ilé-iṣẹ́ kan, gbajúmọ̀ ètò orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán àti onínúure. Ó ti ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò fún àwọn gbajúgbajà ènìyàn bí i Boris Kodjoe, Michael Blackson, Becca, Stonebwoy àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Òun ni aṣojú lóbìnrin fún ilé-ìtàjà kan ní ìlú Londonpẹ̀lú Stonebwoy, tó jẹ́ aṣojú lọ́kùnrin fún ilé-ìtajà náà. Ní ọdún 2019, wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí i olóòtú ayẹyẹ ìgbàmì-ẹ̀yẹ 4Syte TV's BET.[1][2][3][4]

Hailliote Sumney
Ọjọ́ìbíHailliote Sumney
Orílẹ̀-èdèGhanaian
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of California
Iṣẹ́Actress, brand influencer, TV personality

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Sumney sí ìlú Canada, sínú ìdílé Dr. Kodjoe Sumney àti Dr. Akosuah Sumney, àmọ́ wọ́n kó lọ sí United States nígbà tí ó pé ọmọdún méjì.[5] Ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa nursing ní Summit career college, ní California ó sì tẹ̀síwájú láti lọ sí University of California, Riverside ní California, láti gboyè ẹ̀kọ́ mìíràn.[6][7]

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Ó fi iṣẹ́ nọ́ọ̀sì sílè, níbi tí ó ti ń ṣiṣẹ́ ní Riverside Hospital ní United States láti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ fíìmù ṣíṣe ní ilẹ̀ Africa.[8] Ó ṣe ìfarahàn àkọ́kọ́ nínú fíìmù orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Heels and Sneakers èyí tí Yvonne Nelson ṣàgbéjáde. Bẹ́ẹ̀ sì ni ó fi farahàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù àgbéléwò bí i Lagos Fake Life, èyí tí Mike Ezuruonye ṣàgbéjáde. Iṣẹ́ mìíràn tí ó farahàn nínú ni "To kill a ghost" àti Eden , bẹ́ẹ̀ sì ni wọ́n ti gbé àwọn fíìmù rẹ̀ mìíràn sí orí Netflix, Amazon Prime àti IROKOtv. Yàtọ̀ sí èyí, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olóòtú ètò 4Syte TV.

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

àtúnṣe
Ọdún Fíìmù Ipa Ọ̀rọ̀
2016 Heels and Sneakers (series) produced by Yvonne Nelson, Efia Odo
A way back home with Alex Ekubo, IK Ogbonna
2017 Kintampo produced by Chris Attoh, also starring Adjetey Annan, Sika Osei and Deyemi Okanlawon
Desperate Survivors produced by Samuel De Graft featuring Kalsonme Sinare and Benedicta Gafah
2018 Lagos Real Fake Life Mirabel Produced by Mike Ezeronye also starring Annie Idibia, Emmanuella (Mark Angel Comedy)
Track of My Fears produced by Ama K.Aberese and starring Rama Brew, Marie Humbert, and Blossom Chukwujekwu
2018 Shattered (short film) produced by Haillie Sumney featuring Ian Wordi and directed by Chris Gyan
2019 Twisted starring Fela Makafui, James Gardener
2019 2 Days after Friday produced by Venus Films, starring Jackie Appiah, Mofe Duncan, John Domelo
2019 Smoke Screen Maeve Grant directed by Vickie Wills-Doku, starring Rama Brew, Blossom Chukwujekwu, Marie Humbert-Droz, David Dontoh
2020 Eden directed by Harry Bentil, starring Solomon Fixon-Owoo, Kobby Acheampong, Godwin Namboh
A Woman's Scorn directed by Maxwell Akwesi, starring James Gardener, Anthony Woode, Ekow Blankson and featuring Fela Makafui
Trapped directed by Eazzy Ologe starring IK Ogbonna
Soft Work Nonye directed by Darasen Richards, starring Shaffy Bello, Frank Donga, Mofe Duncan, Alexx Ekubo, IK Ogbonna
2021 Ghana Jollof directed by Uzor Arukwe, Funnybone, Akah Nnani, Joselyn Dunmas
2022 Co Habits directed by Peter Sedufa, starring Fiifi Coleman, Caroline Sampson, Jeffery Nortey, Jackie Ankrah
2023 To Kill a Ghost Sharon Directed by Mike Ezuruonye, starring Pat Akpabio, Lovelin Akpan, Treasure Bassey

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Ghanaian TV personality to host 2019 BET Awards red carpet". www.myjoyonline.com. Retrieved 2019-10-25. 
  2. Quartey, Daniel (2019-06-25). "5 photos of Ghanaian TV star said to have hosted 2019 BET Awards red carpet". Yen.com.gh - Ghana news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-10-25. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. "Haillie, host of 2019 BET Awards red carpet". www.graphic.com.gh. Retrieved 2019-10-25. 
  4. Online, Peace FM. "Ghanaian TV Personality, Haillie Sumney Never Hosted The 2019 BET Awards Red Carpet – What Happened?". www.peacefmonline.com. Archived from the original on 2019-10-25. Retrieved 2019-10-25. 
  5. "HAILLIE SUMNEY BECOMES THE FIRST GHANAIAN TV PERSONALITY TO HOST BET RED CARPET.". BeachFM (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 21 June 2019. Retrieved 2019-10-25. 
  6. Issahaku, Zeinat Erebong (2019-06-21). "Ghanaian TV personality, Hailliote Sumney, to host 2019 BET Awards red carpet". AmeyawDebrah.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-10-25. 
  7. "Ghanaian TV personality to host 2019 BET Awards red carpet". www.ghanaweb.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-10-26. Retrieved 2019-10-26.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. "African celebrities are prone to STDs and HIV – Actress, Haillie Sumney says". www.ghanaweb.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-10-25.