Ilé Ìfowópamọ́-àgbà tí Nàìjíríà
(Àtúnjúwe láti Ilé Ìfowópamọ́-àgbà Tí Nàìjíríà (The Central Bank of Nigeria))
Ilé Ìfowópamọ́-àgbà tí Nàìjíríà jẹ́ Ilé-ìfowópamọ́-àgbà tí ó ń ṣe kòkárí àti ìmójútó àwọn ilé Ìfowópamọ́ káràkátà lábẹ́ òfin Ìfowópamọ́ tí Ìjọba Àpapọ̀ gbé kalẹ̀ lọ́dún 1958, tí ó sìn bẹ̀rẹ̀ lọ́jọ́ kìíní oṣù keje ọdún 1959.[1] Ó. Jẹ́ Ilé-ìfowópamọ́ fún àwọn Ilé-ìfowópamọ́[2]. Gómìnà ní orúkọ oyè tí Adarí yànyàn tí ó máa ń darí Ilé Ìfowópamọ́-àgbà máa ń jẹ́. Godwin Emefiele ní Gómìnà Ilé Ìfowópamọ́-àgbà tí ó wà lórí àléfà lọ́wọ́́lọ́wọ́.[2] Ààrẹ àná, Goodluck Jonathan ló yàn án lọ́dún 2014, lẹ́yìn èyí, Ààrẹ Muhammadu Buhari tún ṣe àtúnyàn rẹ̀ lọ́dún 2018 fún sáà Elékejì. [3].
Ilé Ìfowópamọ́-àgbà tí Nàìjíríà | |||
| |||
Headquarters | Abuja, FCT, Nigeria | ||
---|---|---|---|
Established | 1958 | ||
Central Bank of | Nigeria | ||
Currency | Nigerian naira | ||
ISO 4217 Code | NGN 566 | ||
Website | cbn.gov.ng |
Àtòjọ Àwọn Gómìnà Ilé Ìfowópamọ́ àgbà ti Nàìjíríà
àtúnṣeÀwọn wọ̀nyí ni Gómìnà Ilé Ìfowópamọ́ àgbà ti Nàìjíríà tí ó ti jẹ láti ọdún 1960 títí di àkókò yìí:[4]
Governor | Previous position | Term start | Term end |
---|---|---|---|
Roy Pentelow Fenton | 24 July 1958 | 24 July 1963 | |
Aliyu Mai-Bornu | Deputy Governor, CBN | 25 July 1963 | 22 June 1967 |
Clement Nyong Isong | Advisor International Monetary Fund | 15 August 1967 | 22 September 1975 |
Adamu Ciroma | 24 September 1975 | 28 June 1977 | |
Ola Vincent | Deputy Governor, CBN | 28 June 1977 | 28 June 1982 |
Abdulkadir Ahmed | Deputy Governor, CBN | 28 June 1982 | 30 September 1993 |
Paul Agbai Ogwuma | CEO, Union Bank of Nigeria | 1 October 1993 | 29 May 1999 |
Joseph Oladele Sanusi | CEO First Bank of Nigeria | 29 May 1999 | 29 May 2004 |
Charles Chukwuma Soludo | Chief Executive, National Planning Commission | 29 May 2004 | 29 May 2009 |
Sanusi Lamido Aminu Sanusi | CEO, First Bank of Nigeria | 3 June 2009 | 20 February 2014[5] |
Sarah Alade | Deputy Governor, Central Bank of Nigeria | 20 February 2014 | 3 June 2014 |
Godwin Emefiele | Chief Executive Officer, Zenith Bank | 3 June 2014 | 15 September 2023[5][6] |
Yemi Cardoso | Chief Executive Officer, Zenith Bank | 15 September 2023 | to date |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "History of CBN". cenbank.org. Central Bank of Nigeria. Retrieved 25 September 2018.
- ↑ 2.0 2.1 ":: Central Bank of Nigeria : Monetary Policy Functions". Central Bank of Nigeria | Home. 2006-02-20. Retrieved 2020-01-14.
- ↑ "Godwin Emefiele, Central Bank of Nigeria: Profile and Biography". Bloomberg.com. 2019-02-07. Retrieved 2020-01-14.
- ↑ "Past And Present Governors". Central Bank of Nigeria. Retrieved 2010-02-28.
- ↑ 5.0 5.1 "Nigeria central bank head Lamido Sanusi ousted". bbc.com. BBC. Retrieved 25 September 2018.
- ↑ "BREAKING: Senate confirms Emefiele’s re-appointment a day after screening". Oak TV Newstrack. 16 May 2019. Archived from the original on 17 May 2019. https://web.archive.org/web/20190517092505/https://oak.tv/newstrack/breaking-senate-confirms-emefiele/. Retrieved 17 May 2019.