Elena Dementieva

(Àtúnjúwe láti Jelena Dementieva)

Elena Viatcheslavovna Dementieva (Rọ́síà: Елена Вячеславовна Дементьева, Pípè ní èdè Rọ́síà: [jɪˈlʲenə dʲɪˈmʲentʲjɪvə]; ọjọ́ìbí 15 October 1981) ni oníṣẹ́ agbá tẹ́nísì ará Rọ́síà tó ti fẹ̀yìntì.[1] Dementieva gbajúmọ̀ fún àṣeyọrí rẹ̀ nínú ìdíje ni Òlímpíkì 2008 ní Beijing nígbà tó gba ẹ̀sọ́ wúrà ìdíje àwọn obìnrin ẹnìkan, lẹ́yìn ìgbà tó gba ẹ̀sọ́ fàdákà níbi ìdíje Òlímpíkì ọdún 2000 ní Sydney. Ó gba ife-ẹ̀yẹ ìdíje àwọn ẹnìkan 16 lórí WTA, ó dé òpin àwọn ìdíje Open Fíránsì ọdún 2004 àti Open Amẹ́ríkà ọdún 2004.

Elena Dementieva
Елена Дементьева
Orílẹ̀-èdèRọ́síà Rọ́síà
IbùgbéMonte Carlo, Monaco
Ọjọ́ìbí15 Oṣù Kẹ̀wá 1981 (1981-10-15) (ọmọ ọdún 43)
Moscow, Russian SFSR, Soviet Union
Ìga1.80 m (5 ft 11 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà25 August 1998
Ìgbà tó fẹ̀yìntì29 October 2010
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed (two-handed backhand)
Ẹ̀bùn owóUS$ 14,867,437
Ẹnìkan
Iye ìdíje576–273
Iye ife-ẹ̀yẹ16 WTA, 3 ITF titles
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 3 (6 April 2009)
Grand Slam Singles results
Open AustrálíàSF (2009)
Open FránsìF (2004)
WimbledonSF (2008, 2009)
Open Amẹ́ríkàF (2004)
Àwọn ìdíje míràn
Ìdíje WTASF (2000, 2008)
Ìdíje Òlímpíkì Gold medal (2008)
Ẹniméjì
Iye ìdíje152–86
Iye ife-ẹ̀yẹ6 WTA, 3 ITF titles
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 5 (14 April 2003)
Grand Slam Doubles results
Open Austrálíà3R (2005, 2006, 2007)
Open Fránsì3R (2004)
WimbledonSF (2003)
Open Amẹ́ríkàF (2002, 2005)
Àwọn ìdíje Ẹniméjì míràn
Ìdíje WTAW (2002)
Ìdíje Òlímpíkì1R (2004)
Last updated on: 25 October 2010.
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki
Women's tennis
Adíje fún Rọ́síà Rọ́síà
Wúrà 2008 Beijing Singles
Fàdákà 2000 Sydney Singles


  1. "Retirement of Elena Dementieva". wtatour.com. 29 October 2010. Retrieved 30 October 2010.