Joe el
Joel Amadi, tí a mọ̀ sí Joe El, (tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹta ) jẹ́ olórin, òǹkọrin àti eléré ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ilé-iṣẹ́ Kennis Music fọwọ́ síí.
Joe El | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Joel Amadi Didam |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Joe EL, Joe-El, Joe Everlasting |
Ọjọ́ìbí | Sokoto, Sokoto State, Nigeria |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Instruments | Vocals |
Years active | 2006–present |
Labels | Kennis Music |
Associated acts |
Ní ọdún 2006, ó kópa nínú ìdíje orin-kíkọ tí Star Quest ní ìlú Jos,lẹ́yìn náà ni ó tún kópa nínú ìdíje ayẹyẹ àjíǹde ọlọ́dọọdún ti i Kennis Music.
Ẹbí àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeÌdílé Amadi Didam ní ìpínlẹ̀ Sokoto ni a bí Joel Amadi sí. Àmọ́ Ipinle Kano ni ó dàgbà sí.[1] Bàbá rẹ̀ wá láti Zikpak, ìlú Kafanchan, apá Gúúsù Ipinle Kaduna,[2] àti ìyá rẹ̀ láti ìlú Otukpa ní Ipinle Benue. Lẹ́yìn ètò ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀ẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní ilé-ìwé Ramat, ó lọ ilé-ìwé girama Army Day Secondary School, ní Bukavo Barracks, Ipinle Kano, lẹ́yìn tí ó ṣe tán, ó wá lọ Kaduna State College of Education, ní ìlú Kafanchan (èyí tó ní ìbáṣepọ̀ pèlú University of Jos), ó ṣe tán ní ọdún 2005, pẹ̀lú ìgboyè nínú Accounting àti Auditing.[1]
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé-iṣẹ́ ìròyìn ni ó gbé ìròyìn ikú bàbá rẹ̀ láti ọwọ́ àwọn darandaran ìlú rẹ̀, wọ́n sì ba kẹ́dùn.[3][2][4]
Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi olórin
àtúnṣeJoe El bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin kíkọ rẹ̀ ní ọdún 2006 níbi tí ó ti kópa nínú ìdíje orin kan[5] èyí tó jẹ́ ìgbà àkọ́kọ́ rẹ̀ lórí ẹ̀rọ-amóhùn-máwòrán. Ní ọdún 2009, ó kó lọ sí ipinle Eko. Ó pàdé Kenny Ogungbe, olùdarí KEnnis Music, tí ó fún ni iṣẹ́ ní ọdún 2010. Oein àkọ́kọ́ kọ rẹ̀ ni "I No Mind" ni wọ́n padà yàn bíi orin R'n'b tó dára jù lọ ni NMVA 2011 awards.
Ó túnbọ̀ jẹ́ gbajúgbajà si nígbà tí ó gbé orin "Bakololo" jáde, èyí tí ó padà di orin tí ilé-iṣẹ́ rédíò máa ń kọ látigbà dégbà ní ọdún 2011 àti 2012. [5] Ó tún gbé orin bíi "Love song" and "Happy" jáde. Pẹ́lú àwọn orin yìí, ó lọ sí bíi ìpínlẹ̀ mẹ́rin ní orílẹ̀-èdè NAijiria,ó sí kọrin ní Glo Rock n Roll show, the Star Quest Grand Finale, the annual Kennis Music Easter Fiesta àti àwọn orí-ìtàgé ńlá mìíràn.[5]
Wọ́n máa ń fi wé 2face Idibia, tí ó jé gbajúgbajà olórin ilé Nàìjíríà nítori wọ́n jọra bákan.[6] Ní ọdún 2014, ó fi ìfé tó ní sí 2face Idibia hàn àti èrò ọkàn rẹ̀ hàn láti bá a kọrin.[7] Ní ọdún 2014, Joe El gbé orin kan jáde tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Hold On" níbi tí ó ti ṣàfihàn 2face Idibia.
Àwọn orin rẹ̀
àtúnṣeSongs
àtúnṣe- "Gbemisoke", 2016
- "Nwanyi Oma"
- "Keep Loving"
- "Yamarita" (featuring Olamide)
- "Chukwudi" (featuring Iyanya)
- "Celebrate" (featuring Yemi Alade)
- "Oya Now" (featuring Oritsefemi)
- "Rawa (dance)", 2019
- "Epo" (featuring Davido, Zlatan)
Albums
àtúnṣe- Songs
- Hold On
- Timeless (2015)[8]
- Do Good (2016)[9]
- She Like Me
- Onye (Eji Kolo)
- You Are In Love
- I No Mind
Compilations featured
àtúnṣe- "Bridal" (featuring Sound Sultan and Honorebel)
- Kennis Music All Starz Compilation (2011)[10]
Àwọ́n àmì-ẹyẹ̀ rè
àtúnṣeYear | Event | Prize | Recipient | Result | Ref |
---|---|---|---|---|---|
2015 | The Headies | Award for Best Collaboration | "Hold On" (featuring 2Baba)|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [11] | |
2014 | The Headies | Award for Best Collaboration | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [12] | |
Nigerian Music Video Award (NMVA) | Best Video Award By A New Act | "Oya Now" (featuring Oritsefemi) | Gbàá | [13] | |
Best Afro Beat Video | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [13] | |||
Best RnB Video | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [13] | |||
2013 | The Most Finest Girl in Nigeria Beauty Pageant | Best New Act | Himself | Gbàá | |
The Most Endorsed Artiste | Himself | Gbàá | [1] | ||
2012 | Kennis Music | The Most Laspotech celebrated Artiste of the year Award | Himself | Gbàá | |
2011 | Nigerian Music Video Award (NMVA) | Best RnB Video Award | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 "Joe El". notjustok. Archived from the original on 22 September 2020. Retrieved 8 August 2020.
- ↑ 2.0 2.1 "Herdsmen Murder Singer Joeel's Father in Kaduna". THEWILL. 25 July 2020. Retrieved 8 August 2020.
- ↑ Bamidele, Michael (July 25, 2020). "Joel Amadi Loses Father to Herdsmen Attack". The Guardian. https://m.guardian.ng/life/joel-amadi-loses-father-to-herdsmen-attack/.
- ↑ "Singer Joel Amadi's Father Killed By Herdsmen". Retrieved 8 August 2020.
- ↑ 5.0 5.1 5.2 "Joe El". notjustok. Archived from the original on 22 September 2020. Retrieved 8 August 2020.
- ↑ Olatunbosun, Yinka (24 August 2014). "Nigeria: Joe-El's Journey to Stardom". All Africa. This Day. Retrieved 8 August 2020.
- ↑ "I can't fight with Tuface Idibia; he's my brother, a legend. – JoEl Amadi (WATCH)". Idoma Voice. July 25, 2014. Retrieved 9 August 2020.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Nigerian Artist, Joe El Debuts 'Timeless' Album: Features International Music Prodigy B. Howard on 'Blown Away' Track". CISION PR Newswire. King Empire Entertainment. August 19, 2015. Retrieved August 17, 2020.
- ↑ Yhusuff, al (16 September 2016). "Do Good". Tooxclusive. Archived from the original on 7 March 2021. Retrieved 8 August 2020.
- ↑ "Kennis Music All Starz Compilation 2011". Retrieved August 17, 2020.
- ↑ Adeleke, Shayo (30 September 2015). "The Headies Awards 2015 – Full Nominees List". 36NG. http://www.36ng.com.ng/2015/09/30/the-headies-awards-2015-full-nominees-list/.
- ↑ "The Headies Awards 2014 – Full Nominees List (Year in Review: July 2013 - June 2014)". The Headies. May 25, 2014. Retrieved August 17, 2020.
- ↑ 13.0 13.1 13.2 "Niyola's 'Toh Bad' Takes Away Best RnB Video At NMVA". Channels Television. November 27, 2014. Retrieved August 17, 2020.