Juan Martín del Potro
Orúkọ yìí lo àṣà ìṣorúkọ ní èdè Spéìn; àkọ́kọ́ tàbí orúkọ ìdílé bàbá ni del Potro èkejì tàbí orúkọ ìdílé ìyà ni Lucas.
Juan Martín del Potro Lucas (Pípè: [xwan maɾˈtin del ˈpotɾo])[3] (ọjọ́ìbí 23 September 1988), tàbí Delpo (IPA: [ˈdelpo]), jẹ́ agbá tẹ́nìs ará Argentina tó wà ní ipò No. 122 lágbàyé ní tẹ́nìs àwọn ọkùnrin ẹnìkan Association of Tennis Professionals (ATP).[4][5]
Del Potro at the 2016 Wimbledon Championships | ||||||||||||||
Orílẹ̀-èdè | Argentina | |||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Ibùgbé | Tandil, Argentina | |||||||||||||
Ọjọ́ìbí | 23 Oṣù Kẹ̀sán 1988 Tandil, Argentina | |||||||||||||
Ìga | 1.98 m (6 ft 6 in) | |||||||||||||
Ìgbà tódi oníwọ̀fà | 2005 | |||||||||||||
Ọwọ́ ìgbáyò | Right-handed (two-handed backhand) | |||||||||||||
Olùkọ́ni | Sebastián Prieto | |||||||||||||
Ẹ̀bùn owó | US$ 25,889,586 [1] | |||||||||||||
Ẹnìkan | ||||||||||||||
Iye ìdíje | 439–173 (71.73% in ATP Tour and Grand Slam main draw matches, and in Davis Cup) | |||||||||||||
Iye ife-ẹ̀yẹ | 22 | |||||||||||||
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 3 (13 August 2018) | |||||||||||||
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 120 (6 January 2020)[2] | |||||||||||||
Grand Slam Singles results | ||||||||||||||
Open Austrálíà | QF (2009, 2012) | |||||||||||||
Open Fránsì | SF (2009, 2018) | |||||||||||||
Wimbledon | SF (2013) | |||||||||||||
Open Amẹ́ríkà | W (2009) | |||||||||||||
Àwọn ìdíje míràn | ||||||||||||||
Ìdíje ATP | F (2009) | |||||||||||||
Ìdíje Òlímpíkì | F (2016) | |||||||||||||
Ẹniméjì | ||||||||||||||
Iye ìdíje | 41–44 (48.24% in ATP Tour and Grand Slam main draw matches, and in Davis Cup) | |||||||||||||
Iye ife-ẹ̀yẹ | 1 | |||||||||||||
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 105 (25 May 2009) | |||||||||||||
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 443 (13 January 2020) | |||||||||||||
Grand Slam Doubles results | ||||||||||||||
Open Fránsì | 1R (2006, 2007) | |||||||||||||
Wimbledon | 1R (2007, 2008) | |||||||||||||
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò | ||||||||||||||
Davis Cup | W (2016) | |||||||||||||
Iye ẹ̀ṣọ́
| ||||||||||||||
Last updated on: Àdàkọ:Date. |
Àṣeyọrí rẹ̀ tó tọ́bi jùlọ ṣẹlẹ̀ nígbà tó gba ife-ẹ̀yẹ Open Amẹ́ríkà 2009 nígbà tó borí Rafael Nadal ní semifinal àti Roger Federer ní final. Òhun ni ẹni àkọ́kọ́ tó borí Federer àti Nadal nínú ìdíje grand slam kannáà àti ẹnìkan soso lẹ́yìn àwọn tí a mọ̀ sí Big Four (Roger Federer, Rafael Nadal, Novak Djokovic àti Andy Murray), tọ́ gba ife-ẹ̀yẹ grand slam láàrin Open Fránsì 2005 àti Open Amẹ́ríkà 2013. Òhun náà tún ni ará Argentina kejì tó gba ife-ẹ̀yẹ Open Amẹ́ríkà nígbà Open Era.[6]
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "ATP Prize Money Leaders" (PDF).
- ↑ ATP Rankings
- ↑ "The pronunciation by Juan Martín del Potro himself". ATP World Tour. Retrieved 22 October 2017.
- ↑ "Juan Martin del Potro – Overview – ATP World Tour – Tennis".
- ↑ "Rankings | Singles | ATP World Tour | Tennis" (in en). ATP World Tour. http://www.atpworldtour.com/en/rankings/singles.
- ↑ ATP Staff (14 September 2009). "Del Potro stuns Federer to win title". ATP World Tour. Retrieved 4 October 2009.