Tsad
Chad (Faransé: Tchad, Lárúbáwá: تشاد Tshād), fun ibise gege bi orile-ede Olominira ile Chad, je orile-ede tileyika ni arin Afrika. O ni bode pelu Libya ni ariwa, Sudan ni ilaorun, orile-ede Arin Afrika Olominira ni guusu, Kameroon ati Naijiria si guusuiwoorun, ati Nijer si iwoorun. Nitori ijinna re si okun ati asale to gbabe ka, Tsad je mimo bi "Okan Kiku Afrika" ("Dead Heart of Africa").
Republic of Chad | |
---|---|
Orin ìyìn: "[La Tchadienne] error: {{lang}}: text has italic markup (help)" | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | N'Djamena |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | French, Arabic |
Orúkọ aráàlú | Chadian |
Ìjọba | Republic |
Mahamat Idriss Déby Itno (محمود بن إدريس ديبي إتنو) | |
Succès Masra (سوكسيه ماسرا) | |
Independence | |
• from France | August 11, 1960 |
Ìtóbi | |
• Total | 1,284,000 km2 (496,000 sq mi) (21st) |
• Omi (%) | 1.9 |
Alábùgbé | |
• 2009 estimate | 10,329,208[1] (74th) |
• 1993 census | 6,279,921 |
• Ìdìmọ́ra | 8.0/km2 (20.7/sq mi) (212th) |
GDP (PPP) | 2009 estimate |
• Total | $16.074 billion[2] |
• Per capita | $1,611[2] |
GDP (nominal) | 2009 estimate |
• Total | $6.854 billion[2] |
• Per capita | $687[2] |
HDI (2007) | ▲ 0.392 Error: Invalid HDI value · 175th |
Owóníná | CFA franc (XAF) |
Ibi àkókò | UTC+1 (WAT) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+1 (not observed) |
Àmì tẹlifóònù | 235 |
ISO 3166 code | TD |
Internet TLD | .td |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
- ↑ Central Intelligence Agency (2009). "Chad". The World Factbook. Archived from the original on April 24, 2020. Retrieved January 28, 2010.
- ↑ 2.0 2.1 2.2 2.3 "Chad". International Monetary Fund. Retrieved 2010-04-21.