Arinzo
Arinzo jẹ́ fíìmù Nàìjíríà tí a ṣe ní ọdún 2013, láti ọwọ́ Iyabo Ojo. Wọ́n ṣàfihàn àwọn òṣèré láti orílẹ̀-èdè Ghana àti Nàìjíríà nínú fíìmù yìí. Orílẹ̀-èdè Ghana àti Nàìjíríà bákan náà ni wọ́n ti ya fíìmù náà.[1]
Arinzo | |
---|---|
Olùgbékalẹ̀ | Iyabo Ojo |
Déètì àgbéjáde | 2013 |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | Yoruba |
Ìsọníṣókí
àtúnṣeFíìmù náà dá lórí àwọn ọmọbìnrin méjì tó jẹ́ ọmọ ìyá kan náà tí ìbáṣepọ̀ wọn ò dán mọ́rán nítorí ọ̀kan jẹ́ ọlọ́pàá, tí èkejì sì jẹ́ adigunjalè. Nínú eré náà, àwọn ọmọbìnrin méjèèjì di ọ̀tá ara wọn nítorí ìhà tí oníkálùkùú jọ kọ sí ayé.[1]
Àwọn akópa
àtúnṣe- Vivienne Achor
- Blankson
- Ekson Smith Asante
- Anthar Laniyan
- Femi Branch
- Yinka Quadri
- Muka Ray
- Ayo Mogaji
- Bukky Wright
- Doris Simeon
- Iyabo Ojo[2][3]
Àmì-ẹ̀yẹ
àtúnṣeWọ́n yan Iyabo Ojo fún àmì-ẹ̀yẹ YMAA gẹ́gẹ́ bí i olú ẹ̀dá-ìtàn.[4][5]
Tún wo
àtúnṣeÀwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Nollywood Tangos: Iyabo Ojo Vs Laide Bakare". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-02-06. Retrieved 2022-07-29.
- ↑ "Actress Iyabo Ojo steps up, moves into palatial residence". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-08-15. Archived from the original on 2022-07-29. Retrieved 2022-07-29.
- ↑ Orenuga, Adenike (2014-01-24). "Iyabo Ojo set to drop estranged husband's name". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-29.
- ↑ "Dailytrust News, Sports and Business, Politics | Dailytrust". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-29.
- ↑ Ayobami, Abimbola (2013-05-27). "Top Yoruba actors' battle to win at the Yoruba Movie Academy Awards". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-29.