Chizzy Alichi
Chigozie Stephanie Alichi (tí a bí ní ọjọ 23 Oṣù kejìlá ọdún 1993), tí a mọ̀ ní Chizzy Alichi, jẹ́ òṣèré fiimu tí Ìlu Nàìjíríà.
Chizzy Alichi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Chigozie Stephanie Alichi 23 Oṣù Kejìlá 1993[1] Enugu |
Orílẹ̀-èdè | Naijiria |
Iṣẹ́ | Osere fiimu/ Awose |
Ìgbà iṣẹ́ | 2010–lowolowo |
Website | chizzyalichi.com |
Ìgbé ayé rẹ̀
àtúnṣeChizzy Alichi wá láti Ezza Nkwubor Nike ní Enugu East, ìjọba agbègbè kan Nàìjíríà. Enugu, Nàìjíríà. Àbìkẹ́hìn ló jẹ́ nínú àwọn méjì tí òbí rẹ́ bí. Ìròyìn rẹ̀ kàn jákèjádò nígbà tí ó kọ́ ilé ńlá fún àwọn òbí rẹ̀ ní ọdún 2017.[2][3][4][5][6] Ó ń gbé ní Asaba, Ìpínlẹ̀ Delta.[7]
Iṣẹ̀ rẹ̀
àtúnṣeÓ darapọ̀ mọ́ Nollywood ní ọdún 2010 láìrò tẹ́lẹ̀ . Ó darapọ̀ mọ́ Actors Guild of Nigeria. Ó tọrọ fún ààyè láti kópa nínú fíìmù kan, wọ́n sì ṣe àfihàn rẹ̀ nígbà àkọ́kọ́ gẹ́gẹ́ bí òṣèré nínú fíìmù Magic Money tí Mercy Johnson àti Bob-Manuel Udokwu náà kópa nínu rẹ̀.
Ìṣẹ̀lẹ̀ gbòógì tó ni ipa rere nìdíí iṣẹ́ rẹ̀ ni eré Akaraoku, tó túmọ̀ sí *àkàrà gbígbóná", ní 2016. Yul Edochie ló darí rẹ̀. Ìwé ìpolówó rẹ̀ ló gbalẹ̀ kan lórí ìkànnì ìbánidọ́rẹ̀ẹ́ káàkiri tí àwọn èèyàn fi lérò wí pé alákàrà ni lóòótọ́. Èyí fún ní àǹfààní láti kópa nínú àwọn eré mìíràn sí ní ọdún 2017.
̀ ni eré Akaraoku, tó túmọ̀ sí *àkàrà gbígbóná", ní 2016. Yul Edochie ló darí rẹ̀. Ìwé ìpolówó rẹ̀ ló gbalẹ̀ kan lórí ìkànnì ìbánidọ́rẹ̀ẹ́ káàkiri tí àwọn èèyàn fi lérò wí pé alákàrà ni lóòótọ́. Èyí fún ní àǹfààní láti kópa nínú àwọn eré mìíràn sí ní ọdún 2017.
Àwọn ìfarahàn rẹ̀ nínu orin
àtúnṣeỌduń | Orin | Akọrin | Àfikún |
---|---|---|---|
2016 | "Mmege[10][11] | Flavour N'abania |
Àwọn ẹ̀bùn
àtúnṣeỌdún | Ẹ̀bùn | Ẹ̀ka | Àbájáde | Àfikún |
---|---|---|---|---|
2017 | City People Entertainment Awards".[12] | Oṣere Tuntun Ti Odun Ti o dara julọ (Gẹẹsi) | Wọ́n pèé | |
Nigeria Achievers Award.[13] | Oṣere ti o ni atẹle | Gbàá |
Àwọn àsàyàn eré rẹ̀
àtúnṣeỌdún | Fiimu | Ipa | Àfikún |
---|---|---|---|
2018 | Do Good Nwakpaka | Pẹ̀lu kíkópa Ebele Okaro | |
My Story | |||
Power of Madness | Pẹ̀lu kíkópa Nonso Diobi,Ngozi Ezeonu | ||
2017 | Point & Kill | Pẹ̀lu kíkópa Nonso Diobi | |
Tears of Victory | Pẹ̀lu kíkópa Yul Edochie | ||
Power in The palace | Pẹ̀lu kíkópa Chioma Chukwuka | ||
Obudu The Evil Shrine | Pẹ̀lu kíkópa Ebele Okaro | ||
Teckno In The Village | |||
Little Oath | Pẹ̀lu kíkópa Chiwetalu Agu,Ken Erics | ||
Beautiful Mmege | Pẹ̀lu kíkópa Ebele Okaro | ||
The King's Wealth | Pẹ̀lu kíkópa Clem Ohameze | ||
Teri Teri | Pẹ̀lu kíkópa Rachael Okonkwo | ||
Virgin Justice | Pẹ̀lu kíkópa Regina Daniels | ||
Fada Fada | Pẹ̀lu kíkópa Yul Edochie | ||
Financial Woman | Pẹ̀lu kíkópa Yul Edochie | ||
Ajebo America | Pẹ̀lu kíkópaKen Erics,Nonso Diobi | ||
2016 | Akaraoku | Akara Oku | Pẹ̀lu kíkópaYul Edochie |
2015 | Vanity | Pẹ̀lu kíkópaNgozi Ezeonu | |
Attitude | Joan | ||
2014 | Idemmili | Pẹ̀lu kíkópa Pete Edochie,Patience Ozokwor,Yul Edochie | |
The Motherless | Pẹ̀lu kíkópa Ini Edo | ||
Old Soldier | Pẹ̀lu kíkópa Nkem Owoh,Osita Iheme,Chinedu Ikedieze,Ime Bishop Umoh | ||
The Three Blind | Pẹ̀lu kíkópa Chika Ike | ||
2013 | Cry of a Witch | Ifeoma | |
2011 | Double Barrel | Pẹ̀lu kíkópa Francis Odega,Amaechi Muonagor | |
Sherikoko | Pẹ̀lu kíkópa John Okafor,Funke Akindele | ||
2010 | Forgive Me Father | Pẹ̀lu kíkópa Nkem Owoh,Osita Iheme | |
Magic Money | Pẹ̀lu kíkópa Mercy Johnson, Bob-Manuel Udokwu |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Upcoming Nollywood actress releases photos to mark birthday". Pulse. Archived from the original on 19 March 2018. Retrieved 18 March 2018.
- ↑ "CHIZZY ALICHI: Why I don’t kiss just anybody on set". The Nation. Retrieved 18 March 2018.
- ↑ "Nollywood Actress, Chizzy Alichi Builds House For Her Parents". Naija News. Retrieved 18 March 2018.
- ↑ "Nollywood Actress, Chizzy Alichi Builds A House For Her Parents (Photos)". Naijaloaded. Archived from the original on 19 March 2018. Retrieved 18 March 2018.
- ↑ "Nollywood actress chizzy Alichi builds a mansion for her parents". Naij. Retrieved 18 March 2018.
- ↑ "Meet Nollywood Actress who Does not Wear Expensive Clothes". Modern Ghana. Retrieved 18 March 2018.
- ↑ "I’m praying for a man –Chizzy Alichi, actress". The Sun. Retrieved 18 March 2018.
- ↑ "Chizzy Alichi: How Kenneth Okonkwo saved my life on set of my first movie". Naija Gists. Retrieved 18 March 2018.
- ↑ "CHIZZY ALICHI: ‘Why I’m still single". The Nation. Retrieved 18 March 2018.
- ↑ "Flavour features pretty actress in new video". Naij. Archived from the original on 6 August 2018. Retrieved 18 March 2018.
- ↑ "Beautiful Nollywood Actress, Chizzy Alichi Featured In Flavour’s "Mmege" Video". The Info NG. Archived from the original on 15 August 2018. Retrieved 18 March 2018.
- ↑ "List Of Winners At The 2017 City People Movie Awards". Concise News. Archived from the original on 19 March 2018. Retrieved 17 March 2018.
- ↑ "NIGERIA ACHIEVERS AWARDS 2017 NOMINEES LIST". Concise News. Retrieved 17 March 2018.
Àwọn ìtakùn Ìjásóde
àtúnṣe- Chizzy Alichi official website Archived 2020-11-03 at the Wayback Machine.