Darlington Nwokocha

Olóṣèlú Nàìjíríà

Darlington Nwokocha jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó jẹ́ asójú agbègbè Abia Central federal láti ọdún 2023.[1] Kí ó tó di Sénátọ̀, ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Ilé ìgbìmò asofin kékeré tí ó sójú Isiala-Ngwa North/Isiala-Ngwa South láàrin 2015 sí 2019. Nwokocha jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Abia State House of Assembly láàrin 2007 sí 2015.[2]


Darlington Nwokocha
Sénátọ̀ tí ó ń sójú Abia Central
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
29 May 2023
ÀàrẹBola Tinubu
GómìnàAlex Otti
Vice PresidentKashim Shettima
AsíwájúTheodore Orji
Arọ́pòGinger Onwusibe
Ọmọ ẹgbẹ́ House of Representatives for Isiala Ngwa North/Isiala-Ngwa South
In office
29 May 2015 – 29 May 2023
ÀàrẹMuhammadu Buhari
GómìnàOkezie Ikpeazu
Vice PresidentYemi Osinbajo
Ọmọ ẹgbẹ́ Abia State House of Assembly for Isiala Ngwa North
In office
29 May 2007 – 29 May 2015
ÀàrẹUmaru Musa Yar'Adua
GómìnàTheodore Orji
Vice PresidentGoodluck Jonathan
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíÀsìṣe ìgbéọ̀rọ̀sílẹ̀: Àìdámọ̀ àmì ìdádúró-ọ̀rọ̀ sókí "{". 16 August 1967 (16 August 1967-{{{month}}}-{{{day}}}) (ọmọ ọdún Àsìṣe ìgbéọ̀rọ̀sílẹ̀: Àìdámọ̀ ọ̀rọ̀ "august".)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúLabour Party
Other political
affiliations
People's Democratic Party (2017—2023)

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Silas, Don (27 February 2023). "Election result: INEC declares LP's Nwokocha winner of Abia Central Senatorial seat". Daily Post. Retrieved 2 April 2023. 
  2. "Hon. Darlington Nwokocha | Isiala Ngwa North/South Federal Constituency". National Assembly. Retrieved 2 April 2023.