Oníṣe:Demmy/Sandbox/layout2
Ẹ kú àbọ̀ si ojú-ewé Íntánẹ́tì ti Wikipéédíà ni èdè Yorùbá!Wikipẹ́ẹ́díà jẹ́ isẹ́ aláfọwọ́sowọ́pọ̀ lati se ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ èdè. Nínú ti èdè Yorùbá yìí, a ní 34,725 àyọkà. |
Ninu imo mathematiki, nomba gidi (real number) ni a mo si awon nomba ti a le kole gege bi nombamewa (decimal) ti ko lopin. Fun apere 2.4871773339…. Awon nomba gidi je nomba onipin, nomba bi 42 ati −23/129, ati nomba alainiipin, nomba bi π ati gbòngbò alagbarameji 2 (square root) ti won si se fihan gege bi ojuami (point) ni ori ila nomba to gun ni ailopin. A n pe awon nomba gidi be lati le seyato si awon nọ́mbà tósòro (complex number). Ni aye atijo awon onimo isiro mo nomba tosoro gege be nomba tikosi (imaginary number). Nomba gidi le je onipin tabi alainipin; o le je nomba aljebra tabi nomba tikonionka (transcendental number); be si ni won le wa ni apaotun, ni apaosi tabi ki won o je odo. A n fi nomba gidi se iwon awon opoiye to je wiwapapo (continuous). O se se ka fi won han gege bi nombamewa to ni itelentele (sequence) eyonomba (digit) ti ko lopin lapa otun ojuami nombamewa (decimal point); a le fi won han bayi 324.823211247…. Awon ami bintin meta to wa leyin nomba yi tumosi pe awon eyonomba miran si n bo leyin. Àwòrán Ọjọ́ Òní Àdàkọ:POTD/2024-12-27 |