Onje yoruba
Oùnjẹ wíwá Yorùbá jẹ oúnjẹ ti o pọju ti ó sì ní onírúurú tí i ṣe ti àwọn eniyan ilẹ̀ Yorùbá(àwọn agbègbè Yorùbá ní Nigeria). Lára àwọn oúnjẹ ìlúmọ̀ọ́ká Yorùbá nì wọ̀n yìí; Ọ̀fadà, Àsáró, Mọ́í Mọ́ì, Ọbẹ̀ Ẹ̀̀gúsí , Àbùlà, Àkàrà, Ilá Alásèpọ̀, Ẹ̀fọ́ rírò pẹ̀lú Òkèlè, abbl.
Díẹ̀ nínù àwọn oúnjẹ Yorùbá:
- 1. Àkàrà
- 2. Àsun
- 3. Ọ̀fadà
- 4. Àbùlà
- 5. Àsáró
- 6. Èkuru/Ofúlójú
- 7. Ekusu/Ṣapala
- 8. Ẹ̀fọ́ rírò
- 9. Bọ̀ọ̀lì
- 10. Gízídòdò
- 11. Ìkọ́kọrẹ́/Ìfọ́kọrẹ́
- 12. Àdàlù
- 13. Mọ́í-mọ́í/Ọ̀lẹ̀lẹ̀
- 14. Ìrẹsì Ẹyin
- 15 . Ìrẹsì àti ọbẹ̀ ata díndín
- 16. Ayamase
- 17. Ẹ̀wàgọ̀yìn
- 18. Ewédú
- 19. Ṣọkọ
- 20. Òkèlè (Iyán, Ẹ̀bà, Láfún, Àmàlà/Ọkà, Fùfú, Púpúrúetc.)
- 21. Ilà alásèpọ̀
- 22. Dòdò-Ìkirè
- 23 Ègbo àti Ẹ̀wà
- 24. Gúre ọlọ́bọ̀rọ́
- 25. Kókóró
- 26. Gúgúrú àti ẹ̀pà
- 27. Àádùn
- 28. Mósò
- 29. Jọ̀lọ́fù
- 30. Ẹ̀gúsí
- 31. Ìpékeré
- 32. Dùn Dún Oníyẹ̀rì
- 33. Wàrà
- 34. Ẹ̀fọ́ Tẹ̀tẹ̀
- 35. Sisí pẹlẹbẹ
- 36. Ìrẹsì díndín)
- 37. Bàbá dúdú
- 38. Ọbẹ̀ irú
- 39. Dòdò
- 40. Ẹ̀kọ
- 41. Ògì
- 42. Àpọ̀n
- 43. Ẹ̀gúsí Ìjẹ̀bú
- 44. Gurundi
- 45. Búrẹ́dì Agége
- 46. Ìrẹsì alágbọn
- 47. Gúre
- 48. Ọbẹ̀ ẹja díndín
- 49. Márúgbó àti púpùrú
- 50. Èbìrìpò
- 51. Iṣu àti ẹyin
- 52. Dùndún
- 53. Ọbẹ̀ ata Búkà
- 54. Sùpàgẹ́tì oní jọ̀lọ́fù
- 55. Àgbàdo sísun
- 56. Ìgbín díndín
- 57. Zóbò
- 58. Ògi bàbà
- 59. Gbẹ̀gìrì
- 60. Róbó
- 61. Ẹmu
- 62. Ilá àti ọbẹ̀ díndín
- 63. Gàrrí
- 64. Ọ̀gbọ̀lọ̀/oro
- 65. Iṣu àti ọbẹ̀ díndín
- 66. Amẹ́yidùn
- 67. pọfu pọfu
- 68. Ṣápùmáànì
- 69. Bọ́ùnsì
- 70. Àgbàdo àti àgbọn
- 71. Ẹyin Awó
- 72. Mọ́ímoí elépo
- 73. Àkàrà elépo
- 74. Iṣu sísun
- 75. Àkàrà Ẹ̀gùdí
- 76. Ọkà bàbà
- 77. Tìnkó
- 78. Esunsun
- 79. Èékánná Gowon
- 80. Ewédú Ẹ̀lẹ́gúsí
- 81. Ẹ̀wà Pakure
- 82. Ẹ̀fọ́ Ẹlẹ́gúsí
- 83. Báléwá
- 84. Búgan
- 85. Alàpà / Jogi
- 86. Ìṣápá
- 87. Kundi
- 88. Ọ̀jọ̀jọ̀
- 89. Bẹ́síkẹ́ / Wàrà
- 90. Àbàrí
- 91. Páfun
- 92. Ilá àti ọbẹ̀ ata
- 93. Pọfu pọfu
- 94. Ìgbín pẹ̀lú Ọbẹ̀ ata
- 95. Ànọ̀mọ́/Ọ̀dùnkún
- 96. Obẹ̀ Ọ̀fadà
- 97. Ọbẹ̀ Adìyẹ
- 98. Ìlasà
- 99. Àkàrà Kèngbè
- 98. Àkàrà Kókò
- 99. súrú
- 100. Ẹ̀kọ Eléwé
- 101. Jálókè/jáálòkè
- 102. Lápata / Ìpékeré
- 103. Ọbẹ̀ ilá funfun
- 104. Àbùlà
- 105. Luru
- 106. Ọ̀runlá
- 107. Ìmóóyò
- 108. Ẹ̀fọ́( Ṣọkọ, gbagba, Ebòlò, Yanrin, Odu, Wọ́rọ́wọ́, Tẹ̀tẹ̀, Gúre, Ajẹ́fáwo, Ìyànà-Ìpájà)
- 109. Mọ́í Mọ́í Ẹlẹ́mí Méjì
- 110. Yọyọ
- 111. Ọbẹ̀ Ẹyin