Svetlana Kuznetsova
Svetlana Aleksandrovna Kuznetsova ([ Светла́на Алекса́ндровна Кузнецо́ва (ìrànwọ́·ìkéde)] error: {{lang}}: text has italic markup (help)); ojoibi 27 June 1985) jẹ́ agbá bọọ́ọ̀lù ẹlẹẹ́yin orí ọ̀dàntenis ọmó iklẹ̀ Rọ́síà tó gba ife-ẹ̀yẹ Grand Slam Open Amẹ́ríkà àti Open Fránsì.
Kuznetsova at the 2009 US Open | |
Orílẹ̀-èdè | Rọ́síà |
---|---|
Ibùgbé | Saint Petersburg, Russia |
Ọjọ́ìbí | 27 Oṣù Kẹfà 1985 Leningrad, Russian SFSR, Soviet Union |
Ìga | 1.74 m (5 ft 81⁄2 in) |
Ìgbà tódi oníwọ̀fà | 2000 |
Ọwọ́ ìgbáyò | Right-handed (two-handed backhand) |
Ẹ̀bùn owó | $16,524,126 |
Ẹnìkan | |
Iye ìdíje | 463–212 |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 13 WTA, 1 ITF |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 2 (10 September 2007) |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 64 (15 October 2012)[1] |
Grand Slam Singles results | |
Open Austrálíà | QF (2005, 2009) |
Open Fránsì | W (2009) |
Wimbledon | QF (2003, 2005, 2007) |
Open Amẹ́ríkà | W (2004) |
Àwọn ìdíje míràn | |
Ìdíje WTA | RR (2004, 2006, 2007, 2008, 2009) |
Ìdíje Òlímpíkì | QF (2004) |
Ẹniméjì | |
Iye ìdíje | 216–91 |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 15 WTA |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 3 (7 June 2004) |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 40 (15 October 2012) |
Grand Slam Doubles results | |
Open Austrálíà | W (2005, 2012) |
Open Fránsì | F (2004) |
Wimbledon | F (2005) |
Open Amẹ́ríkà | F (2003, 2004) |
Àwọn ìdíje Ẹniméjì míràn | |
Ìdíje WTA | SF (2003, 2004) |
Ìdíje Òlímpíkì | QF (2008) |
Grand Slam Mixed Doubles results | |
Open Austrálíà | 1R (2003) |
Open Fránsì | 2R (2003) |
Wimbledon | QF (2003) |
Last updated on: 15 October 2012. |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "WTA Singles Rankings". WTA. Retrieved 12 September 2011.