The Return of Jenifa
The Return of Jenifa jẹ́ fíìmù apanilẹ́rìn-ín ilẹ̀ Nàìjíríà ti ọdún 2011.[2] Funke Akindele ló ṣagbátẹrù fíìmù yìí, tó sì tún jẹ́ olú-ẹ̀dá-ìtàn nínú fíìmù yìí. Fíìmul yìí jẹ́ apá kẹta, tó tẹ̀lé Jenifa (2008). Olùdarí fíìmù yìí ni Muhydeen Ayinde.[3]
The Return of Jenifa | |
---|---|
Adarí | Muhydeen Ayinde |
Olùgbékalẹ̀ | Funke Akindele |
Òǹkọ̀wé | Funke Akindele |
Àwọn òṣèré | Funke Akindele Denrele Edun Rukky Sanda Yinka Quadri Helen Paul Ireti Osayemi Mercy Aigbe Eldee Ronke Ojo Antar Laniyan Tope Adebayo |
Ìyàwòrán sinimá | D.J. Tee |
Olùpín | Olasco Films and Records |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 172 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | Yoruba, English |
Àwọn akópa
àtúnṣeÀwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Funke Akindele returns with Jenifa'". 15 July 2011. Retrieved 8 June 2020.
- ↑ "FUNKE AKINDELE RETURNS IN SEPTEMBER WITH 'THE RETURN OF JENIFA'".
- ↑ adefaye (2011-10-20). "Return of Jenifa grosses N10m in 7days" (in en-GB). Vanguard News. https://www.vanguardngr.com/2011/10/return-of-jenifa-grosses-n10m-in-7days/amp/.
- ↑ The Return of Jenifa hits Nigerian cinemas in August 2011