Wikipedia:Ìsàmì Ọgọ́ta ọdún Òmìnira ilẹ̀ Nàìjíríà
Ìsàmì Ọgọ́ta ọdún Òmìnira ilẹ̀ Nàìjíríà ni iṣẹ́ àkànṣe kan tí àjọ Yorùbá Wikimedians tí wọ́n jẹ́ olùgbéga ati olùpolongo nípa àṣà , ẹ̀sin, ìṣe àti ẹwà èdè Yorùbá jákè-jádò àgbáyé pátá gbé kalẹ̀ láti fi bá ilẹ̀ abínibí baba wọn dáwọ̀ọ́ ìdùnú lórí pípé ọgọ́ta ọdún tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti gba òmìnira kúrò lọ́wọ́ ìjọba amúnisin Gẹ̀ẹ́sì.
Èróngbà
àtúnṣeÈrò wọn ni láti ṣe àtúnṣe tí ó tọ́ ati tí ó yẹ sí àwọn akòrí àyọkà tí ó ṣe pàtàkì nínú ìtàn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Lára àwọn àtúnṣe bẹ́ẹ̀ ni dídá àwọn àyọkà tuntun tí kò tíì sí ní orí Wikipedia Yorùbá tẹ́lẹ̀. Síṣàfikún àwọn àyọkà tí wọn kò kún ojú òṣùwọ̀n tó, yálà nípa fífi ìtọ́kasí kún wọn ni tàbí ṣíse àfikún amì orí ọ̀rọ̀ ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Àsìkò tí yóò wáyé
àtúnṣeIṣẹ́ àkànṣe yí ni yóò bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kejì sí ọjọ́ Kẹsàán oṣù Kẹwàá ọdún 2020.
Àwọn Olùkópa
àtúnṣeFi orúkọ sílẹ̀ níbí láti kópa. Kọ Orúkọ ní kíkún, kí o sì kọ Orúkọ Oníṣẹ́ siwájú rẹ̀.
- Mikaeel Sodiq Adesina Agbalagba (ọ̀rọ̀) 10:05, 4 Oṣù Kẹ̀wá 2020 (UTC)
- Eiseke Bolaji (Jesu-loba)
- Babalola Najim Akorede (korebabs)
- Sowole Adeniyi Oluwatoyin (Sowoletoyin)
- Adefanike (ọ̀rọ̀) 21:38, 2 Oṣù Kẹ̀wá 2020 (UTC)
- Dansu Peter 10:11, 4 Oṣù Kẹ̀wá 2020 (UTC)
Àwọn Àkòrí tí a fẹ́ siṣẹ́ lé lórí
àtúnṣe- Nàìjíríà
- Frederick Lugard
- Flora Shaw
- Àwọn ènìyàn dúdú
- IMF
- Ìtàn ilẹ̀ Nàìjíríà
- Kánò
- Kàstínà
- Usman dan Fodio
- Àwọn Fúlàní
- Ilẹ̀ Kálìfù Sókótó
- Ìran Yorùbá
- Ilé-Ifẹ̀
- Ilẹ̀ Ọba Ńri
- Òwò Ẹrú ní ilẹ̀ Nàìjíríà
- Èkó
- Ilẹ̀ ọbalúayé Brítánìì
- Ilé-iṣẹ́ Royal Niger
- Ọjọ́ ìgbòmìnira orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
- Ẹgbẹ́ Òṣèlú Nigerian People's Congress
- Ẹgbẹ́ Òṣèlú National Council of Nigeria and the Cameroons
- Nnamdi Azikiwe
- Abúbakar Tafawa Balewa
- Igba Oselu Akoko ile Nàìjíríà
- Action Group
- Ìbò
- Ẹgbẹ́ ọmọ.Odùduwà
- Samuel Ládòkè Akíntọlá
- Anthony Enahoro
- Ìgba Òṣèlú Àkọ́kọ́ Nàìjíríà
- Jaja Wachuku
- Samuel Akínsànyà
- Earnest Ikoli
- Akinọlá Maja
- Chris Ògúnbanjọ
- Yakubu Gowon
- Odumegwu Ojukwu
- Ẹgbẹ́ Òṣèlú Ìmọ́lẹ̀
- Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀
- Oko-ẹrú
- Àmọ́dù Béllò
- Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà
- Aguiyi Ironsi
- Odò Benue
- Odò Niger
- Ìbàdàn
- Olúìlú
- Ọ̀yọ́ Ilé
- Lágelú
- Ìjẹ̀bú
- Paris Club
- Iṣẹ́ Àgbẹ̀
- Àwọn ẹ̀yà Núpé
- Abdulsalami Abubakar
- Ernest Shonekan
- Julius Kòṣébínú Agbájé
- Olúyẹmí Adéníji
- Kòfó Ayọ̀bámi
- Adéyínká Oyèkàn
- Razak Oláyíwọlá Òjòpagogo