Èyí ni Àtòjọ Àwọn Orílẹ̀-èdè Àfíríkà Nípa Bí Wọ́n Ṣe Pọ̀ Tó Níye, a kọ èyí sílẹ̀ nípa lílo ìwòye iye ènìyàn tí ó wà lórílẹ̀ èdè kọ̀ọ̀kan pẹ̀lú Ìtọ́kasí ètò ìkànìyàn tí wọ́n ṣe lẹ́yìn lórílẹ̀ èdè kọ̀ọ̀kan. Láìsí àní-àní, ilẹ̀ Áfíríkà ṣì ní ilẹ̀ tí ó ń dàgbà jùlọ níye ènìyàn ní gbogbo àgbáyé lẹ́yìn ilẹ̀ Asia. [1] Ìdá ọgọ́ta (60%) àwọn ènìyàn Áfíríkà ní wọ́n wà ní ọmọ ọjọ́ orí mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n tàbí kéré sí iye ọjọ́ orí yẹn sí ọjọ́ orí wọn,[2] èyí wá mú kí ṣíṣe àtẹ ìdàgbàsókè iye ènìyàn tí ó wà lórílẹ̀ èdè kọ̀ọ̀kan dá lé bí ètò ìṣèjọba àti ìdàgbàsókè ètò ọ̀rọ̀-ajé ṣe ṣe pàtàkì tó.
Rank
|
Country (or dependent territory)
|
Official figure (where available)
|
Date of last figure
|
Source
|
1 |
Nàìjíríà |
200,963,599 |
2019 |
Worldometers[3]
|
2 |
Ethiopia |
112,078,730 |
2019 |
Worldometers
|
3 |
Egypt |
99,919,467 |
January 25, 2020 |
Official population clock
|
4 |
Democratic Republic of the Congo
|
86,026,000 |
July 1, 2019 |
Official estimate
|
5 |
Gúúsù Áfríkà |
58,775,022 |
July 1, 2019 |
Official estimate
|
6 |
Tanzania |
51,046,000 |
2015 |
Official estimate
|
7 |
Kenya |
47,564,296 |
2019 |
Official estimate
|
8 |
Algeria |
43,000,000 |
January 1, 2019 |
Official estimate
|
9 |
Àdàkọ:SDN |
42,268,269 |
January 25, 2020 |
Official population clock Archived 2020-05-11 at the Wayback Machine.
|
10 |
Àdàkọ:MAR |
35,795,289 |
January 25, 2020 |
Official population clock Archived 2021-05-13 at the Wayback Machine.
|
11 |
Àdàkọ:UGA |
34,634,650 |
August 28, 2014 |
Official estimate
|
12 |
Àdàkọ:MOZ |
28,013,000 |
2015 |
Official estimate
|
13 |
Ghana |
27,043,093 |
2014 |
Official estimate
|
14 |
Àdàkọ:ANG |
24,383,301 |
May 16, 2014 |
Preliminary 2014 census result
|
15 |
Côte d'Ivoire |
22,671,331 |
May 15, 2014 |
Preliminary 2014 census result
|
16 |
Àdàkọ:MDG |
22,434,363 |
2014 |
Official estimate
|
17 |
Cameroon |
21,917,602 |
2015 |
Official estimate Archived 2018-05-17 at the Wayback Machine.
|
18 |
Niger |
17,138,707 |
December 10, 2012 |
Final 2012 census result
|
19 |
Bùrkínà Fasò |
18,450,494 |
2015 |
Official estimate
|
20 |
Mali |
14,528,662 |
April 1, 2009 |
Final 2009 census result
|
21 |
Màláwì |
16,832,900 |
July 1, 2016 |
Official estimate
|
22 |
Àdàkọ:ZAM |
15,473,905 |
2015 |
Official estimate
|
23 |
Somalia |
12,316,895 |
January 1, 2016 |
Official estimate
|
24 |
Àdàkọ:SEN |
14,354,690 |
2015 |
Official estimate
|
25 |
Chad |
11,039,873 |
May 20, 2009 |
Final 2009 census result
|
26 |
Àdàkọ:ZIM |
13,061,239 |
August 17, 2012 |
Final 2012 census result
|
27 |
Àdàkọ:RWA |
10,515,973 |
August 15, 2012 |
Final 2012 census result
|
28 |
Tunisia |
10,982,754 |
April 23, 2014 |
Preliminary 2014 census result
|
29 |
Guinea |
10,628,972 |
April 2, 2014 |
Preliminary 2014 census result Archived 2012-07-12 at the Wayback Machine.
|
30 |
Benin |
10,008,749 |
May 11, 2013 |
Final 2013 census result
|
31 |
Burundi |
9,823,828 |
2015 |
Official estimate Archived 2019-04-03 at the Wayback Machine.
|
32 |
Àdàkọ:SSD |
8,260,490 |
April 22, 2008 |
2008 census result
|
33 |
Togo |
6,191,155 |
November 6, 2010 |
Final 2010 census result
|
34 |
Ẹritrẹ́à |
6,536,000 |
July 1, 2014 |
Official estimate
|
35 |
Àdàkọ:SLE |
6,348,350 |
2014 |
Official estimate
|
36 |
Àdàkọ:LBY |
5,298,152 |
April 15, 2006 |
2006 census result
|
37 |
Republic of the Congo |
3,697,490 |
April 28, 2007 |
2007 census result
|
38 |
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Àrin Áfríkà |
3,859,139 |
2017 |
[1]
|
39 |
Àdàkọ:LBR |
3,476,608 |
March 21, 2008 |
Final 2008 census result
|
40 |
Àdàkọ:MTN |
3,718,678 |
2016 |
Official estimate
|
41 |
Namibia |
2,280,700 |
July 1, 2015 |
Official estimate
|
42 |
Àdàkọ:BOT |
2,024,904 |
August 22, 2011 |
Final 2011 census result Archived 2013-05-25 at the Wayback Machine.
|
43 |
Àdàkọ:LES |
1,894,194 |
2011 |
Official estimate Archived 2014-11-13 at the Wayback Machine.
|
44 |
Gambia
|
1,882,450 |
April 15, 2013 |
Preliminary 2013 census result[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
|
45 |
Gabon |
1,802,278 |
October 5, 2013 |
Preliminary 2013 census result
|
46 |
Àdàkọ:GNB |
1,530,673 |
2015 |
Official estimate
|
47 |
Àdàkọ:MRI |
1,261,208 |
July 1, 2014 |
Official estimate
|
48 |
Guinea Alágedeméjì |
1,222,442 |
July 4, 2015 |
Preliminary 2015 census result
|
49 |
Eswatini |
1,119,375 |
2015 |
Official estimate
|
50 |
Djìbútì |
864,618 |
July 1, 2011 |
Official estimate
|
|
Àdàkọ:REU (France) |
840,974 |
January 1, 2013 |
Official estimate
|
51 |
Kòmórò |
806,200 |
July 1, 2016 |
Official estimate
|
52 |
Cape Verde |
491,875 |
June 16, 2010 |
Final 2010 census result[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
|
|
Western Sahara[4] |
510,713 |
September 2, 2014 |
Preliminary 2014 census result
|
|
Àdàkọ:MYT (France) |
212,600 |
August 21, 2012 |
2012 census result
|
53 |
Àdàkọ:STP |
201,784 |
2018 |
Official estimate Archived 2019-01-24 at the Wayback Machine.
|
54 |
Àdàkọ:SEY |
90,945 |
August 26, 2010 |
Final 2010 census result
|
|
Àdàkọ:SHN (UK) |
5,633 |
June 2016 |
2016 census result
|
Àdàkọ:Pie chart