Foreigner's God (fiimu)

Foreigner’s God jẹ́ fíìmù ọdún 2019, èyí tí Kelechi Freeman Ukadike ṣàgbéjáde, tí Ifan Ifeanyi Michael sì darí lábẹ́ ilé-iṣẹ́ Ifan Micheal Productions.[1][2] Lára àwọn òṣèré tó kópa nínú fíìmù yìí ni Henry Coxe, Ini Dima-Okojie, Toni Tones, Pete Edochie, Nkem Owoh, Bambam (Oluwabamike Olawumi), Teddy A (Tope Adenibuyan), Eucharia Anunobi, Sam Dede, Toyin Abraham, Salma Mumin, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.[3][4]

Foreigner's God (fiimu)
AdaríIfan Ifeanyi Michael
Olùgbékalẹ̀Kelechi Freeman Ukadike
Àwọn òṣèréHenry Coxe, Ini Dima-Okojie, Toni Tones, Pete Edochie, Bambam (Oluwabamike Olawumi), Teddy A (Tope Teddy Adenibuyan), Eucharia Anunobi, Sam Dede, Toyin Abraham.
Ilé-iṣẹ́ fíìmùIfan Micheal Productions
Déètì àgbéjáde
  • 2019 (2019)
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèEnglish

Ìtàn ní ṣókí

àtúnṣe

Eré yìí dá lórí ayàwòrán ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì kan, tó wá sí ilẹ̀ Íbò lásìkò ìjọba amúnisìn. Àyípadà dé bá eré náà nígbà tí ẹ̀ṣọ́ rẹ̀ ṣàdẹ́dé di àwátì, tí í sì padà wá nífẹ̀ẹ́ ọmọbìnrin àjẹ́ kan tí ń gbé nínú igbó.[4][1][2]

Amazon Prime Video

àtúnṣe

Bí ó tilẹ̀ jé pé wọ́n ṣàgbéjáde fíìmù náà ní ọdún 2019, ọdún 2022 ni wọ́n gbe sí orí Amazon Prime Video.[1]

Àwọn òṣèrẹ́ tó kópa

àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 1.2 Nwogu, Precious 'Mamazeus' (2022-05-10). "Ifan Michael's 'Foreigner's God' acquired by Amazon Prime". Pulse Nigeria. Retrieved 2022-07-26. 
  2. 2.0 2.1 "Bambam and Teddy A secure roles in 'Foreigner's God' – The Eagle Online" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2 May 2018. Retrieved 2022-07-26. 
  3. 3.0 3.1 "Movie Fans Await Ifan Michael's 'Foreigner's God' – THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com. Archived from the original on 2022-07-26. Retrieved 2022-07-26.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. 4.0 4.1 4.2 Augoye, Jayne (2018-05-02). "#BBnaija: Teddy A, Bambam land Nollywood roles". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-26. 
  5. "And It's BamTeddy For Nollywood In Foreigner's God". Independent Newspaper Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-05-05. Retrieved 2022-07-26. 


Àdàkọ:Nigeria-film-stub