Richard Mofe Damijo

Òṣeré àti Olóṣèlú

Richard Èyímofẹ́ Evans Mofẹ́-Damijo ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹfà oṣù Keje ọdún 1961 ni gbogbo ènìyàn mọ̀ sí RMD, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá, olùkọ̀tàn, agbẹjọ́rò olùgbéré-jáde àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó ti fìgbà kan tẹ́lẹ̀ jẹ́ Kọmíṣọ́nà fún àti àti ìgbafẹ́ fún Ìpínlẹ̀ Delta nígbà kan rí. Ní ọdún 2005, ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti Africa Movie Academy Award fún Best Actor in a Leading Role.[1][2] Ó gba àmì-ẹ̀yẹ títí láé láé ti 12th Africa Movie Academy Awards fún ipa rẹ̀ nínú eré sinimá ní ọdún 2016.[3][4]

Richard Mofe-Damijo
Mofe-Damijo at the premiere of Love Is War
Ọjọ́ìbíRichard Mofe-Damijo
6 Oṣù Keje 1961 (1961-07-06) (ọmọ ọdún 63)
Aladja, Ípínlẹ̀ Delta, Nigeria
Iṣẹ́Òṣèré, former Olóṣèlú
Ìgbà iṣẹ́1980s-present
Olólùfẹ́Jùmọ̀bí Adégbẹ̀san
Àwọn ọmọ4
Websitehttps://www.rmdtheactor.com

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Richad ní àdúgbò Aladja ní ìlú Udu Kingdom, ìlú tí ó súnmọ́ Warri pẹ́kí pẹ́kí ní Ìpínlẹ̀ Delta. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ti Midwest College, ní ìlú Warri, àti ilé-ẹ̀kọ́ ti Anglican Grammar School, tí ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí ó ma ń ṣeré ìtàgé nígbà náà. Ó tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Fásiti ti UNI BEN, láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa eré-oníṣe Theatre Arts.[5]. Ó tún lọ sí Fásitì ti University of Lagos láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ òfin ní ọdún 1997ó ṣe tán ní ọdún 2004.[1][6]

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Lẹ́yìn tí ó jáde ní fásitì, ó bẹ̀rẹ̀ eré sinimá ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ tí wọ́n pe àkòrí rẹ̀ ní Ripples. Ṣáájú ìg à náà, ó ti ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Ìwé-ìròyìn Concord [7] àti Metro Magazine. [8] gẹ́gẹ́ bí olùjábọ̀ ìròyìn. Ní ọdún 2005, ó di ìlú mọ̀ọ́ká látàrí Out of Bounds tí ó jẹ́ kó gbayì gidi.[5][9]

Ipa rẹ̀ nínú ìṣèlú

àtúnṣe

Wọ́n yan Mofẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùdámọ̀ràn pàtàkì lórí àṣà àti ìgbafẹ́ sí Gómìnà Emmanuel Uduaghan ní ọdún 2008, tí ó sì padà di Kíṣọ́nà fún àṣà àti ìgbafẹ́ fún gbogbo Ìpínlẹ̀ Delta ní ọdún 2009 tí ó kúrò nípò ní ọdún 2015..[10][2][11].

Ìgbé ayé rẹ̀

àtúnṣe

Mofẹ́ ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú arábìnrin May Ellen-Ezekiel tí gbogbo èyàn mọ̀ sí(MEE) tí ó jẹ́ olóòtú àti oníṣẹ́ ìròyìn. Ìyàwó rẹ̀ yí papòdà ní ọdún 1996, tí Mofẹ́ sì tún ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Jùmọ̀bí Adégbẹ̀san tí òun jẹ́ olóòtú ètò orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán.[12]. Moẹ́ bí àwọn ọmọ mèrin, méjì láti ọ̀dò olóògbé tí méjì tókù wá láti ọ̀dọ̀ ìyàwó rẹ̀ tuntun. [13]

Àwọn àṣàyàn fíìmù rẹ̀

àtúnṣe
Year Film Role Notes
1997 Out of Bounds with Bimbo Akintola & Racheal Oniga
Hostages
1998 Scores to Settle with Liz Benson & Omotola Jalade-Ekeinde
Diamond Ring with Liz Benson
1999 Freedom
The Price with Eucharia-Anunobi EKWU
2003 When God Says Yes with Pete Edochie & Stella Damasus-Aboderin
The Richest Man
The Return with Segun Arinze
The Intruder with Stella Damasus-Aboderin & Rita Dominic
Soul Provider with Omotola Jalade-Ekeinde
Romantic Attraction with Stella Damasus-Aboderin, Chioma Chukwuka & Zack Orji
Private Sin Pastor Jack with Genevieve Nnaji, Stephanie Okereke, Olu Jacobs & Patience Ozokwor
Passions with Genevieve Nnaji & Stella Damasus-Aboderin
Love with Genevieve Nnaji & Segun Arinze
Keeping Faith: Is That Love? with Genevieve Nnaji & Joke Silva
I Will Die for You with Omotola Jalade-Ekeinde & Segun Arinze
Emotional Pain with Stella Damasus-Aboderin
Ayomida
2004 The Mayors with Sam Dede & Segun Arinze
True Romance with Rita Dominic & Desmond Elliot
The Legend with Kate Henshaw-Nuttal
Standing Alone with Stella Damasus-Aboderin & Tony Umez
Sisters' Enemy
Queen with Stella Damasus-Aboderin
Little Angel
Kings Pride with Stella Damasus-Aboderin
I Want Your Wife
Indecent Girl Charles with Ini Edo
Indecent Act with Rita Dominic
I Believe in You with Rita Dominic
Engagement Night with Stella Damasus-Aboderin
Deadly Desire
Danger Signal with Desmond Elliot
Critical Decision with Genevieve Nnaji & Stephanie Okereke
Burning Desire with Stella Damasus-Aboderin & Mike Ezuruonye
Critical Assignment The President with Hakeem Kae-Kazim
2005 The Bridesmaid with Chioma Chukwuka, Kate Henshaw-Nuttal & Stella Damasus-Aboderin
Darkest Night with Genevieve Nnaji, Segun Arinze & Uche Jombo
Bridge-Stone with Liz Benson & Zack Orji
Behind Closed Doors with Stella Damasus-Aboderin, Desmond Elliot & Patience Ozokwor
Baby Girl with Pete Edochie
2006 Angels of Destiny
2007 Caught in the Middle
2014 30 Days in Atlanta Kimberley's father
2016 Dinner with Iretiola Doyle
The Wedding Party Felix Onwuka with Sola Sobowale, Ireti Doyle & Adesua Etomi
The Grudge with Doyle and Funmi Holder[14]
2017 10 Days in Sun City Otunba Ayoola Williams with Ayo Makun & Adesua Etomi
2017
The Wedding Party 2 Felix Onwuka with Sola Sobowale, Ireti Doyle & Adesua Etomi
2019 God Calling [15]
Love Is War Dimeji Phillips with Omoni Oboli

Awards and nominations

àtúnṣe
Year Event Prize Recipient Result
Gbàá
2009 5th Africa Movie Academy Awards Best Film In Nigeria State of The Heart Yàán
2012 2012 Best of Nollywood Awards Special Recognition Award Himself Gbàá
2015 2015 Africa Magic Viewers Choice Awards Best Supporting Actor 30 days in Atlanta Yàán
2016 12th Africa Movie Academy Awards LifeTime Achievement Award Himself Gbàá
2017 2017 Africa Magic Viewers Choice Awards Best Actor in Leading Role Oloibiri Yàán
Africa Movie Academy Awards   Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀
2017Nigeria Entertainment Awards Best Supporting Actor   Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 Akande, Victor (28 November 2009). "New world of A-list stars blacklisted in 2005". The Nation (Lagos, Nigeria: Vintage Press Limited). http://thenationonlineng.net/web2/articles/26859/1/New-world-of-A-list-stars-blacklisted-in-2005/Page1.html. Retrieved 24 August 2010. 
  2. 2.0 2.1 "Delta State Government swears in two new Commissioners". Archived from the original on 13 October 2020. Retrieved 26 January 2010. 
  3. Ekechukwu, Ferdinand (27 October 2018). "For RMD, It's Good News from Kigali". Thisday Live (Lagos, Nigeria). https://www.thisdaylive.com/index.php/2018/10/27/for-rmd-its-good-news-from-kigali/. Retrieved 22 April 2019. 
  4. Ekpai, Joan (14 June 2016). "RMD receives Lifetime Achievement award from Pete Edochie (AMAA 2016)". Nollywood Community (Lagos, Nigeria). https://nollywoodcommunity.com/rmd-receives-amaa-life-time-achievement-award-from-pete-edochie/. Retrieved 22 April 2019. 
  5. 5.0 5.1 Ogunbayo, Modupe. "Richard Mofe-Damijo: An Actor's Actor". Newswatch (Lagos, Nigeria: Newswatch). Archived from the original on 13 October 2020. https://web.archive.org/web/20201013033028/https://www.newswatchngr.com/editorial/allaccess/special/10112232035.htm/. Retrieved 24 August 2010. 
  6. Balogun, Sola. "Acting on stage is my greatest passion". Daily Sun (Lagos, Nigeria: The Sun Publishing Limited). http://www.sunnewsonline.com/webpages/features/showtime/2009/jan/09/showtime-09-01-2009-001.htm. Retrieved 24 August 2010. 
  7. "After Concord Newspaper died, it felt like I lost a baby –Mike Awoyinfa". 
  8. "Richard Mofe-Damijo: Profile of an iconic Nollywood actor". P.M. News. 8 May 2020. 
  9. "Richard Mofe-Damijo – Profile". New York City: African Film Festival. Archived from the original on 13 October 2020. Retrieved 24 August 2010. 
  10. "Special Adviser or not im still an actor RMD". thenigerianvoice.com. Retrieved 29 August 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  11. "Comedian mocks RMD". AllAfrica.com. Retrieved 29 August 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  12. "Remembering May Ezekiel, 21 years after". Archived from the original on 2020-10-21. Retrieved 2020-10-19. 
  13. "RMD: Two Decades of Screen Romance". Archived from the original on 17 August 2010. Retrieved 26 January 2010. 
  14. "FUNMI HOLDER: The Nigerian Actress Who Went Back in Time". 19 January 2020. 
  15. "God Calling Movie". IMDb. Retrieved 13 June 2019. 

Àwọn Ìtàkùn ìjásóde

àtúnṣe


Àdàkọ:Africa Movie Academy Award for Best Actor