The Wedding Party (Fíìmù 2016)
(Àtúnjúwe láti The wedding party)
The Wedding Party jẹ́ fíìmù àgbéléwò apanilẹ́rìn-ín àti ajẹmọ́fẹ̀ẹ́ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jáde lọ́dún-un 2016 tí Kemi Adetibasì jẹ́ olùdarí fíìmù náà. Àfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ jáde lọ́jọ́ kẹjọ oṣù kẹsàn-án ọdún 2016 ní Toronto International Film Festival ní Canada àti lọ́jọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kọkànlá ọdún kan náà ní Èkó hotel and suites ní Èkó. Agbẹ́jáde fíìmù náà lágbàáyé wáyé lọ́jọ́ kẹrìndínlógún oṣù kejìlá ọdún 2016 tí ó sì jẹ́ fíìmù àgbéléwò tí àwọn èèyàn ń wò jù.[4][5]
The Wedding Party | |
---|---|
Adarí | Kemi Adetiba |
Àwọn òṣèré | |
Orin |
|
Ìyàwòrán sinimá | Akpe Ododoru |
Olóòtú | Andrew Webber |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Ebonylife Films FilmOne Inkblot Production Koga Studios |
Olùpín | FilmOne Distributions |
Déètì àgbéjáde |
|
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | English Yoruba Igbo |
Ìnáwó | ₦60 million[2] |
Owó àrígbàwọlé | ₦453,000,000[3] |
Àwọn Akópa
àtúnṣe- Adesua Etomi bíi Dunni Coker (ìyàwó)
- Banky W bíi Dozie Onwuka (ọkọ ìyàwó)
- Richard Mofe Damijo bíi Chief Felix Onwuka (bàbá ọkọ)
- Sola Sobowale bíi Mrs. Tinuade Coker (ìyá ìyàwó)
- Iretiola Doyle as Lady Obianuju Onwuka (ìyá ọkọ)
- Alibaba Akporobome as Engineer Bamidele Coker (bàbá ìyàwó)
- Zainab Balogun as Wonu (agbátẹrù ayẹyẹ)
- Enyinna Nwigwe as Nonso Onwuka (àbúrò ọkọ)
- Somkele Iyamah-Idhalama as Yemisi Disu (ọ̀rẹ́ ìyàwó)
- Beverly Naya as Rosie (ìyàwó ọkọ nígbàkanrí)
- Daniella Down as Deardre Winston (ọ̀rẹ́ ìyàwó)
- Afeez Oyetoro as Ayanmale
- Ikechukwu Onunaku as Sola (ọ̀rẹ́ ọkọ)
- AY Makun as MC
- Emmanuel Edunjobi as Woli (wòlíì)
- Kunle Idowu as Harrison
- Jumoke George as Iya Michael
- Sambasa Nzeribe as Lukman
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "The Wedding Party". Archived from the original on 19 August 2016. Retrieved 19 August 2016. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "LONG READ: How The Wedding Party became the biggest critical and commercial Nollywood success story". 31 December 2016.
- ↑ "The Inflection Point Of Nigerian Cinema?". 15 May 2019.
- ↑ Vourlias, Christopher (2017-02-04). "'Wedding Party' Fuels Record Nigerian Box Office Despite Ailing Economy". Variety (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-10-05.
- ↑ "'Wedding Party 1' named highest-grossing Nollywood movie of the decade2 minutes read". News Central - Latest in Politics, Business, Sports and stories across Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-01-09. Retrieved 2020-10-05.