Ẹkáàbọ̀!

Ẹpẹ̀lẹ́ o, Taoheedah,ẹkáàbọ̀ sí Yòrùbá Wikipedia!! Adúpẹ́ fún àfikún yín. Mo lérò wípé ẹ nífẹ́ sí kí ẹ wà níbí. Ẹwo àwọn oun tí a ṣètò sí ìsàlẹ̀ yìí bóyá ó lè wúlò fun yín:

Ẹ jọ̀wọ́ ẹ rántí fi òǹtẹ̀ tẹ oun tí ẹ bá kọ sí ọ̀rọ̀ ojú ewé pẹ̀lú igun mẹ́rin (~~~~); èyí máa gbé orúkọ yín àti déètì jáde. Bí ẹ bá ń fẹ́ ìrànlọ́wọ́ ẹ kàn sí mi, +/-, mo sì máa ràn yín lọ́wọ́, ẹkáàbọ̀! T CellsTalk 09:37, 26 Oṣù Kàrún 2022 (UTC)

Àyọkà

àtúnṣe

Ẹ kú ìṣe óò! Orúkọ tèmi ni T Cells. Mo ri wípé ẹ ń ṣẹ̀dá àyọkà tí kò si òun kohun níbè bí Ann Mukoro, Prisca Emeafu, Dami Olonisakin àti bẹ́ẹ̀bẹ̀ẹ́ lọ. Ẹ jọ̀wọ́ ẹ kọ àwọn àyọkà yí dáadáa kí ẹ tó ṣẹ̀dá òmíràn. Ẹ ṣeun. T CellsTalk 09:48, 26 Oṣù Kàrún 2022 (UTC)

I am just seeing this notification as my phone screen spoilt as at the time it was sent. Thank you for the feedback Taoheedah (ọ̀rọ̀) 04:45, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

Àkíyèsí pàtàkì

àtúnṣe

Ẹ káre Oníṣe:Taoheeda, a kí yín kú iṣẹ́ takuntakun, Mo fẹ́ pè yín sí àkíyèsí pàtàkì lórí àwọn àyọkà yín rí ẹ ń dá sílẹ̀. Ẹ ṣe ògbufọ̀ yín dára dára kí ẹ tó ṣẹ̀dá àwọn àyọkà yí sórí Wikipedia èdè Yorùbá, ó ṣe pàtàkì kí ẹ ṣe èyí fún ìdẹsẹ̀ múlẹ̀ iṣẹ́ gbogbo wa. Ẹ ṣeun púpọ̀.Agbalagba (ọ̀rọ̀) 22:53, 27 Oṣù Kàrún 2022 (UTC)

I was tagged to a wrong userpage so I could not see this feedback. Taoheedah (ọ̀rọ̀) 04:43, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

Àkíyèsí pàtàkì

àtúnṣe

Oníṣẹ́@Taoheedah, mo ṣàkíyèsí wípé púpọ̀ nínú àwọn àyọkà rẹ tí o kọ sí orí Wikipedia èdè Yorùbá ni wọ́n jẹ́ kíkọ sílẹ̀ pẹ̀lú irinṣẹ́ Google Translation. Mo ma gbà ọ́ níyànjú kí o ṣe àtúnṣe tí ó yẹ sí wọn kí wọ́n lè mọ́yán lórí jù báyí lọ. Lásìkò tí o bá ń ṣe èyí, n ó gbà ọ́ níyànjú kí o má ṣe da àyọkà tuntun míràn sílẹ̀ nítorí kí o lè ráyè kọbi ara sí àwọn àtúnṣe rẹ gbogbo. Àpẹẹrẹ irúfẹ́ àwọn àyọkà bẹ́ẹ̀ ni: Átẹ́gùn Ooru, Ìmúdọ́gba Àyipàdà Ójú Ọjọ́ , Ipà Àyipada Óju Ọjọ ninu Ẹkọ Ọgbin, Aarun Ómi ati Àyipada Óju Ọjọ, Ìṣilọ ati Àyipada lori Àyika Ágbàyè, Ájálù to ṣẹ̀lẹ nipa Ìfómipamọ ti Gusau, Desmond Màjẹkòdùnmì àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Àwọn ohun tí a ń retí nínú àwọn àtúnṣe rẹ ni:

  1. Ṣíṣàmúlò àkọtọ́ gidi lórí àwọn àyọkà rẹ.
  2. Ṣíṣayípada àwọn ọ̀rọ̀ bíi arákùnrin náà, àti àwọn ohun tó fara pa, ìdí ni pé ìṣọwọ́kọ̀wé yí kò bá ìsọwọ́ kọ ìmọ̀-ọ̀fẹ́ sílẹ̀ mu.
  3. Lílo àwọn àmì ohùn tó yanjú lórí àwọn àyọkà rẹ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Lákòòtán, ìkìlọ̀ tó wà níbẹ̀ ni wípé bí a kò bá rí àtúnṣe tó lọ́ọ̀rìn lóri àwọn àyọkà wọ̀nyí, a ó dárúkọ wọn fún ìparẹ́ kíákíá. Àwọn àyọkà tó mọ́yán lórí la ń fẹ́ lórí Wikipedia èdè Yorùbá; kìí ṣe danda wìì. O ṣeun púpọ̀. Agbalagba (ọ̀rọ̀) 16:32, 18 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

::Ibanilorukọ jẹ to lagbara<\del> :Mo yi ayọka ti oloyinbo mọ si Title "The Polytechnic Ibadan" pada si "Polytechnic Ilù Ìbàdàn" ni toripe YORUBA Wikipedia lawa. O jẹ iyanilẹnu pe Iwọ Agbalagba tọka simi gẹgẹ oluṣẹda ayọka, nigba to jẹ pe ayọka yi ti wa tipẹ ti a da silẹ lati ọdọ Olukọwe miran. Odawipe ọrọ yi o ti kọja oun miran ti koyemi rara. Ibanilorukọ jẹ yi lagabara ti ko si bojumu. Taoheedah (ọ̀rọ̀) 17:16, 18 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC) ::O ṣeun púpọ̀ fún àlàyé rẹ. Mo sì fẹ́ kí o di àwọn kókó ìsàlẹ̀ yí mú dára dára. ::#Kò s'ẹ́ni t'ó ráyè láti ma lo àsìkò iṣẹ́ ọ̀fẹ́ rẹ̀ láti ma fi tún àwọn àyọkà tí ìwọ ní ànfàní láti kọ dárá dára nígbà tí o ń kọọ́ lọ́wọ́. Irúfẹ́ ìṣòro yí pọ̀ tí a ń palẹ̀ wọn mọ́ tí wọn kò tíì tán nílẹ̀ #Mo mọ̀ wípé ìwọ kọ́ ni o kọ àyọkà Polytechnic Ilù Ìbàdàn, àmọ́ ìṣọwọ́ kọ akọ́lé rẹ̀ ni ó gún mi ní kẹ́ṣẹ́ láti lọ wo àwọn akọsílẹ̀ rẹ àtẹ̀yìn wá dára dára tí mo sì rí àwọn abùjẹnjẹkù orísiríṣi nínú wọn. #A ti sọ láìmọye ìgbà wípé kí á ma fi àwọn àkọ́lé tí ó bá ti jẹ́ orúkọ ayémọ̀ (orúkọ tí ǹkan ń jẹ́) (proper noun) sílẹ̀ bí wọ́n bá ṣe wà fún ànfàní àwọn tí wọn kò lè ma fi èdè Yorùbá wá àyọkà lórí Google. Àkọ́lé rẹ ọ̀hún kò tún bójúmu bí o bá kàá dára dára. #Kìí ṣe nítorí àyọkà Polytechnic Ilù Ìbàdàn nìkan ni mo ṣe fi ìwé ránṣẹ́ sì ọ, bí kò ṣe nítorí púpọ̀ àwọn àyọkà rẹ tí o ti kọ sẹ́yìn tí wọ́n kò gún règé tó tí ó sì yẹ kí o bójútó wọn kí wọ́n lè mọ́yánlórí. #Lílo àmì ohùn rẹ kò dára tó. Púpọ̀ nínú àwọn àyọkà rẹ ni àmì orí-ọ̀rọ̀ wọn ń kolùgbẹ́, èyí sì léwu púpọ̀ fún èdè Yorùbá gẹ́gẹ́ bí èdè alohùn. Bí ohun tí o bá kọ sílẹ̀ bá dára, tí àmị̀ orí rẹ̀ bá korò, àṣìgbọ́ àti àṣìkà ni àwọn ònkàwé yóò ma kà. Bí èyí bá dàbí irọ́, lọ ka àwọn àyokà rẹ tí mo tọ́ka rẹ̀ fún ọ. Yóò dára bí o bá lè ma kọ àyọkà láì fi àmì si nígbà náà, àmọ́ tí o bá ri wípé ó pọn dandan kí ó fi si, o lè kàn sími kí n ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún ọ lórí èyí. #Irúfẹ́ àwọn àyọkà tí mo tọ́kasí fún ọ ṣáaj̀ù wọ̀yẹn ni wọ́n kò tọ́ kí wọ́n wà lòrí pẹpẹ ìmọ̀-ọ̀fẹ́ Yorùbá; ń ṣe ni wọn yóò ma kó ẹrẹ̀ bá Wikipedia èdè Yorùbá lápapọ̀ lọ́dọ̀ àwọn tí wọ́n bá ń kàá. Nítorí rẹ̀ wọ́n lè má padà wá sí Wikipedia èdè Yorùbá mọ́. #Mo ti fi ìwé ránṣẹ́ sí ọ rí lòrí àyọkà Sikọlashipu ti Chenening tí o kọ̀ láti fèsì sí ọ̀rọ̀ mi, àyàfi lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n pa àyọkà náà rẹ́ kí o tó dáhùn. ::#Mo lérò wípé bí mo ṣe pe àkíyèsí rẹ sí àwọn àṣìṣe, àṣìkọ àti àṣìgbékalẹ̀ èdè Yorùbá nínú àwọn àyọkà rẹ ni o kórìíra jọjọ, èyí sì mú kí o ma rí àwọn iṣẹ́ lámèyítọ́ mi gẹ́gẹ́ bí àtakò. Ìhùwàsí yí lòdì sí òfin Wikipedia tí ó sọ wípé Assume good faith and engage in constructive edits Ní èrò rere. ::#O kò kí ń ṣe ẹni àkọ́kọ́ tí mo ma pè sí àkíyèsí lórí irúfẹ́ àwọn àtúnṣe báyìí tí wọ́n gbọ́ tí wọ́n sì ń ṣe dára dára, bákan náà ni o kò ní jẹ́ ẹni ìkẹyìn tí kò fẹ́ kọ́ ìmọ̀ tí ó lè mú ìlọsíwájú bá Wikipedia èdè Yorùbá. ::Láfikún, ojúṣe tèmi tìẹ ni láti bójútó Wikipedia èdè wa kí ó lè gún régé ju bí ó ti wà yí lọ. ::Níparí ọ̀rọ̀, mo fẹ́ kí o mò wípé gbogbo ẹ̀gbin àti awọ̀sí ti o fi kàn mí ni níbí àti ní ojú ayé pàá paá jùlọ lórí (WhatsApp group chat) lòdì sí òfin 'UCoC Article (3.1-Harrasment) látàrí wípé mo pè ọ́ sí àkíyèsí pàtàkì. Fúndí èyí, ó yẹ kì́ o tọrọ àforíjìn fún ìhùwàsí́ rẹ kí o sì gbọ́ àmọ̀ràn kí o sì mulò kí ó lè ṣe ẹ́ ní ànfàní. Ju gbogbo rẹ̀ lọ, mo fẹ́ kí o mọ̀ wipé iṣẹ́ tèmi ni mo ń ṣe ire ooAgbalagba (ọ̀rọ̀) 23:29, 18 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

::Thank you for the response Agbalagba :I would first like to debunk the accusation of using the google translating tool for the articles I created. I have not used google translating tools in the YORUBA Wikipedia in the articles aforementioned.

:I am glad you reiterate that I was tagged to an article I did not create (Polytechnic Ilù Ìbàdàn), your response shows that you were ever prepared to attack my contributions on the Wikipedia page (It is like being monitored) which I find shocking. Time spent on monitoring like this can be utilized in organizing Training sessions on the Ami ohun gap as you have done in the past as I had benefited and sharpen my skills therein.

:For the Whatsapp group mentioned, I stated my observation for being tagged to what I did not create, No response to my complaints rather it was a threat to be blocked if I continue to express my complaints on being treated unfairly. Taoheedah (ọ̀rọ̀) 04:38, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC) ::I see no reason of creating a storm in a teacup over a harmless instructions to correct wrong edits. I have carefully read the conversation on this and I found nowhere where User: Agbalagba "defamed" you as you alleged. All I saw was a call of attention of the wrong change of The Polytechnic Ibadan on the article and other articles which you created but look like you used Google translator to create them because those articles are actually badly created and significantly meaningless. The syntax of those articles are very poor to believe that they are created using Google translator, which is not good for writing yoruba articles because of its automated but fundamental translation errors which wrongly translate those words, phrase and sentences in Yorùbá. Also, Yoruba tone mark on those articles are very wrong. Hence, the civil call for your attention to correct those errors. How is this a defamation? Oniṣe:Taoheedah, many of these errors created in the pass by some users are still being tidied up till now, hence, we encourage users to avoid those mistakes again so as to make Yoruba Wikipedia a true encyclopedia of yoruba knowledge where readers will read meaningful articles. Please, let's thread softly and treat one another with love and respect. In the entirety of your conversation with Agbalagba I did not see any form of defamation as you alleged but a harmless call to order on how to create a meaningful article and not damage existing one. Please, let's work together as a big family for the progress of our volunteering efforts on Yoruba Wikipedia. Thanks. Macdanpets 06:36, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

:::I did not create the "The Polytechnic Ibadan" @Macdanpets, It was another editor. The title was only changed to a Yoruba version.

For the google translator tool, I did not use any automated tool in the articles I had created.

If @Agbalagba did not have personal aggreviance against me, he would not have tagged me under a wrong article. Threatening to delete already existing articles without nomination or correcting the said mistakes is not an action done with Love or an harmless one as indicated above.


For the Ami ohun, I will be glad if a guide or explicit correction is made on how to correct that in the existing articles aforementioned. Maybe a Training session since it is indicated above that I am not the only editor being corrected on the articles in the YORUBA Wikipedia. Taoheedah (ọ̀rọ̀) 07:18, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

I think the point she's trying to make was that she didn't create the article 'polytechnic ìlú Ìbàdàn' where she was erroneously tagged.

Anyone can be corrected as this is a public space but tagging one to a wrong message can come off as a personal beef which I'm sure is a misunderstanding and an oversight from user: Agbalagba.

She only changed title for this particular article which is a minor edit. The particular user who created the article should be tagged for their errors not her.

Also, with the above mentioned corrections as regards articles previously created by her, I'm sure she would take to correction and make amendment as suggested. Tesleemah (ọ̀rọ̀) 06:56, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

*comment - @Agbalagba:, the Polytechnic of Ibadan article was not created by Tahoheeda and she should not have been pinged on the article's talk page. In the future, you should consider reviewing page history before making any blanket assessment of its creation. That said, nothing rises to the level of defamation (in the legal context of the word). Tahoheeda, Yoruba Wikipedia does not allow machine translation, as it has been pointed out to you numerous times. I see many instances where machine translations have been used in translating your articles; please refrain from doing so in the future. Defensively claiming that your articles were not created with Google translation is not helpful. For example, Prisca Emeafu and Ann Mukoro were certainly created with a Google translator. Please refrain from doing that, and I encourage you to revisit all the articles you have created here to fix them accordingly. I believe that feedback has been given, lessons have been learned, and these would help you to improve. Let's get back to work. T CellsTalk 07:54, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

T Cells, Maybe due to the Ami ohun that was wrongly placed or other errors made the articles looks like an automated one. I did not use google translator on the two articles aforementioned, this is the first time I will be hearing of such tool.

I translated the aforementioned articles with the knowledge of yoruba I had and that of the training session previously organized by the Yoruba Usergroup.

Like I said earlier, I would require support such as a training session on how to fix the ami ohun and any other mistakes I had made during the cause of my Translation. Taoheedah (ọ̀rọ̀) 08:13, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC) OK. Why did you translated Ann Mukoro (born 27 May 1975) is a Nigerian footballer who played as a midfielder for the Nigeria women's national football team. as Ann Mukoro jẹ Obinrin agbàbọọlu orilẹ ede Naigiria ti a bini 27, óṣu May ni ọdun 1975. Elere naa ṣere fun team awọn obinrin naigiria ti national lori bọọlu gẹgẹbu Midfielder? What do you meant by Elere naa ṣere fun team awọn obinrin? How does this translate into ... played as a midfielder for the Nigeria women's national football team? Perhaps we should start from there. T CellsTalk 09:01, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC) @T Cells,Since you identified the wrong translation of the statements aforementioned, perharps you can give a correct one so that I can get it fixed. Taoheedah (ọ̀rọ̀) 10:13, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC) This has not answered my question. You don't create a mess for other volunteers to mop up. You can't continue to create a mess for other volunteers to mop up for you. Either you stop, or you are shown the door. T CellsTalk 10:30, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC) I am not creating a mess @T Cells, you identified a fix and I requested a solution since I had Translated the article 2 years ago. Telling me I will be shown the door is uncivil and against the principles of the Wikipedia.

Volunteers are to be encouraged and supported not to be talked down on as you have just done.

This is the second time I will be threatened to be blocked by you Taoheedah (ọ̀rọ̀) 10:34, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

Ẹ kú dédé ìwòyí o, Taoheedah. Mo máa gbà yín níyànjú kí ẹ kọ́ sùùúrù. Gbogbo ohun tó wà nílẹ̀ yìí ò ì tó ohun à ń jà rọ̀inrọ̀ìn lórí. Mo lérò wí pé ohun tí Agbalagba ń gbìyànjú láti sọ ni pé kí ẹ ṣàtúnṣe sí àwọn àyọkà tí ẹ ti kọ sẹ́yìn. Kò sì sí ìbanilórúkọ jẹ́ kankan nínú gbogbo ọ̀rọ̀ wọn. Ìdí abájọ ni pé gbogbo àwọn àyọka wọ̀nyí ò bá òfin kíkọ èdè Yorùbá mu, bẹ́ẹ̀ sì ni kò bá àkọtọ́ òde-òní mu pẹ̀lú. Akitiyan wa lórí ìwé ìmọ̀-ọ̀fẹ́ Yorùbá yìí ni pé kí a ní àwọn àyọkà tó kúnjú òṣùwọ̀n, tí wọ́n fi èdè Yorùbá tó jiná dénú kọ, tí ó sì bá òfin èdè Yorùbá mu. Àti pé Yorùbá Wikipedia jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọ̀nà láti gbé èdè Yorùbá lárugẹ, kí ó sì wà lórí ẹ̀rọ-ayélujára. Kò wá ní dára tí a ò bá kọ ọ́ pérépéré, lọ́nà tó máa dùn ún kà, tó sì máa dùn ún gbọ́. Kò ní dára kí àwọn àyọka Yorùbá lórí Wikipedia má ṣe é lò fún àwọn alákada, òjọ̀gbọ́n tàbí àwọn tó ń ṣe iṣẹ́-ìwádìí. Bí àwọn iṣẹ́ wa ò bá sì wúlò fún àwọn ènìyàn inú àwùjọ, a jẹ́ pé asán ni gbogbo ìgbìyànjú wa. Kò sì sẹ́ni tó fé ṣiṣé lásán. Bákan náà, mo fẹ́ pé àkíyèsí yín sí lílo èdè Gẹ̀ẹ́sì lórí ìkànní yìí. Wikipedia ti èdè Yorùbá ni èyí, kì í ṣe ti Gẹ̀ẹ́sì, nítorí ìdí èyí, èdè Yorùbá ló yẹ kí a lò nínú rẹ̀. Gẹ́gẹ́ bí a ò ṣe lè lo èdè Yorùbá lórí Wikipedia ti Gẹ́ẹ̀sì, bẹ́ẹ̀ náà ni a ò lè lo èdè Gẹ́ẹ̀sì níbí. Èyí já sí wí pé gbogbo ìdáhùn yín gbọ́dọ̀ wà ní èdè Yorùbá. Ẹ ṣé o. Ọmọladéabídèmí99 (ọ̀rọ̀) 08:30, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

ìdálẹ́kun

àtúnṣe

Mo ti dá ẹ lẹkun làti kópa ní orí Wikipedia ti èdè Yorùbá fún "kíkọ àwọn àyọkà tí kò bójú mú àti láìgba ìmọ̀ràn láti ọwọ́ àwọn Oníṣe míràn". Ẹ ṣeun. T CellsTalk 10:55, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

:You are a bully @T Cells and it is so obvious from your conversation so far. All what you said I did was manipulated and because I refuse to give in to your accusations you Decided to block me as you have threatened. Kudos! Taoheedah (ọ̀rọ̀) 11:04, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

In light of the above, I have now revoked your talk page access for harassment. Regards. T CellsTalk 11:10, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

Appeal to Revoke block

àtúnṣe

Ẹ jọ̀wọ́ @T Cells,E bawa dá ojú ìwé @Taoheedah padà láti kópa ní orí Wikipedia tí èdè Yorùbá. Kò yẹ kí irú àwọn ọ̀rọ̀ báwọn yìí ṣẹlẹ̀ ní àkọ́kọ́. @Taoheedah jẹ́ akọ̀wé Yorùbá ti ó ṣe tán láti kọ́ ìmọ̀ kún ìmọ̀ nípa èdè Yorùbá. Bí ọrọ ṣe ṣẹlẹ̀ lónìí ló jẹ́ kí ó fi ìbínú sọ̀rọ̀. Ẹ jọ̀wọ́ ẹ jẹ́ ebu rẹ̀, kí ẹ sì fà á kọ̀wé yìí mọ́ra kí a lè jumo gbé àṣà wá lárugẹ. Tesleemah (ọ̀rọ̀) 11:41, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC) E ǹ lẹ́ ó, Tesleemah Ó ṣeni láàánú pé arábìnrin yìí padà fi ẹnu ara rẹ̀ kóbá ara rẹ̀. Ó yàmí lẹ́nu pé ẹ̀ ń bá a bẹ̀bẹ̀ kí wọ́n gbà á láyè láti máa kọ àyọkà sórí Yorùbá Wikipedia yìí. Ẹ tún wá ń sọ̀rọ̀ nípa gbígbé àṣà Yorùbá lárugẹ? Ǹjẹ́ ẹ ti gbàgbé pé ọkàn lára àwọn àṣà Yorùbá yìí ni ìbọ̀wọ̀fágbà àti ẹ̀kọ́ ilé? Ẹ ò ri bí ó ṣe wọ́ Agbalagba nílẹ̀, tó tún ń lo "ó" fún un? Èyí fi hàn gbangba gbàǹgbà pé arábìnrin yìí ò ní àwọn ohun méjì tí mo dárúkọ yìí. A ò gbọdọ̀ sọ pé nítorí a wà lórí ẹ̀rọ-ayélujára, kí a wá máa ṣe bó ti wùn wá. Èyí sì kọ́ ni ìgbà àkọ́kọ́ tí irú èyí á máa wáyé. Èmi gan-an alára ti kàbùnkù lọ́wọ́ arábìnrin Taoheedah yìí, tó jẹ́ wí pé èmi gan-an ni mo wá ń bẹ̀bẹ̀, kí àlàáfíà ba lè jọba. Ní àsìkò tí mo bá a sọ̀rọ̀ pé kò kọ àwọn àyọkà rẹ̀ dáadáa, kò bá ti fi àkókò yìí kọ́ ìmọ̀ kún ìmọ̀ nípa èdè Yorùbá, kí ó sì ṣe àtúnṣe lórí àwọn iṣẹ́ rẹ̀. Ẹni a wí fún, ọba jẹ́ ó gbọ́... Ire ó. Ọmọladéabídèmí99 (ọ̀rọ̀) 12:45, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

Ẹsẹ sùúrù arábìnrin @Ọmọladéabídèmí99, Okùn kí rù rúrù ká wá rúrù. Ilé ayé kó sì pìn sí orí ikawé Yorùbá Wikipedia. Ibí tí ọ̀rọ̀ bá wà lósi yẹ ká sọ sì. Àtúnṣe ni ọ́mọ̀ Yorùbá tótọ́ má ń ṣe kì í ṣé ìdaru rárá.
Kí àlàáfíà jọba ní èrò tèmi tí mò fín pàrọwà sí @T Cells
Olúwa yó tún gbógbó wá ṣe ní ti dáadáa. Ire ooooo Tesleemah (ọ̀rọ̀) 13:12, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)
Ẹ mà kú ìjíròrò o...
@Tesleemah,@Ọmọladéabídèmí99 @Macdanpets, àti @T Cells. Èmi kò mọ̀ wípé òkun ọ̀rọ̀ ti gùn tó báyí, àṣé lóòtọ́ lòwe àwọn àgbà tó sọ pe bọ́mọdé bá gbà odi ẹyìn, ṣọṣọ á sọ ọ́. Ẹ̀wẹ̀, fúnra Ìdá ni yóò sì pera rẹ̀ lẹ́rú, ṣebí iṣẹ́ tèmi ni mo ń ṣe gẹ́gẹ́ bí alákòóso àti alábójútó fún Wikipedia èdè Yorùbá àti àwọn ọmọ ẹgbẹ́ rẹ̀ tí mo fi ń tọ́ oníṣẹ́ Taoheedah sọ́nà tí mo sì ń pe àkíyèsí rẹ̀ sí ohun tí ó lè kò ẹ̀yẹ àti apọ́nlé báa látara àwọn akọsílẹ̀ rẹ gbogbo. @Tesleemah, O kò lè sọ wípé o kò mọ irúfẹ́ ọṣẹ tí Oníṣẹ́ Taoheedah kò fimí gún tán látarí ohun tí mo sọ? Ṣebí sùúrù àti èbùrẹ́ ni mo jẹ, n kò sì fèsì kan kan sí gbogbo ìwọ̀sí rẹ̀. Abí bẹ́ẹ̀ kọ́? Ó fi hàn wípé oníṣẹ́ Taoheedah kìí gba ìmọ̀ran àti ìtọ́ni tí kò sì ka ẹnìkan sí rárá, èyí sì léwu fún iṣẹ́ wa.
Gẹ́gẹ́ bí mo ti sọ, ìwé tí mo fi ránsẹ́ si kìí ṣe nítorí Ibadan Poly tí ó ń pa mọ́ka kiri tí kò sì jẹ́ kí ó rí kókó ọ̀rọ̀ mi mú dání, bí kò ṣe àwọn àtúnṣe tí mo ri wípé ó yẹ kí ó ṣe kí Wikipedia Yorùbá lè dára si. Ojúṣe tèmi ni láti pe àkíyèsí ẹnikẹ́ni tí ó bá ti ń ṣe afikún sí Wikipedia èdè Yorùbá kí wọ́n lè ṣe ohun tí ó tọ̀nà, ìyẹn kìí ṣe wípé mo dójú lé wọn. Àìmọye aláfikún bíi tiẹ̀ ni mo ti pè sí akíyèsí, díẹ̀ làra wọn ni @Marvelousola01, rushina, blessing, Aderiqueza, @Ọmọladéabídèmí99, Adeseyeyoju Deborah ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ tí wọ́n sì gbọ́rọ̀. Kò sí ìkan nínú wọn tó fẹ́sùn kànmí rí. Báwo wá ni tiẹ̀ yóò ṣe yàtọ̀ tí yóò fi ma rò wípé mo ń ba òun lórúkọ jẹ́? Ìgbéraga náà pọ̀ gidi.
@Tesleemah, kí o lè mọ̀ wípé oníṣẹ́ @T Cells àti ẹnikẹ́ni kò ní Taoheedah lọ́kàn rárá, kò sẹ́ni tó bu tàbí tàbùkù rẹ̀ bí ó ti wulẹ̀ kí ó kéré mọ. Òun ló ya Amọ̀kẹ́ Ajà-bí-ìjì. ìwà àti ẹnu rẹ̀ ni ó fi gbéra rẹ̀ ṣubú lọ́dọ̀ olóòtú àgbà. Bí a bá wà nírú àwùjọ tí a wà yí, a kìí ṣe àtakò ẹlòmíràn. Bẹ́ẹ̀ ni a kìí búnìyàn tàbí sọ̀rọ̀ òdì sí akẹgbẹ́ wa. Ohun tí oníṣẹ́ Taoheedah sọ yí You are a bully jẹ́ gbólóhùn tó lòdì sí àwùjọ àwọn aláfikún Wikipedia gẹ́gẹ́ bí òfin yí [1] àti eléyí náà tó dásí ìwà ìfìwọ̀sí lọni [2] kí n má wá ì tíì sọ tèmi tó ṣe fún mi láàrín àwọn ènìyàn tí wọn kò mọ ohun tó ṣẹlẹ̀ láàrín wa lórí Wikipedia. Àwọn òfin méjèèjì òkè yí ni mo lérò wípé Oníṣẹ́ T Cells fi ṣe ìdájọ́ fún Taoheedah gẹ́gẹ́ bí alábòójútó àgbà fún Wikipedia èdè Yorùbá.
Fúndí èyí, oníṣẹ́ Tesleemah. Ẹni ọ̀rọ́ kan yóò wà lábẹ́ ìdíllọ́nà gẹ́gẹ́ bí awọn òfin òkè wọ̀nyí ti sọ.
Ẹ kú ìkàlẹ̀..Agbalagba (ọ̀rọ̀) 15:27, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)
Bẹẹni, ọrọ nà 'You Are bully' tóbi, kosi bójú mú rárá àmọ́ tí à bá ọmọ dé wí, a tún fà mọ́ rà ni.
Má tún bọ́ rọ́ @T Cells àti @Agbalagba àti ẹlòmíràn tí ọ̀rọ̀ yìí kan, kí ẹ jẹ́ ebu rẹ̀, Kí ẹ fí ọwọ́ wọnú kí akọ̀wé @taoheedah lè padà sí ẹni tí ó lè ṣe atẹ́ jáde lórí ikawé yìí.
Àgbà tí ó bá bínú ní ọmọ rẹ̀ pò. Tesleemah (ọ̀rọ̀) 16:21, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)
Mo tì bá Oníṣe @Taoheedah sọ̀rọ̀, òsì ṣé tán láti tọrọ aforiji fún àwọn ọ̀rọ̀ tí ó sọ sì òkè. Ẹ jọ̀wọ́ @T Cells. Ẹ bá wà síí ojú ọ̀rọ̀ Oníṣe yìí láti ṣe òun tí ó tọ́. Tesleemah (ọ̀rọ̀) 17:02, 19 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

Àfikún orí-ọ̀rọ̀ Tesleemah (ọ̀rọ̀) 02:07, 20 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

Appeal by Tahoheeda via email

àtúnṣe

Hello T Cells,

I'm writing to appeal to be unblocked on yo.wiki. I acknowledge that I used an offensive statement such as "Bully", which was wrong and I apologize for that. I understand that my actions led to the talk page block, and I'm willing to retract my statements and make amends.

Regarding the suggestions made on the articles, I'm willing to work on them and improve my contributions. I realize now that I misunderstood the corrections and will strive to do better.

Kindly review my appeal. I look forward to your feedback. Tahoheeda. 27 Apr 2024, 18:49.

Comment from blocking admin

àtúnṣe

First off, You would need to retract all the false claims you have made against me at Meta:Requests for help from a sysop or bureaucrat#Request for Organizer Rights: Taoheedah and other venues, including the ones you made here. At Meta:Requests for help from a sysop or bureaucrat#Request for Organizer Rights: Taoheedah, you had falsely claimed that "the Blocking was done as a result of sentiments and biases on his part." and also claimed that you "find it shocking that @T Cells keep tracing my movements on the Wiki space after several threats and abuse of power on the yo.Wiki.". I have more than 800,000 global edits and my contributions to Meta-Wiki alone is more than 80% of your global contributions. Thus, I have no idea why you claimed that I was following you around Wikis. You do need to immediately retract these malicious comments there and on any other platforms or venues where you have made similar false claims (that I haven't seen).

Secondly, you would need to show commitment to fixing the disruptive articles you wrote and edited here and explain how you plan to avoid the behaviour that resulted in your block.

Finally, you would be restricted to fixing your articles and edits for the first two months without creating any new articles. You would only return to creation of new articles when all your past contributions are fixed, and following a successful appeal of this restriction to the community. The appeal to remove the article creation restriction should be submitted at Wikipedia:Èbúté Àwùjọ. Regards. T CellsTalk 00:59, 28 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

Appeal to be unblocked

àtúnṣe

Thank you for unblocking my talk page @T Cells.

I would work on fixing my previous articles on yo.wiki once I am unblocked And I will always take corrections as regarding my contributions with good faith.

I acknowledge that I will not create any new articles until I fix the aforementioned articles.

Kindly review my appeal to be unblocked so that the fixing can commence @T Cells

Thank you for the intervention @Demmy Taoheedah (ọ̀rọ̀) 07:58, 28 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

Next steps
  1. You would need to retract all the false claims you have made against me at Meta:Requests for help from a sysop or bureaucrat#Request for Organizer Rights: Taoheedah and other venues, including the ones you made here. At Meta:Requests for help from a sysop or bureaucrat#Request for Organizer Rights: Taoheedah, and on any other platforms or venues where you have made similar false claims (that I haven't seen).
  2. You would need to explain what you understand of the behaviour that led to your block and how you plan to avoid the behaviour in the future.

Once these had been done, we can move forward with your appeal. Regards. T CellsTalk 08:30, 28 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

I would work on fixing my previous articles on yo.wiki once I am unblocked And I will always take corrections as regarding my contributions with good faith.
I acknowledge that I will not create any new articles until I fix the aforementioned articles. Regards @T Cells
@Demmy Taoheedah (ọ̀rọ̀) 08:53, 28 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

Unblock appeal declined

àtúnṣe

The blocked user has failed to show that they understand the behaviour that resulted in their block and has refused to explain how they would avoid the same behaviour in the future. The blocked user was asked to retract the false claims made against the block and the blocking admin in numerous venues as part of the unblock condition, but they refused to do so, which further confirms that they continue to justify the behaviour that resulted in their block. 

The block user may submit a new appeal in 2 months, and before the appeal, they

  1. Must retract all the false claims they made against the block and the blocking admin at Meta:Requests for help from a sysop or bureaucrat#Request for Organizer Rights: Taoheedah and other venues,
  2. They must explain in their appeal what they understand of the behaviour that led to their block and how they plan to avoid the same behaviour in the future. Regards. T CellsTalk 09:23, 28 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

== Harsh Conditions regarding Blocking ==

The last statement I said before I was blocked @T Cells was this "I am not creating a mess @T Cells, you identified a fix and I requested a solution since I had Translated the article 2 years ago. Telling me I will be shown the door is uncivil and against the principles of the Wikipedia. Volunteers are to be encouraged and supported not to be talked down on as you have just done. This is the second time I will be threatened to be blocked by you"

And for the Meta Wiki request, you went ahead to indicate that I should not be allowed to lead events when the discussions therein has nothing to do with yo.wiki. It seems as if you are bent on following up my wiki movements aside yo.wiki which is against the policies of the Wikimedia community. Pointing out how your contributions globally supercede mine indicate that you were trying to silence my opinion as a younger editor in the Wiki community.

Deciding to revoke my block appeal based on personal view or decisions is unfair from your side. Regards. Taoheedah (ọ̀rọ̀) 10:51, 28 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

:@T Cells N kò lérò wípé ó yẹ kí á ma fi ọ̀pá pọ̀òlọ̀pọọlọ pejò tí ń jòwèrè. Tí a bá wo ìṣesí àti ìhùwàsí oníṣẹ́ yí, ẹ ó ri wípé wọn kò ṣetán láti ṣe àtúnṣe bí ó ti wulẹ̀ kí ó mọ. Ń ṣe ni wọ́n ń yẹra fún òkodoro ọrọ̀ tí ó sì dàbí ẹni wípé wọ́n ń fipá mú oníṣẹ́ yí láti ṣe ohun tí ó tọ́. N kò lérò wípé ó yẹ kí a ma fàkókò wa ṣòfò lórí irúfẹ́ ìgbẹ́jọ́ báyí. @Demmy, ẹ ṣeun tí ẹ da sí ọ̀rọ̀ yí, inú mi sì dùn wípé ẹ̀yin náà yóò ti má a rí wípé kò sí bí a ṣe lè pọnmọ alágídí kí ẹsẹ̀ rẹ̀ kò ní wọ́lẹ̀. A lè fi tipátipá m'ẹ́ṣin t'odò, amọ́ a kò lè fipá fun lóní mu. Ṣókí lejò ń gánni.Agbalagba (ọ̀rọ̀) 12:17, 28 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

Appeal to be Unblocked

àtúnṣe

Hello T Cells, I am making an appeal to have my block lifted. I understand that my previous actions may have caused concern, but I have taken time to reflect and learn from my mistakes.

I have retracted my statements and I am committed to following the rules and guidelines of the yo.wiki. I am eager to contribute positively to the yo.wiki community.

I would appreciate it if you consider unblocking me. I am willing to work with you to address any concerns and ensure a constructive and respectful environment for everyone. Thank you for your time and consideration. Taoheedah (ọ̀rọ̀) 03:16, 7 Oṣù Kàrún 2024 (UTC)

  • Comment - I have unblocked your account following your successful appeal. First step to move forward is to go back to the list of articles you have created here and fix them. It is my hope that you would not repeat the behaviour that resulted in your block. Regards. T CellsTalk 09:52, 9 Oṣù Òkúdu 2024 (UTC)Reply
Thank you T Cells for the unblock. All feedback as well as corrections are noted and will be worked on Taoheedah (ọ̀rọ̀) 12:03, 9 Oṣù Òkúdu 2024 (UTC)Reply