Bòtswánà, lóníbiṣẹ́ bíi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Bòtswánà (Tswana: [Lefatshe la Botswana] error: {{lang}}: text has italic markup (help)), jẹ́ orílẹ̀-èdè àdèmọ́àrinlẹ̀ tó bùdó sí Apágúsù Áfríkà. Àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè únpe ara wọn bíi "Batswana" (ẹyọìkan: Motswana), sugbon awon elede miran unpe won bi "ara Botswana". Teletele o je ibi-abo Britani to unje Beshuanalandi, Botswana gba oruko tuntun leyin ominira ni ojo 30 Osu Kesan 1966. Latigba na lo lo ti unse idiboyan oselu to gbomitoro.

Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Bòtswánà
Republic of Botswana
Lefatshe la Botswana

Motto: Pula (Òjò)
Orin ìyìn: Fatshe leno la rona
(Orílẹ̀-èdè wa yìí)
(This Land of Ours)
Ibùdó ilẹ̀  Bòtswánà  (dark blue) – ní Africa  (light blue & dark grey) – in the African Union  (light blue)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Bòtswánà  (dark blue)

– ní Africa  (light blue & dark grey)
– in the African Union  (light blue)  —  [Legend]

OlùìlúGaborone
Ìlú tótóbijùlọolúìlú
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaGẹ̀ẹ́sì
Setswana
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
Tswana 79%
Kalanga 11%
Basarwa 3%
Kgalagadi 3%
White African 3%
òmíràn 1%
Orúkọ aráàlúBatswana/Motswana
ÌjọbaOrílẹ̀-èdè olómìnira oníléaṣòfin
• Ààrẹ
Mokgweetsi Masisi
Slumber Tsogwane
AṣòfinIlé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin
Ìlómìnira
• látòdọ̀ Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan
30 September 1966
Ìtóbi
• Total
581,730 km2 (224,610 sq mi) (47k)
• Omi (%)
2.6
Alábùgbé
• 2010 estimate
2,029,307[1] (144k)
• 2001 census
1,680,863
• Ìdìmọ́ra
3.4/km2 (8.8/sq mi) (229k)
GDP (PPP)2011 estimate
• Total
$29.707 billion[2]
• Per capita
$16,029[2]
GDP (nominal)2011 estimate
• Total
$17.570 billion[2]
• Per capita
$9,480[2]
Gini (1993)63[3]
Error: Invalid Gini value
HDI (2010) 0.633[4]
Error: Invalid HDI value · 98th
OwónínáPula (BWP)
Ibi àkókòCentral Africa Time (UTC+02)
• Ìgbà oru (DST)
kòsí
Ojúọ̀nà ọkọ́òsì
Àmì tẹlifóònù+267
ISO 3166 codeBW
Internet TLD.bw

Botswana je petele, be sini 70% je bibomole pelu Aginju Kalahari. O ni bode mo orile-ede Guusu Afrika ni gusu ati gusuilaorun, Namibia ni iwoorun ati ariwa, ati Zimbabwe ni ariwailaorun. Bode re mo Zambia ni ariwa nitosi Kazungula, Zambia ko fi be nitumo sugbon ko gun ju bi ogorun mita lo. [5]

Botswana kò ní ju iye èniyàn t'ótó bí irínwó lè díẹ̀ ni milionu meji lọ. nitorie o je ikan ninu awon orile-ede alabugbe kekere julo ni agbaye. Nigba ti Botswana gba ilominira latowowo Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan ni 1966, o je ikan ninu awon orile-ede to talaka julo ni Afrika pelu GDP ti enikookan bi US$70. Latigbana Botswana ti yira re pada lati di ikan ninu awon ti okowo re undagba julo lagbaye de eyi to ni GDP (agbara iraja) ti enikookan to to bi $14,000.[1] Bakana asa oselu asoju gbale daada nibe.

Ìtàn ilẹ̀ Bòtswánà
 
Àyọkà yìí jẹ́ ìkan nínú àwọn àyọkà ẹlẹ́sẹẹsẹ
Ìtẹlẹ̀dó àwọn Bàntú
Àwọn Tswana
Àwọn Grikua
Stellaland
Ibiàbò Beshuanalandi
Bechuanaland Stamps history
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Bòtswánà
Ẹ tún wo
History of Gaborone
{Àdàkọ:Data99

Èbúté Bòtswánà
Fáìlì:Gaboronecitycentre.JPG
Àwọn ilé ní àrin ìlú Gaborone, Botswana

Ni orundun 19k, ogun sele larin awon Tswana ti won ti ungbe Botswana ati awon eya Ndebele ti won sese unko bo si agbegbe yi lati ariwa-ilaorun. Bakanna rogbodiyan sele pelu awon ateludo Boer lati Transvaal ni ilaorun. Leyin itoro awon olori Batswana bi Khama III, Bathoen ati Sebele fun iranlowo, Ijoba Britani fi "Bechuanaland" si abe abo re ni ojo 31 Osu Keta 1885. Ibi-ile apaariwa nigbana wa labe imojuto taara bi Ibiabo Beshuanalandi ibe lasi mo loni bi Botswana, nigba ti ibi-ile apaguusu di apa Ileamusin Cape loni o je apa igberiko ariwaiwoorun orile-ede Guusu Afrika. Opo awon eniyan to unso ede Setswana loni ungbe ni orile-ede Guusu Afrika.

Nigbati Isokan ile Guusu Afrika je didasile bi orile-ede ni 1910 latinu awon ileamusin gbangba Britani ni agbegbe na, Ibiabo Bechuanaland, Basutoland (loni bi Lesotho) ati Swaziland (eyun "High Commission Territories") ko je ara re, sugbon eto wa nigbana lati safikun won lojowaju. Ipinnu ni pe ijiroro yio sele pelu awon alabugbe ibe botileje pe awon ijoba Guusu Afrika mura lati da awon ibi-ile na pada fun won, Britani dina eyi; nitorie ko sele. Idiboyan ijoba Asetolorile-ede ni odun 1948, to pile eto apartheid, ati ikesejade Guusu Afrika kuro ni Egbe Kajola ni 1961, fi opin si ero pe awon ibi-ile yi yio bo si owo orile-ede Guusu Afrika. Ifidimule ijoba britani ati idasile ijoba ibile fa idasile ni 1920 igbimo agbero meji lati soju awon ara Afrika ati ara Europe. awon ikede ni 1934 selana ijoba ati agbara ibile. Igbimo agbero ara Afrika ati ara Europe kan je didasile ni 1951, be sini isepo 1961 selana igbimo asofin adamora.

Ni Osu Kefa 1964, Britani fowo si aba idasile ijoba-araeni olselu ni Botswana. Ibujoko ijoba kuro ni Mafikeng ni Guusu Afrika ni 1965, si ilu tuntun ni Gaborone, " Cara Mendapatkan Kuota Gratis 3 10 GB terbaru 2017 Archived 2017-11-15 at the Wayback Machine. " ti kkojinna si bode re. Isepo 1965 fa idiboyan gbogbogbo wa ati ilominira ni ojo 30 Osu Kesan 1966. Seretse Khama, olori ninu awon egbe irinkankan fun ilominira ati ajoye Ngwato je didiboya bi aare akoko, o si tun ti je atundiboyan lemeji latigbana.

Ipo aare bo sowo igbakeji aare, Quett Masire, to jje didiboyan fun ra re ni 1984 ati lemeji si ni 1989 ati 1994. Masire feyinti ni 1998. Igbakeji re Festus Mogae, je didiboyan fun ra re ni 1999 ati lekan si ni 2004. Ni 2008 ipo aare bo sowo Ian Khama (omokunrin aare akoko), to fi ipo re sile bi olori Ile-ise Iseabo Botswana lati le ba bo si ipo oloselu yi.

Ijiyan lori bode pelu Namibia lori Caprivi Strip je lilaja latowo Ile-Ejo Akariaye fun Idajo ni Osu Kejila 1999, pe Erekusu Kasikili je ti Botswana.[6]

Ìṣèlú àti ìjọba

àtúnṣe

Iselu ni Botswana unwaye labe eto orile-ede olominira oloselu asoju, nibi ti Ààrẹ ilẹ̀ Bòtswánà ti je olori orile-ede ati olori ijoba, ati labe sistemu egbe oloselu pupo. Agba apase wa lowo ijobat. Agbara Asofin wa lowo ijoba ati Iléaṣòfin ilẹ̀ Bòtswánà. Idiboyan aipe, ikewa iru re, waye ni ojo 16 Osu Kewa 2009.

Lati igba ilominira, oselu ni Botswana ti je gigaba latowo Egbe Oloselu Botswana. Adajo ni ilominira latodo apase ati asofin. Gege bi Isekedere Akariaye se so, Botswana ni orile-ede Afrika to ni iwa ibaje to din julo, be sini ipo re sunmo Portugal ati Korea Guusu.[7] Nevertheless the country is considered to have the most secretive public institutions.[8] Orin-iyin orile-ede ni Fatshe leno la rona.

Àwọn ìpín àmójútó

àtúnṣe

Botswana je pinpin si sàkání 15 – sakani oko 9 ati sakani ilu 6.

Oríilẹ̀yíyà

àtúnṣe

Òrọ̀àyíká

àtúnṣe

Ìṣeàbò

àtúnṣe

Òkòwò

àtúnṣe

Ẹ̀yàìlú

àtúnṣe

Ẹ̀sìn

àtúnṣe

Ẹ̀kọ́

àtúnṣe

Eré-ìdárayá

àtúnṣe

Iṣẹ́ọnà

àtúnṣe

Oúnjẹ

àtúnṣe

Àwọn ọjọ́ ìsinmi

àtúnṣe


  1. 1.0 1.1 Central Intelligence Agency (2009). "Botswana". The World Factbook. Archived from the original on 15 October 2015. Retrieved 3 February 2010. 
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 "Botswana". International Monetary Fund. Retrieved 2012-04-17. 
  3. "Distribution of family income – Gini index". The World Factbook. CIA. Archived from the original on 2009-05-13. Retrieved 2009-09-01. 
  4. "Human Development Report 2010" (PDF). United Nations. 2010. Retrieved 5 November 2010. 
  5. Darwa, P. Opoku (2011). Kazungula Bridge Project. African Development Fund. p. Appendix IV. Archived from the original on 2012-11-14. https://web.archive.org/web/20121114113821/http://www.afdb.org/fileadmin/uploads/afdb/Documents/Project-and-Operations/Multinational%20(Zambia-Bostwana)%20-%20AR%20-%20Kazungula%20Bridge%20Project.pdf. Retrieved 2012-05-04. 
  6. "Namibia General Information". Southern-eagle.com. 1990-03-21. Retrieved 2011-08-21. 
  7. Transparency International 2008 Corruption Perception Index 2008 Archived 2009-03-11 at the Wayback Machine.. Retrieved 7-23-09.
  8. Glenda Daniels (2011-11-11) Botswana, Southern Africa's most secretive state. Mail & Guardian. mg.co.za